Prev  

1. Surah Al-Fâtihah سورة الفاتحة

  Next  




بِسْمِ اللهِ الرَّحْمَٰنِ الرَّحِيمِ
Yoruba
 
Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.

Ayah  1:2  الأية
  
  +/- -/+  
الْحَمْدُ لِلَّهِ رَبِّ الْعَالَمِينَ
Yoruba
 
Gbogbo ẹyìn ń jẹ́ ti Allāhu, Olúwa gbogbo ẹ̀dá,



Ayah  1:5  الأية
  
  +/- -/+  
إِيَّاكَ نَعْبُدُ وَإِيَّاكَ نَسْتَعِينُ
Yoruba
 
Ìwọ nìkan ni à ń jọ́sìn fún. Ọ̀dọ̀ Rẹ nìkan sì ni à ń wá oore sí.

Ayah  1:6  الأية
  
  +/- -/+  
اهْدِنَا الصِّرَاطَ الْمُسْتَقِيمَ
Yoruba
 
Fi ẹsẹ̀ wa rinlẹ̀ l'ójú ọ̀nà tààrà ('Islām),

Ayah  1:7  الأية
  
  +/- -/+  
صِرَاطَ الَّذِينَ أَنْعَمْتَ عَلَيْهِمْ غَيْرِ الْمَغْضُوبِ عَلَيْهِمْ وَلَا الضَّالِّينَ
Yoruba
 
ọ̀nà àwọn tí O ṣe ìdẹ̀ra fún, yàtọ̀ sí (ọ̀nà) àwọn ẹni-ìbínú (ìyẹn, àwọn yẹhudi) àti (ọ̀nà) àwọn olùṣìnà (ìyẹn, àwọn nasọ̄rọ̄).
 
Open بادئة  

 

End خاتمة

       
 







© EsinIslam.Com Designed & produced by The Awqaf London. Please pray for us