Gbagede Yoruba
 



Owo Olopaa Ti Te Odey To Fipa Ba Omo Odun Meje Lo Po N’Ilesa
 
Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Owo Olopaa Ti Te Odey To Fipa Ba Omo Odun Meje Lo Po N’Ilesa

Taanutaanu ni okunrin eni odun metalelogun kan n wo nigba towo awon olopaa ilu Ilesa te e laipe yii lori esun pe o fipa ba omo odun meje lo po. Bakan naa ni Umeh Emmanuel naa ti n fimu danrin lakolo awon olopaa l«Osogbo bayii lori esun pe o fun omo odun mejila loyun.

Ni nnkan bii aago mefa, ojo ketadinlogun, osu kesan-an, odun yii la gbo pe Arabinrin Teresa Peter to n gbe lagbegbe Odogbo, niluu Ilesa fi awon omo re obinrin meji: Happy, omo odun mewaa ati Mary, omo odun meje sile sinu ile, to si lo soko.



Nigba ti yoo fi pada denu ile nirole ojo naa, o ri i pe okunrin kan ti fipa ba omo re, Mary, lo po, ninu iwadii e lomo ohun si ti so pe Odey lo huwa buruku naa soun.

Iya Mary loo foro naa to awon olopaa leti, owo si te Odey, bee ni won mu Mary lo fun itoju nileewosan, nigba ti Odey si n ran awon olopaa lowo ninu iwadii won.

Ojo kerindinlogun, osu kesan-an, odun yii ni Arabinrin Ijemo Okoileaboh Prisea to n gbe lagbegbe Obelawo, niluu Osogbo, mu aburo re omo odun mejila lo sodo awon olopaa to si salaye pe nigba toun fura pe o ti loyun loun beere eni to fun un loyun lowo re.

Leyin opolopo atotonu lomobinrin naa jewo pe Umeh Emmanuel to n gbe lojule kerinla, oju-ona Obafemi Awolowo, lagbegbe Ayetoro, niluu Osogbo, lo fipa ba oun lo po losu meji seyin, to si yori soyun.

Won ti gbe omo naa lo sileewosan bayii fun itoju, nigba towo si ti te Emmanuel fun iwadii


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 04:25:59 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo:
Yoruba Greetings, (Middle) Names In Yoruba Language With Titles Of Obas (Kings)


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo



"Owo Olopaa Ti Te Odey To Fipa Ba Omo Odun Meje Lo Po N’Ilesa" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com