Gbagede Yoruba
 



Agbaaya Ma Leleyii O: Bakare N Bomo Lanloodu E Lo Po N’Ilorin
 
Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
Lati Owo Seyi Adeshina, Ilorin

Agbaaya Ma Leleyii O: Bakare N Bomo Lanloodu E Lo Po N’Ilorin

Asiri okunrin kan, Ogbeni Bakare, to n ba omo lanloodu e, Tosin sun ti tu bayii nitori bi won se ri i nigba to n huwa ibi naa, ti won si fi olopaa mu un.

Gege bi a se gbo, o pe ti Bakare ti n ba omobinrin ohun sun. Nibi to ko somo naa lori de, bo ba ti lo sileewe laaaro, ki i pee pada wale nigba tawon obi e ba ti lo sibi ise, odo tenanti yii ni yoo wa ti iyen yoo si maa ko ibasun fun un karakara.



Omobinrin yii ko ju omo odun merindinlogun lo, won so pe o ti figba kan se oyun to ni fun okunrin yii, die lo si ku ko ku nigba ti inu n run un. Bakan naa la gbo pe okan omo naa ko si ninu iwe mo, bee lawon oluko e so pe ki i se gbogbo igba lo maa n wa sileewe.

Eyi lo mu ki baba omo naa so pe kawon eeyan maa ba oun so o, ko si pe ti Ogbeni Bakare tun fi tan omobinrin naa wonu yara e to si n ba a lo po karakara. Bawon eeyan se fipa ja ilekun yara e niyi ti won si ka a mo ibi to ti n kona bo omo naa labe. Nise ni won lu u bii baara. Itiju oro naa lo mu ki Ogbeni Bakare sa jade ninu ile lati bii ojo merin si asiko ti a n ko iroyin yii, ko si ti i pada wale.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 05:27:04 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara:
Asiri Nla Alaaji Amosa So Itan Igbesi Aye Re, O ni: Anjonnu Ni Mo Fe Niyawo


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara



"Agbaaya Ma Leleyii O: Bakare N Bomo Lanloodu E Lo Po N’Ilorin" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com