Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Asiri tu! Idi ti won se sun ojo idibo siwaju ree o
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Akoroyin Olootu

Asiri tu! Idi ti won se sun ojo idibo siwaju ree o

Kangun kangun, oro eto idibo to ye ko waye lopin ose yii ti kangun sibi kan bayii pelu bi alaga ajo eleto idibo lorile-ede yii, Ojogbon Attairu Jega, se kede ni ojo Abameta, Satide, ose to koja, pe eto idibo naa ko ni i waye bawon se seto e tele. Ni bayii, ojo kejidinlogbon, osu keta, odun yii, ni eto idibo aare to ye ko waye ni Satide, ose yii, yoo waye bayii, nigba ti tawon gomina ti won ti fi si ojo kejidinlogbon, osu yii, tele yoo waye lojo kokanla, osu kerin.

Lose to koja ni Iwe Iroyin Yoruba ti koko gbe e jade pe o see se ki won sun ojo idibo siwaju.

Eleyii ko seyin ariwo to ti n lo nigboro lati bii ojo die seyin lori eto idibo ohun, ko si jo pe igbese ajo eleto idibo, (INEC), ba opo eeyan lojiji rara, bo tile je pe ireti opo araalu ni pe ko si ona ti won yoo gba lati sun ojo idibo naa siwaju.Sugbon o, awon to n foye gbe gbogbo oro to n lo atawon ohun to n jade latenu awon alase ijoba ti n so pe afaimo ki won ma sun eto idibo ohun siwaju. Olori eso alaabo ile yii patapata, Alaaji Sambo Dasuki, lo koko ju bombu oro ohun ni nnkan bii ose die seyin. Oun lo koko so pe boun se n wo gbogbo nnkan ati bi eto aabo se ri, gege bii oga to n sakoso eto aabo, o jo pe ki won sun ojo idibo siwaju ni yoo daa.

Se oro ti akuwarapa ba so, ara orun lo so o. Eyi lo koko da ipaya ati iberu si okan awon oloselu atawon araalu, ti onikaluku si n pariwo pe ko seni to gbodo dan-an wo pe awon yoo sun ojo idibo siwaju. Bi awon oloselu se n so tiwon, bee lawon elegbejegbe naa n da si i, ariwo ti won si n pa ni pe ojo kerinla, osu keji, ko gbodo ye fun ibo aare.

Pelu re naa, ariwo tawon to faramo ki won sun ojo idibo siwaju, leyii ti opo won je omo egbe PDP n pa ni pe ajo eleto idibo ko ti i gbaradi fun eto idibo ohun, bi won ba si fi seto idibo naa gege bi awon kan se n pariwo, afaimo ki gbogbo nnkan ma mehe, eyi to see se ko fa wahala nla. Won ni kaadi alalope tawon araalu yoo fi dibo ko ti i kari, ida merinlelogbon ninu ogorun-un lo ti ri tie gba. Bee ni awon ohun eelo idibo ti won fee ko wa latoke okun ko ti i kari. Awon mi-in tun so pe awon agunbaniro ti ajo eleto idibo ti gbekele lati lo so pe awon ko ni i lo sile Hausa.

Yato si eyi, won ni awon osise ti ajo eleto idibo yoo lo to ye ki won ti maa ko lekoo bi won yoo se seto idibo naa, won ko ti i maa ko won. Ati pe awon oyinbo to fee wa latile okeere lati wa mojuto bi eto idibo naa se lo si ti so pe awon ko ni i de ile Hausa.

Gbogbo awawi orisiirisii bayii lawon ileese aare atawon alatileyin won pelu die ninu awon omo egbe APC ti won ni awon eeyan awon ko ti i ri kaadi alalope gba n pariwo.

Gege bi asiri to tu si Iwe Iroyin Yoruba lowo, awon kan ni awawi ti ko lese nile to ni gbogbo eyi tawon egbe PDP ka sile yii, won ni ohun ti won fee tori e sun eto idibo ohun siwaju ni pe ojora ti mu won, eru n ba won pe bo ba se pe bi gbogbo nnkan se wa yii naa lo wa ti won fi dibo, egbe oselu PDP yoo ja kule laye, won yoo gbo lorun. Pelu bi won se n ju Jonathan loko lotun-un losi ni awon ipinle to ti lo nile Hausa, ati bi ariwo Buhari ati egbe APC se rinle dodo kaakiri, o see se ki PDP ma rowo mu. Eyi gan-an la gbo pe ileese aare atawon alatileyin re se n wa gbogbo ona lati sun ojo idibo naa siwaju, eyi ti won gbagbo pe yoo fun won lanfaani lati tubo gbaradi si i.

Eru ariwo ti egbe oselu alatako atawon eeyan nla nla to fi mo awon oba n pa pe won ko gbodo sun un siwaju lo ba ileese aare ti won fi koko dawoko lori oro naa. Eyi lo si mu ki awon araalu gbagbo pe ibo naa yoo waye bo se ye ko lo. Nigba tawon eeyan tie ti n fehonu han, ti awon elegbejegbe ti n so pe ko sohun to jo ki won sun ojo idibo siwaju.

Ojoojumo ni oro yii n ko aibale okan ba Jonathan atawon eeyan re, eyi lo mu ki ileese aare fookan kun eeji, ki won si tun ronu ona ti won le gbe e gba. Nni won ba ni awon yoo gbe oro naa lo siwaju igbimo to ga julo lorile-ede yii, nibi ti awon olori eleto aabo gbogbo, awon aare to ti je ni Naijiria tele, atawon gomina pelu olori ile igbimo, asofin keekeke ati agba, alaga ajo eleto idibo ti pade. Se ohun tileese aare ro ni pe ibe ni won yoo ti kun oro naa, ti won yoo ti pa a.

Sugbon ohun ti won ko ro ni won ba pade nigba ti Ogagun Buhari to je oludije ipo aare fegbe APC yo sibi ipade naa ganboro, bo tile je pe odun bii mewaa seyin lo ti ba won jokoo sibi ipade ohun gbeyin.

Nloro ba beyin yo, gbogbo awon ti aare ti fee lo lati doju nnkan de ko le soro taara mo, egbe kan enu ni won fi n soro. Nigba ti won si bi alaga ajo eleto idibo pe se won ti mura sile fun ibo, o ni lako lawon wa bii ibon, ati pe ko sohun to le ye ojo idibo naa. Nloro ba di wo mi n wo o, ileese aare ko mo ibi ti won yoo gba mu oro naa mo.

Se ogbon ki i tan laye ka wa a lo sorun, pelu atileyin awon gomina PDP to wa nibi ipade ohun, ni won ba fenuko pe ki Atairu Jega to je oga ajo eleto idibo sepade pelu awon ileese eto aabo, nitori Jega ko le da idibo naa se lai si atileyin awon eeyan yii nibe.

Abajade ipade won ni Satide, ose to koja, ni pe Jega loun ti setan lati seto idibo, awon eleto aabo ni awon ko fun un ni idaniloju pe awon le pese aabo to to fun un. Won ni awon soja to wa nile, oro Boko Haram ni won n yanju, bee ni won fee koju awon afemisofo naa ki won si ba won ja leekan soso. Eyi ko le fun awon lanfaani lati seto aabo to pe fun awon ohun eelo eto idibo atawon araalu paapaa.

Jega so lojo Satide to koja pe bi won ba fi didaa oun, eto idibo naa yoo waye nitori awon ti wa ni imurasile, sugbon ki i se ohun ti oun nikan le da se lai fi ajo eso alaabo se. Nni ejo ba ku s'Ake, ko sohun ti Jega nikan si le da se lori oro naa mo, lo ba towo omo re boso, oun naa si fowo si i pe ki eto idibo to ye ko waye ni Satide ose yii, di sisun siwaju.

Won si ti fenuko bayii pe ibo aare ati ile igbimo asofin agba ati asoju-sofin yoo waye lojo kejidinlogbon, osu keta, odun yii. Nigba ti ti gomina ati ile igbimo asofin ipinle yoo waye ni ojo kokanla, osu kerin.

Sugbon inu bi awon egbe alatako, paapaa julo egbe oselu APC ti won ti nawo nara lati polongo ibo, ti won si ti wa ni imurasile fun opin ose yii ti won reti pe eto idibo yoo waye. Alaga egbe ohun, Odigie-Oyegun, so pe ifaseyin nla ni igbese naa je fun eto awa-ara-wa, bee lo ni awon agbaagba ninu egbe awon yoo jokoo lati sepade pajawiri, awon ko si ni i je ki eti araalu, paapaa awon omo egbe di si igbese tawon ba maa gbe.

Bee ni awon araalu kan naa n so pe ko daa bi won se sun eto idibo naa siwaju nitori ko sigba ti won sun un si to se pe gbogbo araalu ni yoo gba kaadi idibo, bee leyi ko so pe ki idibo naa lo lai ni eru ninu. Won tun so pe se ose mefa lawon eleto aabo fee fi ba Boko Haram ti won ko segun won latodun meta ja.

Sugbon oro ko ri bee fegbe PDP, senken ni inu won n dun fun ayipada ojo idibo yii bo tile je pe won ko so o sita. Ohun tawon kan yo so fun Iwe Iroyin Yoruba ni pe ise ti n lo labele lati pada lo si awon ile Hausa yii, bee ni won ti n be awon eeyan lowe sawon oba alaye ibe pe ki won ba awon ba awon eeyan won soro ki won se ti egbe PDP.

Eyi nikan ko, a gbo pe ohun to tun mu inu awon egbe PDP dun si ayipada ojo idibo yii ni pe won gbagbo pe ko ni i fi bee si owo mo lowo awon egbe alatako ti won ti n nawo lori ipolongo latojo yii wa pelu ero pe eto idibo naa yoo waye lopin ose yii.

Alakooso eto ipolongo Aare, Oloye Fani-Kayode naa ko sai soro o, o ni egbe awon, iyen PDP, ko lo wa nidii bi won se sun eto idibo siwaju bi ko se bi gbogbo nnkan se ri, o ni opo ni ko ti i ri kaadi idibo gba, ajo eleto idibo paapaa lawon ipenija kan ti ko han saye labenu, bee ni won ko ti i gbaradi to, eyi to le mu ipa lara ba eto idibo naa to ba waye.

Ohun tawon onwoye n so ni pe pelu bi won se sun eto idibo siwaju, eyi ko so pe ki eto naa lo lai ni eru ninu, sugbon gbogbo omo Naijiria lo fowo leran, won n wo ibi ti eto idibo naa yoo ja si ninu osu keta ti won sun un si.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 01:30:07 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Asiri tu! Idi ti won se sun ojo idibo siwaju ree o" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: