esinislam.com
 
     
Search Results for: Yoruba Media
- Onka Yoruba - esinislam.com

Onka Yoruba Lati Ori Ookan De Egbeegberun Lona Egberun - Yoruba Numbers from 1 (One) to 1,000,000,000 (One Billion) Naming Numbers as in figure e.g. 3 = Eeta (i.e. Three); 10 = Eewa (i.e. Ten):

:: EsinIslam Yoruba Media Fun Iroyin, Atoka, Iwe-Irohin ...

Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, ni nnkan bii aago merin oru ojo keeedogbon, osu kin-in-ni, odun yii, nisele naa waye ni ojule ketalelogun, laduugbo Abari, n'Iyana-Ipaja, niluu Eko, iyen nigba ti Grace gbimo-po pelu orekunrin re to n je Benjamin Otu lati pa oko re ti won jo wa lati Akwa Ibom pelu obe idana.

EsinIslam Media - Onka Yoruba - Numbers In Yoruba: Figures ...

Onka Yoruba Lati Ori Ookan De Egbeegberun Lona Egberun - Yoruba Numbers from 1 (One) to 1,000,000,000 (One Billion) Naming Numbers as in figure e.g. 3 = Eeta (i.e. Three); 10 = Eewa (i.e. Ten):

:: EsinIslam Yoruba Media Fun Iroyin, Atoka, Iwe-Irohin ...

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe omo osu meje pere ni omobinrin toruko re n je Favour ohun, o si ku die ki Happiness ri i gbe sa lo kowo too te e. Ohun ti a ri gbo ni pe awon olopaa ayarasise (Rapid Response Squad) to n sise lagbegbe Eric Moore lo ri okunrin naa ti won si fura si irin ese re.

- Owo Te Oladele To N Ta Ori Eeyan N'Ibadan :: EsinIslam ...

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, aajin oru lawon olopaa loo ka okunrin naa mole, boya oogun ifura to si n lo lo je ko mo pe won ti wa nitosi ni, tabi boya o gburoo awon agbofinro naa nigba ti won de enu ona ile e, ko si eni to ye, ohun to sa han sawon agbofinro ni pe won ko ba baba naa nile, jagunlabi ti ta poro ba ona eyinkule sa lo.

Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa ...

Iyalenu ni o je fun mi wipe awon Yoruba Media Team EsinIslam.com fi aaye gba iru itan yi lati je kika fun awon eniyan tobe gee ti a fi le ri laarin awon eniyan ti nwon yio maa ro wipe EsinIslam.com gan naa npe iru awon alaimokan nwonyi ni oniwaasi tabi alufa. Ijiya awon oniwuruju nwon yi sese bere ni.

- Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun ...

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe o pe ti Oriyomi ti maa n paayan, to si maa n mu un je, sugbon aago re to kun a-kun-wo-sile ni ko se mori bo nigba towo te e pe o gbemii ore re. Iwadii fi han pe odun 2013 lowo koko te e, iyen lojo kesan-an, osu kesan-an. Nigba ti won wo o de kootu majisreeti to wa l'Ebute-Meta, odaran yii jewo pe omo egbe okunkun Black ...

Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Ise Logun ise - Toju Iwa ...

"Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Ise Logun ise - Toju Iwa Re Ore Mi - Omo to m" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

- Odidi Odun Meta Loko Mi Fi Pa Mi Ti, Mi o Se Mo — Taiwo ...

Lati Owo Akoroyin Olootu Odidi Odun Meta Loko Mi Fi Pa Mi Ti, Mi o Se Mo — Taiwo Igbeyawo ogun odun kan lo ti wa ni bebe iforisanpon bayii pelu bi iyaale ile naa se n kunle, to n rababa nile-ejo koko-koko kan to wa ni Oke-Eda, niluu Akure, pe ki won ba oun fopin si ibasepo olodun gbooro to wa laarin oun atoko oun lori esun pe okunrin naa pa oun ti bii aso to ti gbo fun odidi odun meta.

- Rasidi Yekini: Eyi Ni Bi Won Se Bi i, Bo Se Di Agbaboolu ...

Awon oniroyin Yoruba tun ri ko wipe bayi gan an ko ni oro ti se ri. Gbogbo botiwule ki or ri, ko si eniti o lee so pato idi iku omokunrin daradara yi. Bakan naa ni Iwe Iroyin Yoruba tun n gbo awuyewuye pe obinrin ti Rasidi ko fe nisu loka to je omo Ijebu lo sebi si i.

Next Matches
 
 

esinislam.com