Gbagede Yoruba
 



Àwon Origun Esin Islãm Itunmo si Ede Yoruba
 
Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
Àwọn Origun Ẹsin Islãm

أركان الإسلام بلغة اليوروبا

Itunmọ si Ede Yoruba

Lati ọwọ:

AbdulWahab Muhammad Jãmiu Ẹlẹsin

Ilẹ Saudi Arabia, Ilé isẹ - Minisiri - ẹkọ giga - Ilé-ẹkọ giga Islãm ni Mọdinat

Àyè iwadii-Imọijinlẹ - Ẹka títúmọ ede si omiran

Àwọn Origun Ẹsin Islãm

Ọrọ Isãju

Ọpẹ ni fun Ọlọhun, ikẹ ati ọla ki o maa ba igbẹyin awọn annabi, Annabi wa Muhammad ọmọ 'Abdullahi r. Lẹhin na:

Dajudaju titan awọn imọ ẹsin Islam ka o ni ipa kan ti o tobi l'ori sise alaye papa ẹsin Islam, ati fifi idi awọn opo ẹsin rinlẹ, ati mimu ilọsiwaju ba ijọ (Musulumi). Eleyi jẹ ero ngba nla, ohun naa ni ile ẹkọ giga ti Islam (Islamic University) n sapa lati se pẹlu ipepe ati ikọnilẹkọ.

Ni ifọwọsowọpọ l'ori eyi ni ile isẹ ti n se amojuto iwadi imọ-ijinlẹ ni ile ẹkọ yii fi dide lati se ọna ati igbesẹ kalẹ l'ori ọpọlọpọ ninu awọn isẹ adawọle ti o jẹ ti imọ, ninu rẹ ni sise iwadi ti o jinlẹ nipa Islam ati awọn daada ti o gbe wa, ati sise afọnka rẹ, lati le fun awọn ọmọ Musulumi ni imọ ti o peye nipa ẹsin wọn, adisọkan rẹ, pẹlu awon ofin rẹ.

Iwadi yi ti o da le ori (Awọn Origun Islam) jẹ ọkan ninu awọn igbesẹ ile işẹ yi, nitori naa ni o fi pe apakan ara awọn olukọ ni ile ẹkọ giga yi ki wọn kọ nkankan nipa origun Islam, lẹyin naa ni o tun wa gbe awọn ikọ kan dide ni ile işẹ naa lati se ayẹwo nkan ti wọn kọ, ki wọn si se atunse ti o yẹ l'ori rẹ ki wọn si gbee jade, ki wọn si gbiyanju lati maa mu ẹri wa lati inu Al-Qur'an ati Sunna (Ilana Annabi) l'ori gbogbo ọrọ imọ ti wọn ba mu ẹnu ba.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Monday, November 25 @ 05:23:19 PST Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin:
Oorun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin



"Àwon Origun Esin Islãm Itunmo si Ede Yoruba" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com