Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ladoke Akintola fee di oga ara re, bee ni Obafemi Awolowo n so pe omoose oun ni,
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Akoroyin Olootu

Ladoke Akintola fee di oga ara re, bee ni Obafemi Awolowo n so pe omoose oun ni, ko le lo, asiko ibo odun 1960 ni nnkan tubo daru si i

Nitori pe iyawo Oloye Obafemi Awolowo, Hannah Idowu Dideolu, ati iyawo Oloye Ladoke Akintola, Faderera, ti ni ikunsinu ara won bo tile je pe won n se oju aye, ko pe ti kinni naa fi n ran mo awon oko won. Se oro aye yii le die, bi aarin awon ore meji ti won je okunrin ba n toro, nitori pe awon iyawo awon mejeeji naa n ba ara won se ni. Awon iyawo alakowe ko tile see ba se iru ere bee, won yoo da aarin awon mejeeji ru kiakia ni. Awolowo ati Akintola paapaa bere si i ni ara won sinu, kaka ki won si ri ara won bii ore ti won ti jo n se bo, won ri ara won bii orogun ni. Awolowo n tenumo on, o si n fi i huwa pe oun logaa, ipo oga ni Akintola si gbodo fi oun si, sugbon Akintola naa n so o moro, o si n hu u niwa pe oun ki i se omoose enikan ni toun o, ipo ti oun si wa, ki i se enikan lo gbe oun debe bi ko se Olorun ati awon araalu.

Boya Akintola fee di olori egbe Action Group, boya o fee gba ipo naa mo Awolowo lowo, ko seni kan to le so pato, nitori ko kuku du ipo olori egbe yii, sugbon iwa re to n hu lati igba to ti pinnu pe oun ko ni i maa gba ase lowo Awolowo mo ko yato si eni to fee gba ipo naa, nitori oun naa fee maa lo agbara olori egbe gege bii Awolowo ti n lo o nigba to n se Peremia, nitori opo awon nnkan to ba ti ro pe o dara fun araalu, tabi to ba ti ro pe o ye kijoba oun se ni yoo sare se, bee ni nigba miiran, yoo ti se awon kinni naa tan ko too je ki Awolowo gbo.Won-in ni eebu agba, mo mu aja lowo, o n na aja naa, bi ko ba si aja lowo mi, emi lo ba na nu-un, ohun ti Awolowo ka awon iwa Akintola yii si niyi, arifin nla lo si jo loju re pe enikan yoo fi oruko egbe Action Group jokoo si ori aga ijoba, yoo si so pe oun ko ni i fi toun se.

Akintola mo pe gbogbo ilu lo feran Awolowo, o si mo pe ko si ohun ti Awolowo se ju pe lasiko to fi n sejoba, o seto to te awon araalu lorun, eyi naa ni won se feran re. Bo ba je eleyii ni, ko si ohun to soro ninu iyen, oun Akintola naa yoo se eto to te awon ilu lorun, boun ba si ti se bee fun won, won yoo bere si i pariwo oruko toun naa kiri ni. Bi Awolowo ba se ise olori alatako re daadaa nile igbimo asofin to wa l«Ekoo, won yoo maa pariwo oruko re nibe, sugbon ni toun ni ile Yoruba nibi, oun yoo sejoba Western Region naa daadaa debii pe ko si eni ti yoo gbagbe oun, nitori eto ti yoo de araalu lorun loun yoo maa se.

Awolowo ko ri kinni naa bee rara, o ri i bii igba ti Akintola n mura lati pa oruko oun re nile Yoruba, ati pe nitori e lo se fee maa se awon eto kan to so pe iderun ilu loun fi n wa, oro naa si tubo mu ki ikunsinu po si i laarin ara won.

Awolowo fi ejo Akintola sun. Oni lojo kan nibere odun 1960, Akintola so foun were bii eni to kan n fi oro sere pe oun n ro kinni kan lokan, oun n ro o lati din owo-ori awon eeyan ku ni West, iyen ni pe owo-ori ti won n san ko ni i to iye ti won n san mo, won yoo din owoori naa ku repete. Ohun ti Akintola so ni pe owo ti wa, owo to n wole fun ijoba si ti po ju ti tele lo, nigba ti owo si ti po bee yen, ko si ohun to ye kawon se ju ki awon fi iru nnkan bee mo araalu lo, ki awon naa je ki won je anfaani owo to po, ona kan naa ti awon si fi le se bee ni ki awon din owo-ori ti won n san ku. Ohun ti Akintola wi niyi, sugbon Awolowo ni o kan so o foun bii eni to n sere lasan ni. Sugbon kia loun ti da a mo on lenu, oun ni ko ma ronu iru eto bee rara, nitori ohun to lewu patapata gbaa ni, bi wahala re ba si de, apa awon ko ni i ka a.

Awolowo ni leyin ti oun ti soro naa tan, Akintola ko wi kinni kan mo, sugbon nigba to di ojo kewaa, osu keji, odun 1960 yii, Peremia naa pe ipade awon ti won n seto inawo ninu ijoba re sile Awolowo. Awon meji pere naa ni o, Oloye Jonathan Odebiyi ti i se minisita fun eto inawo, ati Oloye Simeon Adebo ti i se akowe agba nileese eleto inawo yii, eni to tun je oun ni olori awon osise ijoba Western Region. Awolowo ni oun ko mo ohun ti Akintola pe ipade fun, afi nigba ti awon debe ti Akintola ni oro nipa owo-ori loun tori e pe ipade yii, oun woye pe o ye ki awon din owo-ori ti awon eeyan n san ni Western Region ku patapata. Owo-ori ti awon eeyan n san nigba naa din die ni Pon-un marun-un ni, Akintola si ri i pe o jo pe kinni naa n ni awon eeyan lara, ati pe ko tile ye kawon obinrin maa san owo-ori rara ni tiwon, kawon kuku pa a re.

Nibi ipade yii, Oloye Odebiyi lo koko soro, ohun to si so ni pe inu oun dun pe Akintola gbe oro naa wa si ipade bayii, ati pe oro naa soju Awolowo funra re, nitori oun ati oga oun yii ti n fa oro naa lati ojo die seyin ti oun ti so pe ohun ti won fee se yii ko daa, nigba ti Akintola ko si gba naa lo je koun ni ko gbe oro ohun wa siwaju Lida, asaaju egbe awon. Nigba naa ni Awolowo tenu boro, o si salaye pe ko dara lati din owo-ori naa ku rara. Oni idi merin ni kinni naa ko se dara, to si je ohun to lewu fun egbe awon. Akoko ni pe bi Akintola ba se bee, yoo fi abuku kan awon ijoba to sese koja lo ni, iyen ijoba Awolowo funra re, yoo si so ijoba naa di yepere debii pe awon araalu yoo ri ijoba naa bii ijoba afiyajeni, nitori won yoo so pe ijoba to n fi ipa gba owo-ori lowo awon ni, ati pe opelope Akintola, nigba to de ni owo-ori parun.

Idi keji ti Awolowo mu kale ni pe eeyan ko ni i tori pe nnkan oun n po si i ko bere si i fon on ka, kaka bee, yoo maa ko o pamo ni, nitori ojo ti oda ba da a, ko le ri ohun lo. Awolowo ni bi Akintola ba tori pe opo owo wa lapo ijoba bayii to ba ni ki awon eeyan ma sanwo-ori mo, tabi to ba din in ku, bi kinni naa ba waa sele ti awon ko ri owo bi awon ti n ri owo tele mo nko, iyonu ati idaamu ni yoo je, ko si ni i si bi awon yoo ti se e.

Yato si eyi, Awolowo ni ohun to mo awon eeyan lara ni pe bi e ba din kinni kan ku, o te awon eeyan lorun, awon ko ni i fe ko je pe won yoo tun fi le e ni. Oni inu awon ara Western Region yoo dun bayii bi Akintola ba din owo-ori ku, sugbon bi isoro ba de to ba fee fi kun owo ohun, yoo di wahala debii pe apa oun naa ko ni i ka a, nitori awon eeyan ki i fe ki owo gun ori owo-ori won. Awolowo ni lona kerin, awon obinrin Naijiria ki i fee sanwo-ori, bi ko ba si lawon ipinle mi-in, bi won ba wa n sanwo-ori ni West, afi kijoba ran won lowo lori e.

Nigba ti won so oro naa bee tan, Akintola ni ki awon tubo tesiwaju, bo ba tun di ojo mi-in kawon pade lori e, inu oun yoo si dun bi awon agbaagba egbe paapaa ba le waa pade ki awon jo gbe oro yii yewo.

Nibi yii ni won fenu oro naa jona si, ti ipade naa si wa sopin. Lesekese naa ni Awolowo so pe oun ti bere si i ko awon omo igbimo apase egbe jo, lati so pe kawon jo jokoo kawon wo o boya won le din owo-ori ku bi Akintola ti fe. Boya Akintola waa ro pe bi awon agbaagba egbe yii ba pade, ohun ti Awolowo fe yii naa lawon naa yoo fe ni o, ti won ko si ni i je koun se ohun toun fee se lati mu inu awon eeyan dun soun naa ki won si feran oun bi won ti feran Awolowo, ko seni to mo ohun to fa a, sugbon ohun to kan sele ni pe Akintola ko duro ki won se ipade mo, nigba to si di ojo keje, osu keta, odun 1960, Akintola kede jakejado pe ijoba oun ti din owo-ori ku ni West.

Oro yii bi Awolowo ninu, o ka a lara jojo. Ohun to n bi i ninu to tun n bi awon agbaagba egbe won ninu ni pe ki lo de ti Akintola n huwa bayii, ki lo de ti ko gbe oro sibi tawon ti jo so o si, ki lo de to lo n da nnkan se lowo ara re, toun naa si mo pe bi wahala yii ba sele, gbogbo egbe ni yoo kan patapata. Akintola gege bii olori ijoba re ko duro sidii pe o din owo-ori ku nikan, o tun kede pe awon obinrin kan ko ni i maa san owoori mo, awon ti iye ti won ba n gba ko ba ti to nnkan. Eto tuntun ti Akintola da se lowo ara tire ree gege bii olori ijoba, ko tile si ninu awon ohun ti won ti jo jiroro le lori tele, bee ni ko si fi kinni ohun lo enikeni ninu awon asaaju egbe re, kaluku kan gbo ikede naa pe ijoba ti pa owo-ori awon obinrin kan re ni. Nigba ti eyi sele, oro naa gbe ironu wo okan Awolowo, o si tubo mu ko ni Akintola sinu.

Ni ti Akintola ewe, ohun ko ri ohun to buru ninu gbogbo ohun toun se yii, idi naa si ni pe o ti ro o lokan ara re, bee ni awon eeyan ti won je tire paapaa si ti so fun un pe ijoba to n se, ijoba tire ni o, ki i se ijoba Awolowo, ohun to ba si se naa ni awon eeyan yoo maa royin leyin re, bo ba laju sile to ba je ki Awolowo ti oun wogbo, tabi ki Awolowo je koun se awon eto kan to le ko inira ba araalu, oruko Awolowo ko ni won yoo maa pariwo o, oruko tire ni won yoo maa pe. Sugbon ohun to n lo lowo gan-an ko niyen. Ohun to n lo gan-an ni pe Akintola fee gba ominira kuro labe Awolowo, o fe koun ni ase gege bii olori ijoba toun. Yato si eyi, nigba to ri i pe isoro wa foun lati da ohunkohun se boun ko ba je olori egbe AG, o gbiyanju lowo ara re lati je olori egbe naa, gege bi Awolowo ti se nigba toun naa n sejoba.

Awon ti ko ba je ki eti eni di, won ko ni i je ki inu eni dun. Awon ti won n gba Akintola ni awon amoran lori ohun ti yoo se yii, iyen awon ti won je minisita labe re, to se pe oun ni won n ba sise ki i je ki eti re di si opolopo oro to n lo lodo awon Awolowo, awon wonyi ni won yoo si maa so fun un pe nigba ti ko si nibe, ohun bayii ni Lida wi, oro bayii ni Baba Ikenne so. Bee, gbogbo awon oro ti won n so yii, ko si eyi ti yoo mu inu Akintola dun, kaka bee, yoo tubo maa mu eegun re le si i, yoo si maa mu inu re baje pe oga oun ko feran oun ni. Sugbon bi awon ti won n gboyii-soyii fun Akintola ti po to nni, eyin ni won n to awon ti Awolowo, nitori olori egbe AG naa ni awon opolopo eeyan ti won n ba Akintola sise, ati awon ti won je asaaju egbe, to je oun nikan lawon fokan tan, ohun to ba si fe lawon fee maa se ni tiwon.

Awon wonyi naa ko je ki eti Awolowo di si gbogbo igbese ti Akintola n gbe, nitori ko too so rara ni won yoo ti fi oro naa to Awolowo leti, ki Akintola si too kede ero yoowu to wa lokan re, oga re ti gbo gbogbo re tan patapata. Awon ohun toun naa n gbo yii ko mu inu re dun, ko si si ero meji to wa lokan re naa ju pe Akintola fee pa oruko toun re ko fi tire ropo, o fe ki awon ara Western Region gbagbe oruko toun Awolowo, ko je oruko tire ni won yoo maa pariwo. Won ti so fun Awolowo pe ti ko ba mura daadaa, Akintola ti n petepero, o si ti n mura lati gba ipo olori egbe awon lowo re, bo ba si ti gba a tan, ipo naa ni yoo maa lo lati fi se gbogbo ohun to ba fee se, ti ko si ni i si eni to le di i lowo mo. Lati igba yii naa si ni Awolowo ti n so Akintola lowo, to n so o lese, to si n wo ibi ti yoo ba yo soun ti oun yoo si tete ge iye apa re danu kia.

Sugbon gbogbo bi Akintola ti n se to yii, oun naa mo pe oun ko lagbara, nitori o ni iwonba ohun to le se, awon kinni kan wa to n ka a lowo ko. Ohun to n ka a lowo ko julo ni pe ijoba to n se nigba naa, iyen ijoba to n se lati odun 1959, ijoba Awolowo ni. Ohun ti eyi tumo si ni pe ibo ti won fi gbe Awolowo wole lojosi lo fi n sejoba, ko ti i si eni to mo oun, oun ko ti i dibo, bee ni ki i se awon ara Western Region ni won fa a kale bii olori won. Awolowo ni won dibo fun, igba toun si fee loo du ipo olori ile Naijiria ni 1959 yii lo sokale nipo Peremia to wa, lo waa ni ki Akintola waa gba kinni ohun ko si maa sejoba oun lo. Asiko to ye ki Awolowo gbejoba sile ko ti i pe rara, iyen ni pe ijoba Awolowo to ku l«Akintola n ba a se.

Ohun to fi ese eyi mule julo ni pe gbogbo awon minisita ti won n ba a sise, ati awon alase ileese ijoba nla nla paapaa, awon eeyan ti Awolowo ti yan sipo naa ko too kuro ni, awon omo Awolowo ni gbogbo won, Akintola ko ti i da awon eeyan tire yan, afi awon kookan ti won ba kan bo seyin re, awon ti won feran oun ju Awolowo to ti je oga won tele lo. Nigba ti ki i se oun lo ni awon minisita, ti ki i se oun lo ni awon oga ileese ijoba, iwonba ni faari ati fulenge re yoo mo, nitori gbogbo ipade to ba se, gbogbo ohun to ba si gba lero, lesekese ni kinni naa yoo ti de ile Awolowo, nigba toun funra re ko ti i so fun Awolowo, tabi ti ko tile lero lati so fun un rara. Alagbaro ki i gbin ogede, ohun ti won ba si fi elemoso so ni i so, o loju ohun ti Akintola le se nitori Awolowo lo nijoba to n se.

Sugbon Akintola ko fe bee mo, o mo pe koun too le sejoba oun bo ba se wu oun ati bi agbara oun ba ti to pelu imo ti oun ni, afi koun yo owo Awolowo kuro ninu ibo to gbe oun wole, bi bee ko, kaka ki awon eeyan daruko oun, oruko Awolowo yii kan naa ni won yoo maa da kaakiri. Ohun to fa a to fi fowo si i ki won tete seto ibo mi-in lodun 1960 niyi, bee asiko ti won iba dibo naa ko ti i sunmo rara. Sugbon nitori lati dan agbara idibo oun naa wo, lati mo bi awon eeyan ti se feran re to, ati lati le je koun naa ni ase gege bii eni ti araalu funra won dibo fun yato si eni ti Awolowo fa kale, Akintola tete fi ojo si ojo idibo, eyi si ni akoko ibo ti won yoo di leyin ti won ti fi enu ominira Naijiria jona. Lojo kejo, osu kejo, odun 1960, ni won dibo naa, bo si tile je pe Awolowo naa lo saaju awon ti won n polongo, sibe Akintola laye ri i pe o wole, to si di Peremia.

Ibo naa dara nitori pe opolopo ibi ti egbe AG ko ti wole tele ni won ti wole, Awolowo ni ise ti oun se lawon adugbo naa lo fa a, sugbon Akintola atawon eeyan re so pe nitori oselu ka-rin-ka-po ti oun Akintola se lawon eeyan se dibo fun egbe awon, iyen ni pe ki i se Awolowo ni won kuku feran debe, oun Akintola ni.

Sugbon lojo idibo yii gan-an ni ija mi-in ti tun n rugbo bo, bee awon araalu to dibo ko si mo kinni kan. Ohun to fa ija naa ni pe ni gbogbo ibi ti won ba ti dibo bee, leyin ti won ba ti dibo tan, gbogbo awon asaaju egbe pata yoo kori si ile Awolowo, ibe ni won yoo si wa ti gbogbo won yoo jo maa gbo ikede esi idibo naa bo se n wole, titi ti won yoo fi ka ibo naa tan pata. Sugbon lojo yii, Akintola ko dele Awolowo, kaka bee, oun duro si Ogbomoso, ko si so fun Awolowo pe oun ko ni i wa.

Ni ale pata, ni bii aago mewaa, ni Akintola pe oga re pe Ogbomoso loun wa, ati pe awon asaaju egbe kan nibe ni won so pe oun ko le fawon sile, ti won si waa jokoo ti oun nile ti awon jo n gbo esi idibo naa lapapo.

Eleyii bi Awolowo ninu, bo tile je pe ko so o jade. Iyen ni pe bi awon asaaju egbe AG se n waa jokoo sile oun ni Ibadan, ti awon jo n gbo esi idibo, iru e naa ni Akintola fee da sile l«Ogbomoso yii, oga fee di meji ninu oko ko niyi, ohun to n dun Awolowo nisale ikun lohun-un niyen. Akintola paapaa ko le so pe oun ko mo pe oga oun yoo binu, se oun naa ti pinnu lokan ara re pe nigba ti Awolowo n se Peremia lawon n lo sodo re loo gbo esi idibo, asiko Peremia toun lo dele yii, eni ba fee gbo esi idibo, odo oun ni yoo wa, ki i se oun loun yoo maa ko agbada korun lo sile enikan. Bee ni kinni ohun n rugbo bo, ohun ti ko daa si ni.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 01:28:39 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Ladoke Akintola fee di oga ara re, bee ni Obafemi Awolowo n so pe omoose oun ni," | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: