Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Awon isele nlaodun to koja: Awon koko inu iroyin ati isele ni odun 2014 - 2015
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Akoroyin Olootu

Awon isele nlaodun to koja: Awon koko inu iroyin ati isele ni odun 2014 - 2015


Ojo kin-ni-ni, osu kin-in-ni
• Egberun kan ati igba omo egbe PDP nipinle Kaduna darapo mo APC.

• Onkowe agba, Odia Ofeimun, gboriyin nla fun Oloogbe Obafemi Awolowo nigba to so pe baba Ijebu naa niyi ju asiwaju ile Liberia, Oloogbe Nelson Mandela lo.

Ojo keji,osu kin-in-ni
• Ijoba apapo kede pe afikun ko ni i gori owo epo bentiroolu ti awon araalu yoo maa ra.

Ojo keta, osu kin-in-ni
• Awon janduku kolu olutele Muhammadu Buhari kan, Alhaji Abdulmajid Danbuiki, ninu mosalasi kan ni Kano. Won lu baba naa gidi.Ojo kerin, osu kin-in-ni
• Oludasile ijo INRI, Primate Babatunde Elijah Ayodele so asotele pe idarudapo yoo sele lagbo oselu, awon oloselu yoo maa kuro legbe won lo segbe mi-in. Bee ni ki Aare Goodluck Jonathan sora se lori erongba re lati dupo aare leekeji nitori ilera re, o tun ni ki won gbadura fun Patience Jonathan naa.


Ojo karun-un, osu kin-in-ni
• Jonathan kede pe oro Boko Haram yoo ditan laipe. Ninu ijo Church of Christ to wa ni Garki, l'Abuja lo ti kede pe awon omo-ogun Naijiria yoo teri iko naa ba.

• Ajagun-feyinti Muhammadu Buhari, Oloye Bisi Akande, Rotimi Amaechi ati Nasir-El Rufai so pe Aare Jonathan n lepa emi awon, ati pe oruko awon wa lara awon eeyan ti aare fee pa.

• Awon adigunjale pa pasito Ridiimu ni Magboro, l'Ogun, leyin ti won yinbon fun un ni won fobe ko ifun e jade.


Ojo kefa, osu kin-in-ni
• Egbe oselu APC soko oro pada sijoba apapo latari bi ofiisi aare se n fesun kan won lori wahala Boko Haram.


Ojo keje, osu kin-ni-ni
• Eeyan mejilelaaadota ku, bee ni opolopo dukia baje nigba ti tirela to gbe epo fegbe lele lori biriiji Berger Cement, nijoba ibile Ajeromi, nipinle Eko.

• Osise banki Access meji padanu emi won lori afara elekeeta nipinle Eko, taya iwaju jiipu won lo fo lori ere.

• Onarebu Friday Adefemi to ti figba kan je agbenuso ile igbimo asofin ipinle Ekiti ati gomina fidi-he olojo meta jade laye.


Ojo kejo, osu kin-in-ni
• Gomina Rotimi Amaechi tipinle Rivers fesun kan komisanna olopaa ipinle naa, Joseph Mbu, pe o n ledi apo po pelu egbe oselu PDP lati tako isakoso oun, bee lo n di awon asofin ipinle Rivers lowo lati sise won.

• Omokunrin eni odun mejidinlogun kan, Ikechukwu, fun omobinrin eni odun mejila toruko re n je Bose Ogoja lorun pa nitori egberun lona ogorun-un naira. O ni pasito kan lo gbe ise naa foun ni Surulere ti won jo n gbe.


Ojo kejila, osu kin-in-ni
• Eeyan metala jona ku ni Effurun, lebaa Warri, nipinle Delta, nigba ti oko akeromerindinlogun kan deede gbina. Bee lomo osu mejo jona mole l'Oworonsoki l'Ekoo.

• Awon olopaa yinbon fun Magnus Abe laya ni Portharcourt, iyen seneto to n soju ekun Guusu IlaOorun ipinle Rivers ninu iwode kan ti awon olutele Gomina Amaechi se, sugbon awon olopaa so pe awon ko.


Ojo ketala, osu kin-in-ni
• Won gbe Magnus Abe lo sorile-ede UK lati gba emi re la.


Ojo kerinla, osu kin-in-ni
• Ogbon eeyan padanu emi won lowo ikolu Boko Haram, aadota mi-in farapa yanna-yanna ni Maiduguri nigba ti agbesunmomi kan so bombu mora ti ado oloro naa si bu gbamu. Awon odo fehonu han lori ikolu ohun, won ni owo gomina ana nipinle naa, Ali Modu Sheriff, ko mo lori re.

Won ba ofiisi re je, bee ni won ba ile re kan naa je ni GRA.

Ojo keeedogun, osu kin-in-ni Bamanga Tukur, alaga PDP tele fipo re sile leyin opolopo awuyewuye.


Ojo kerindinlogun, osu kin-in-ni
• Aare Jonathan ro awon oga ologun kan loye, o si fi awon mi-in ropo won. Alex Badeh gbapo lowo Ola Sa'ad Ibrahim, Kenneth Tobiah Minimah gbapo lowo Azubike Ihejirika, Usman Jibrin gba aaye Dele Ezeoba, bee ni Adesola Nunayon Amosu bo sipo ti Badeh wa tele.

Ojo kejidinlogun, osu kin-in-ni
• Gomina ipinle Plateau nigba kan ri, Oloye Michael Botmang, jade laye leni odun merindinlogorin.

Aisan ito suga ni won lo pa a.


Ojo kokandinlogun, osu kin-in-ni
• Boko Haram pa eeyan mejidinlogun ni Borno, bee ni awon Fulani darandaran pa eeyan mejila ni Benue.

• Egbe PDP labe ase Goodluck Jonathan yan alaga mi-in, Adamu Muazu to ti figba kan je gomina ipinle Bauchi lo di alaga tuntun.

• Awon eeyan ipinle Taraba sekilo fun igbakeji Gomina Danbaba Suntai, iyen Garba Umar, pe Gomina to n saare naa ko gbodo ku, afi toun naa ba setan lati ba a lo.


Ogunjo, osu kin-ni-ni
• Jonathan tun yan Bamanga Tukur gege bii alaga ileese oko-oju-irin ile wa.

Ojo kejilelogun, osu kin-in-ni Ile igbimo asoju-sofin daru nigba ti Femi Gbajabiamila so pe olori awon eeyan perete ni Leo Ogor to je olori awon omo egbe to po ju. Inu bi awon omo egbe PDP, won si fa ibinu yo.


Ojo ketalelogun, osu kin-in-ni
• Awon alase Yunifasiti Lasu ti ileewe naa pa latari ifehonu-han awon akekoo lori bi won se ni ki awon kan ninu won ma ti i se idanwo. Awon akekoo ya wo kilaasi, won ba opolopo dukia je, won tun da sun-kere-fa-kere oko sile ni marose Eko si Badagry. Ori lo ko olori fasiti naa, Omowe John Obafunwa, yo lowo won.

• Edwin Clark, asiwaju awon Ijaw, so pe gbogbo eni to ba n ba Jonathan ja n ba Olorun ja ni nitori Olorun lo yan an sipo naa.


Ojo kerinlelogun, osu kin-in-ni
• Ile-ejo giga ijoba apapo to n jokoo l'Osogbo da ejo ti ajo Incorporated Trustees of Egalitarian Mission for Africa pe Aregbesola nu, nibi ti won ti ni ki won ye opolo gomina naa wo boya o pe.

Adajo Babs Kewumi fagile ejo naa nigba tawon ajo yii ko yoju mo.


Ojo karundinlogbon, osu kin-in-ni
• Iko agbaboolu Naijiria, Super Eagles, pegede lati wo ipele to kangun si asekagba ninu idije ere boolu ile adulawo Ojo kerindinlogbon, osu kin-in-ni
• Dokita Bukola Saraki kede pe o kere tan, omo egbe PDP metadinlogun yoo darapo mo APC nitori won ti to gbogbo iwe won lodo eka to ye fun isipopada.


Ojo ketadinlogbon, osu kin-in-ni
• Iko eso alaabo SSS da minisita olu ilu ile wa tele, Nasir El-Rufai, sile leyin ti won mu un fun oro to so pe eto idibo 2015 yoo di wahala bi won ko ba fi ooto se e.


Ojo kejidinlogbon, osu kin-in-ni
• Orji Uzor Kalu, gomina ipinle Abia, tele kede pe oun ko dije dupo aare mo latari bi awon Ohaneze Ndigbo se ni ko jawo na, nitori ojo iwaju lawon yoo lo o.


Ogbonjo, osu kin-in-ni
• Ajo to n ri si iwole-wode awon ajoji lorile-ede yii sawari ile kan ti won n ko awon aboyun si ti won si n gbe omo ti won ba bi ta niluu kan ti won n pe ni Ilutitun, Okitipupa, nipinle Ondo. Ogbeni Aliu Ojo, eni odun merindinlaaadorin ati Happiness Ogundeji, eni odun marundinlogoji lowo sinkun ofin te fun esun naa.


Ojo kokanlelogbon, osu kin-in-ni
• Ango Abdullahi, agbenuso fun igbimo agba Arewa fesun kan awon olori orile-ede yii pe owo ti won ri lati ile Hausa ni won fi n se igbedide eka epo bentiroolu wa. O ni loooto lawon ti se olori Naijiria fun opolopo igba, sugbon awon tun Naijiria se ju bawon se se ilu awon gan-an lo, iyen naa ni won fi maa n so pe awon go.


Ojo kin-in-ni, osu keji
• Alaga telifisan ijoba apapo, eka tipinle Ondo, Ogbeni Alex Akinwale, iyawo re, omo won ati omo odo won padanu emi won sinu ijamba oko loju ona Akure si Ondo. Igbakeji gomina ipinle Ondo naa wa ninu isele yii nitori oko re n lo pelu awon oko ti won jo kowoorin naa ni ki ori too ko o yo.

• Awon agbaboolu Super Eagles gba ami-eye buronsi ninu idije ile adulawo nigba ti won na Zimbabwe ni ami kan si odo.


Ojo keji, osu keji
• Ijoba apapo towo bowe adehun atunse ina monamona pelu ileese agbaye kan, ‘General Electric'.

Milionu lona oodunrun ataabo naira ni won la kale lati ri i daju pe ileese naa mojuto ipese ina oba kereje-kereje.


Ojo keta, osu keji
• Gomina ileefowopamo apapo ile wa nigba kan, Sanusi Lamido, kegbajare pe ajo elepo bentiroolu Naijiria ko ti i da bilionu lona ogun dola ti won yo lara owo epo robi ti won ta pada sinu apo Naijiria.

Ojo kerin, osu keji
• Ojo yii lawon omo ileewe jakejado ipinle Osun pa aso ileewe won ti ti won wo aso esin musulumi, aso soosi ati tawon elesin abalaye lo si ileewe won nitori ofin ti Gomina Aregbesola se pe ki gbogbo ileewe nipinle naa maa wo aso kan naa.

Ojo karun-un, osu keji
• Leyin ti won mu un sodo fun iforowanilenuwo oniwakati mefa, ajo SSS yonda olori awon ajijagbara Niger/Delta, Asari Dokubo, won kilo fun un pe ko so enu re lori oro to so pe itajesile yoo sele bi Jonathan ko ba wole.


Ojo kefa, osu keji
• Egbe igbimo agba Yoruba(Yoruba Unity Forum) fesun kan Aare Goodluck Jonathan pe o n se oju-saaju ninu ipo pinpin pelu bo se je pe awon omo Yoruba ko ri ipo gidi di mu ninu isejoba re.


Ojo kesan-an, osu keji
• Aare Jonathan atawon eeyan re ninu egbe oselu PDP sepade idakonko, awon amoye so pe oro bi ibo si ipo aare yoo se ja mo won lowo ati bi won yoo se ri awon ibi tawon eeyan ko ti fe tiwon gba ni won loo so.


Ojo kewaa, osu keji
• Olori awon osise lofiisi aare, Oloye Mike Oghiadomhe, sadeede kowe fipo re sile. Bawon kan se n so pe o fee tesiwaju ninu oselu lawon mi-in so pe Jonathan lo pa a lase lati kowe fipo sile nitori ojo iwaju.

Ojo kokanla, osu keji
• Ijoba apapo Naijiria yo Stella Oduah, minisita fun eto irinna ofurufu ti won fesun kan pe oodunrun milionu din die bo sapo re. Oko akotami meji ni won lo fee fowo naa ra. Awon mi-in ti won tun padanu ipo won ni: Caleb Olubolade, Godsday Orubebe ati Yerima Ngama.


Ojo kejila, osu keji
• Egbe oselu PDP ipinle Rivers bu enu ate lu pipe ti gomina ipinle Rivers, Rotimi Amaechi, pe Olusegun Obasanjo lati waa si awon akanse ise kan gege bii ipe abosi, won ni won kan n tan awon eeyan je pe awon ko ja mo ni.

• Jelili Adesiyan ti won yan fun ipo minisita nipinle Osun farahan nile igbimo asofin orile-ede yii lati we oruko re mo pe oun ko lowo si iku Oloye Bola Ige ti won fesun re kan an.


Ojo ketala, osu keji
• Aare Goodluck Jonathan kede pe ebun milionu kan naira ni enikookan awon agbaboolu Super Eagles yoo gba fun sise ipo keta ninu idije ile adulawo to waye lorile-ede South Africa. Stephen Keshi yoo gba milionu kan aabo naira. Daniel Amokachi, Ike Shorounmu ati Valer Houndinou ti won je amugbalegbe yoo gba milionu kan naira enikookan, bee ni akowe iko naa atawon dokita to mojuto ilera won yoo gba milionu marun-un naira enikookan.


Ojo Kerinla, osu keji
• Ile-ejo giga kan niluu Abuja da agbenuso ile igbimo asofin nigba kan ri, Dimeji Bankole, sile pe ko maa lo sile re nitori ko jebi esun bilionu mesan-an naira ti ajo EFCC fi kan an pe o se basubasu.

Adajo Evoh Chukwu lo dajo naa.


Ojo keeedogun, osu keji
• Jonathan sabewo sawon oba alaye nile Yoruba, bee lo de odo Ado Bayero to je Emir Kano nigba naa. Jonathan de aafin Oba ilu Oyo, Lamidi Adeyemi, odo oba Ife, Okunade Sijuwade ati Oba Eko, Rilwan Akiolu ni imurasile di asiko ti yoo kede ipinnu re lati du ipo aare leekan si i.


Ojo kerindinlogun, osu keji
• Gomina ipinle Borno, Kashim Shettima, so pe inu ibanuje loun wa latigba toun ti dori aleefa nitori awon isele to n sele niluu oun. O ni oun kan n rerin-in lawujo awon eeyan ni, ibanuje sodo sisale ikun oun lopo igba.


Ojo ketadinlogun, osu keji
• Aare Goodluck Jonathan yan olori awon osise tuntun fun ofiisi re, Ogagun Jones Arogbofa, ni olori tuntun naa n je.


Ojo kejidinlogun, osu keji
• Awon omo egbe okunkun pa omodebinrin eni odun metadinlogun kan, Opeyemi Odusanya, to je akekoo olodun keta ni Yunifasiti Bowen, Iwo, nipinle Osun. Inu ile awon obi re ni adugbo Alakuko, nipinle Eko, ni won ti gun un lobe pa nitori ko gba lati ba won doree. Won ni o n fi awon sako lawon se pa a.


Ojo kokandinlogun, osu keji
• Aare Goodluck Jonathan da gomina ileefowopamo ile wa, Sanusi Lamido, duro lenu ise lori awon oro to je mo sise owo ilu mokumoku. O yan Abileko Sarah Alade gege bii adele.


Ogunjo, osu keji
• Sanusi Lamido fi ehonu han si bi Aare Goodluck Jonathan se fun un niwee gbele-e naa. O ni oun yoo gba ile-ejo lo lati fi han pe owo oun mo.

• Ile igbimo asofin daru lori idaduro Sanusi Lamido, bi awon kan se n so pe aare ko letoo lati da a duro lawon mi-in so pe o le se bee labe ofin.


Ojo kokanlelogun, osu keji
• Ile-ejo giga Ikeja dajo iku fun Kolade Arowolo, okunrin ti won fesun kan pe o pa iyawo re, Titilayo, lodun 2011. Adajo Lateefat Okunnu lo dajo naa.

Ojo kerinlelogun, osu keji
• Awon ajinigbe ji baba agbalagba olori ile awon Aare Goodluck Jonathan, Oloye Inengite Nitabai, gbe nile re to wa ni Bayelsa.


Ojo keeedogbon, osu keji
• Awon gomina ipinle ti Naijiria ti n ri bentiroolu koro oju si awon gomina mokandinlogun apa Ariwa ti won so pe ki ijoba apapo maa fun ilu awon lowo to po. Won ni kawon eeyan naa loo wa ona ti owo yoo fi maa jade lodo won bi won ba nilo owo tabua.


Ojo kejidinlogbon, osu keji
• Awon Boko Haram pa akekoo metalelogoji nileewe ijoba apapo to wa ni Buni Yadi, ipinle Yobe.

Aago meji oru ni won ya wobe ti won dana sun yara awon omo naa ki won too maa dunbu won.


Ojo ketadinlogbon, osu keji
• Awon ebi Oloogbe Gani Fawehinmi ko ami-eye ti ijoba apapo fun un gege bii isami si ogorun-un odun Naijiria sile, won ni Gani ko ni i gba iru ebun bee to ba wa laye.

• Awon adajo agba meji niluu Abuja gba iwe gbele-e fungba die fun iwa aito ti won ni won ka mo won lowo. Adajo-binrin Gladys Olotu ati Ogbeni U.A Inyang ni awon ti obe ba nidii.


Ojo kejidinlogbon, osu keji
• Gbogbo awon to ti se olori Naijiria ri ti won si wa laye darapo mo Aare Goodluck Jonathan lofiisi re lati sami ogorun-un odun Naijiria.


Ojo kin-in-ni, osu keta
• Awon ajinigbe to ji Oloye Inengite Nitabai, baba Aare Goodluck Jonathan, gbe so pe dandan awon yoo gba milionu lona eedegbeta naira lowo awon ebi e.


Ojo keji, osu keta
• Gomina Rotimi Amaechi salaye idi ti ko se yoju sibi ayeye ogorun-un odun orile-ede yii niluu Abuja, o ni nitori pe aare ko wa si eyi tawon se niluu Portharcourt loun naa ko se yoju si eyi ti aare se.


Ojo keta, osu keta
• Aare Goodluck Jonathan fowo si yiyan ti won yan Adajo Idris Kutigi gege bii alaga igbimo apero ati Ojogbon Bolaji Akinyemi gege bii igbakeji alaga.


Ojo kerin, osu keta
• Aare Goodluck Jonathan yo minisita fun ere idaraya lorile-ede yii, Mallam Bolaji Abdulahi, nipo, o si fi Dokita Tamuno Danagogo ropo e lesekese.


Ojo karun-un, osu keta
• Orile-ede Amerika gbese le nnkan-ini Oloogbe Sanni Abacha tiye re je milionu lona ogota dola.

Ojo kefa, osu keta
• Ijoba apapo kede oruko awon omo igbimo ipade-apero. Akowe ijoba, Anyim Pius Anyim, lo kede awon oruko yii.


Ojo keje, osu kefa
• Awon ara Yobe ati Adamawa tako bi ijoba apapo se sofin ko-nile-gbele lawon ipinle mejeeji naa, ati bi won se ko awon agbofinro repete wo awon ipinle ohun.


Ojo kejo, osu keta
• Awon agbebonrin kan ti won le laaadota gbiyanju lati wo ile ijoba ipinle Enugu, sugbon awon olopaa, soja atawon Sifu Difensi ko fun won laaye. Okan ninu awon agbegbon naa ba isele ohun lo.


Ojo kesan-an, osu keta
• Naijiria kuna lati gba ami-eye ninu idije ere idaraya World Indoor Championship to waye lorile- ede Poland.


Ojo kewaa, osu keta
• Ileese ologun ile wa kede pe owo agbarijo awon ologun ti won n pe ni ‘Multi National Joint Task Force' ti te awon omo egbe Boko Haram.


Ojo kokanla, osu keta
• Awon Fulani agbebonrin kolu gomina ipinle Benue, Gabriel Suswam, nitosi ijoba ibile Guma, odidi wakati kan lawon agbebonrin naa pelu awon eso aabo gomina si fi yinbon lu ara won.


Ojo kejila, osu keta
• Eto iforukosile awon oludibo di wahala repete nipinle Osun pelu bii masinni ti ajo eleto idibo gbe lo sipinle naa ko se gba oruko awon to fee foruko sile wole. Awon omoota kolu awon eeyan lawon ilu bii Ife ati Ilesa.


Ojo ketala, osu keta
• Minisita fun oro ile okeere lorile-ede yii, Ambasado Aminu Wali, so fun ajo United Nation pe Naijiria ko setan lati yi ofin to de awon okunrin tabi obinrin to n ba ara won sun pada.

Ojo kerinla, osu keta
• Eeyan to din die nirinwo ni won riku ojiji he lasiko tawon omo egbe Boko Haram ati agbarijo awon omo-ogun ile wa koju ija sira won lojo tawon apanijaye ohun kolu ileese ologun ile wa nipinle Maiduguri ati Borno.

Ojo keeedogun, osu keta
• Eeyan mejidinlogun ku, opo awon mi-in si farapa nibi ayewo ti won se fawon to n wase nileese asobode ile wa to waye niluu Abuja.

Ojo kerindinlogun, osu keta
• Pasito Tunde Bakare tijo ‘Later Rain Assembly' ko milionu mejila naira tijoba apapo fun awon omo igbimo ipade-apero.


Ojo ketadinlogun, osu keta
• Aare Gooluck Jonathan fowo sawon adajo meeedogbon ile-ejo ko-te-mi-lorun ti ajo NJC yan.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 00:44:34 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Awon isele nlaodun to koja: Awon koko inu iroyin ati isele ni odun 2014 - 2015" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: