Gbagede Yoruba
 



Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo
 
Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose Lati Owo Akoroyin Olootu

Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo

Kootu ibile keji niluu Osogbo ti tu igbeyawo olodun mefa ka laarin Ogbeni Rasheed Olalekan atiyawo re, Mutiat Olalekan, lori esun wahala ojoojumo.

Ogbeni Rasheed lo mu ejo iyawo re lo sile-ejo, o ni onijagidijagan ati oniwahala niyawo oun to je onisowo, ati pe oun ko le farada wahala re mo lo je koun fee jawee fun un.

O ni, ''Wahala re ti po ju, ki i gbo ibawi rara, ko fi mi lokan bale ninu ile. Mo ti koko figba kan fi olopaa mu un, sugbon awon yen so pe tori pe o n gbe omo kekere lowo, ki n se suuru.


Gbogbo igbiyanju mi lati je ko yipada lo ja si pabo, e tu wa ka, n ko fe e mo.'' Ninu awijare iyawo, o ni iro patapata ni oko oun n pa mo oun pe onijangbon loun, o ni se lokunrin naa korira omo toun bi fun un, idi si niyi to fi maa n fikanra mo oun ninu ile.

Mutiat ni, ''Oko mi koriira omo ti mo bi fun un, koda ki i fee ri awon omo ti mo bi sile oko aaro ko too di pe mo fe e. Wahala to sele gbeyin nigba ti mo ni ko fun mi lowo ki n fi ra bata fun omo mi to farapa nibi kanga kan ti oko mi n gbe lowo siwaju ile, ko fun mi lowo yen, se lo so pe wahala mi ti po ju.

''Emi ko setan lati ko oko mi sile rara nitori ko seni ti yoo ba mi toju omo mi to n saisan lowo.'' Leyin atotonu awon loko-laya, aare kootu ohun, Oloye Popoola Bolarinwa pase pe ki igbeyawo naa di tituka latari bi oko-iyawo se yari kanle pe oun ko nifee iyawo oun mo.

Popoola waa ro awon mejeeji lati ma se fa wahala kankan mo, ki onikaluku si maa lo lalaafia.

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 20:37:42 PST Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose:
Iru Pasito Radarada Wo Waa Ni Oluso-Aguntan Oyelami Yii Gbogbo Awon Omobinrin Ij


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose



"Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com