Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nibi ipade awon lobaloba gbogbo Naijiria, nibe ni won ti pa Ogagun Agba Aguiyi I
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Olayiwola Alaga

Nibi ipade awon lobaloba gbogbo Naijiria, nibe ni won ti pa Ogagun Agba Aguiyi Ironsi

Ni ojo kokandinlogun, osu keje, odun 1966, ni olori ijoba igba naa, Aguiyi Ironsi sabewo siluu Ibadan, ojo naa si je ojo kan to miringindin, ojo naa je ojo kan to larinrin. Se Ironsi ti sabewo siluu Eko, o si ti se si Abeokuta, Ibadan ni opon irin-ajo naa si sun kan. Nigba ti yoo fi de ilu Ibadan yii paapaa, awon ologun gbogbo ti n duro de e, Adekunle Fajuyi ti i se olori ijoba Western Region ko si sun, ko wo, bi Ironsi yoo se wa si ilu naa lalaafia ti yoo pada sibi to ti wa lo wa lokan re, se oun naa ti n gbo finrinfinrin, o mo pe iji nla fee ja bi awon ko ba tete dawo wahala to wa niluu nigba naa duro, ookan ibi ti iji naa yoo si ti ja wa ni ko ye enikeni ninu won. Nitori bee lo se je pe gbogbo won lo n sora, bi eegun yoo ba tile di eeyan, ko senikan to fe ko je nita baba oun, abewo Ironsi yii, iberu lo ko ba Adekunle Fajuyi.

Gbogbo bi Ironsi ti de, ti awon ero to lo bere soju ona ti won n duro de e, ti awon soja duro wamu ti won pade re, ti Olubadan si mu un de Oke Mapo, ti won jo duro lori oke giga naa ti won n wo gbogbo ilu Ibadan, ati nibi apeje pataki ti won se lale, Fajuyi ko kuro legbee oga re, o kuku mo pe bi oun ba wa nibe, bi asa kan yoo ba tile wole gbe omo ewure lo, oju gbogbo awon ni yoo se. Sugbon awon ti won n pete ijamba yii, boya nitori iberu Fajuyi, tabi nitori eto ti awon omoleyin Ironsi ti se ko le dan kinni kan wo, kaluku towo omo re bo aso ni. Tabi pe boya won n reti ohun ti Ironsi yoo so ti yoo dija ni, sugbon okunrin olori ijoba naa ko soro kan to le muja wa, kaka bee, ohun to n so fun won ni pe ise to wa nile fun gbogbo won lati se bayii ni ise ti Naijiria yoo fi wa nisokan, ko gbodo sogun, ko gbodo sote rara.Lojo keji re, iyen ni ogunjo, osu keje, odun 1966, Ironsi gbera o di ile Hausa, Kaduna lo si bale si gude, irin-ajo ile Hausa yii si je eyi to mu ipaya nla dani. Nibi toro naa le de, Ironsi funra re nigba ti yoo wonu eronpileeni n'Ibadan, ohun to so fawon to sin in debe ni pe, “A n lo o, boya a oo pada de laaye saa!” Ohun to fa iru oro yii naa ni pe Ironsi mo pe ile Hausa yii ni wahala gidi wa, ibe ni won ti n binu, awon soja won ti n mura lati gbajoba, awon oloselu won si ti n rin kaakiri lati so fawon araalu ki won fiya je omo Ibo, oro naa si ti di ijaagboro nibi ti won ti pa awon Ibo ati Yoruba towo won ba te. Ki Ironsi le salaye fun won ohun ti ijoba re n se ati ona to le mu alaafia wa nibi gbogbo to n tori e lo, se awon asaaju Hausa wonyi ti so fun un pe awon ofin kan to sese se sita, ko pa ofin naa re nikan ni alaafia le fi wa, bi bee ko, biliisi ni.

Ohun to je ki irin-ajo re sile Hausa mu nnkan dani naa ree, o ni jo pe awon kan ti wa loooto ti won fe koun ku sohun-un, o jo pe won ti seto lati pa oun sibe laarin ara won. Ohun tawon soja Hausa yii seto ni pe bo ba ti debe, bo ba ti di lowo ale, awon yoo ji i gbe, awon yoo si loo pa a sinu igbo kan, leyin naa ni awon yoo too gbe e jade. Bi awon ba si ti pa a si Kaduna lohun-un, awon yoo seto bi awon yoo se ko awon eeyan awon pada sile Hausa, awon yoo si yapa kuro lara Naijiria. Ohun tawon Hausa yii ti ro ree, awon soja si ti mura lati se ohun ti won fee se lale ojo to ba de siluu naa gan-an. Nitori eyi, nigba ti won so pe ki awon soja waa pade re, opolopo awon soja naa ni ko mura daadaa, awon mi-in ko tile se bii eni pe alejo de, nitori ohun tawon n reti, oto ni, won n reti ki ile su ki won ji Ironsi gbe ni.

Oro naa ti kuro ni nnkan asiri paapaa, nitori oga awon soja pata nibe ti gbo, iyen Duke Bassey, sugbon ko mo ohun to le se. Nitori bee lo se gba olori ijoba naa nimoran nigba tiyen de Kaduna pe ko je kawon dogbon soro to wa nile yii, nitori oun ti gbo pe awon soja Hausa ti mura lati pa Ironsi si Kaduna nibe. Amoran to gba a naa ni pe ki ogagun agba yii ma wa si baraaki lati waa so pe oun fee ba awon soja yii soro o, nise ni ko so pe ara oun ko ya rara, aare si ti mu oun, oun ko le yoju si won. O ni bo ba ti se bee, awon yoo dogbon gbe e jade, enikan ko si ni i ri awon ti awon yoo fi lo. Sugbon Ironsi taku, o ni oun ko le gba iru amoran bee, oun ko si le se bee ni toun, oun n bo ni baraaki o, bi won ba fee pa oun ki won tete se bee kia. Iyen ni Ironsi se lo si baraaki awon soja yii, to si ba won ti won ko mura sile.

Sugbon ko too de ni awon oyinbo ti won je olukoni ni Yunifasiti Ahmadu Bello ti tun gba awon oba won nimoran pe ki won kilo fawon omo won ki won ma pa Ironsi siluu won o, nitori oro naa le di ogun nla, ti gbogbo agbaye yoo si koyin si won. Won ni ki won je ko se ohun to waa se, ki won si je ko pada siluu re.

Bee ni Ironsi se lo sile Hausa to si pada, oro to ba won so nibe ko si tu irun kan bayii lara won, awon ko fe kinni kan latodo ijoba re, afi ko saa gbe kinni naa sile ko maa lo. Eyi lo se je pe irin-ajo ti Ironsi se yii, bii aja to lo sile ekun to bo ni, nitori enu ya awon ara Eko paapaa nigba ti won ri i to pada de, Babafemi Ogundipe to je igbakeji re to si loo pade re so pe irin-ajo to rin lo sodo awon Hausa lohun-un yii ti fihan pe aheso lasan loro awon ti won pariwo kiri pe awon Hausa fee gbajoba lowo awon.

Ni bayii, Ogagun Agba Ironsi ti lo sawon ipinle meji, o ti de ile Hausa, o si ti de ile Yoruba, sugbon o ku ipinle meji, iyen ipinle Eastern Region nile awon Ibo lohun-un, ati ipinle Midwest ni Binni. Alaye kan naa lo kuku n tori e lo, alaye nipa pe ijoba oun ko setan lati gbe Ibo gun ori awon eya to ku ni Naijiria, ati pe ofin ti a o se, ofin ki Naijiria le dara ni. Nitori e lo se fee kiri gbogbo ipinle to wa ni Naijiria, leyin to si ti lo sipinle meji, nigba to di ojo kerindinlogbon, osu keje, odun 1966, okunrin naa gbera, o di ilu Binni, olu ilu Midwest.

Bo ti n lo si papa-oko-ofurufu Ikeja lawon araalu n juwo si i, bee naa si ni won se fun un nigba to bo sile niluu Binni, awon omoleewe to lati papa naa titi de ile ijoba, won n juwo si Ironsi. Odidi ojo meji ni Ironsi fi wa nibe to n sabewo yii, David Ejoor ti i se gomina ibe si gba a lalejo gbaka¯-gbiya;n.

Ni deede aago mejo aaro ni ojo kejidinlogbon, osu keje, odun 1966, ni Ironsi pelu awon ti won jo loo sabewo si Binni kuro nibe, won n pada lo si ilu Ibadan. Bo tile je pe ko ju ojo mewaa ti won kuro niluu naa lo, sibe, won tun pada lo. Won pada lo nitori lojo naa ni awon oba gbogbo ni Naijiria waa sepade niluu Ibadan. Oro to sele nile Hausa, ijaagboro to sele nibe ti won paayan repete, ti awon ajoji si kuro nipinle naa lo fa ipade yii, awon oba Hausa fee ran awon oba ile Ibo ati ile Yoruba sawon eeyan won pe ki won maa pada bo nile Hausa lati wa maa sise won, nitori ko sogun mo, ko sote mo, ko si senikan ti yoo pa won lara.

Eyi lo je ki gbogbo won wa o, o si fere je pe gbogbo oba Naijiria lo peju si Ibadan lojo naa, kaluku won ninu agbada nla ati aso ibile gbogbo. Sugbon nibi ipade yii ni won ti mu Ironsi, nibe ni won pa a si.

Bawo lo se je bee, e ma a ka a lo ninu Iwe Iroyin Yoruba ose to n bo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 01:21:43 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Nibi ipade awon lobaloba gbogbo Naijiria, nibe ni won ti pa Ogagun Agba Aguiyi I" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: