Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Leyin towo te Kehinde to digunjale niluu Ore, o ni kawon olopaa pa oun ti won ba
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Akoroyin Olootu

Leyin towo te Kehinde to digunjale niluu Ore, o ni kawon olopaa pa oun ti won ba tun mu oun

E jowo, e saanu mi. Be e ba tun ri mi ti mo tun loo jale, se ni ke e pa mi, e ma wule saanu mi mo bowo ba tun te mi. Ki i se pe mo deede n jale o, ebi-o¯ga¯ja¯-fowo;-me;ke; lo sun mi si i, e joo, mi o tun je se bee mo." Eyi nigbe tokunrin eni odun mokanlelogun kan, Kehinde Abiodun, fi bonu latimole olu ileese olopaa to wa l'Akure, nipinle Ondo, lasiko t'Iwe Iroyin Yoruba sabewo sibe l'Ojoru, Wesde, ose to koja.

Kehinde atawon emewa re, Akeem Gbenga, eni odun marundinlogbon ati Henry Obu to je eni odun metadinlogbon lowo awon olode to n so adugbo Kiwi, niluu Ore, nijoba ibile Odigbo, nipinle Ondo, te ni nnkan bii aago meta oru ojo ketadinlogbon, osu to koja, lasiko ti won loo ka awon eeyan kan mole, ti won si ja won lole owo ati ohun-ini bii ero ibanisoro.Gege bi enikan ta a foruko bo lasiiri se so f'Iwe Iroyin Yoruba lasiko ta a koko sabewo sibi isele ohun niluu Ore, lose to lo lohun-un, marun-un lawon ole ohun, leyin ti won si gba ibon owo olode to n so adugbo naa tan ti won fee de e lokun lo figbe bonu. Ariwo tawon egbe re to wa nitosi gbo lo je ki won tete sare wa lati wo ohun to n sele.

Igba ti won debe, won ba awon ole ohun pelu olode naa ta a foruko bo lasiiri nibi ti won ti n jijakadi, sugbon owo te meta ninu won. Awon afurasi ole towo te naa ni won fa le ileese olopaa ilu Ore lowo.

Nigba t'Iwe Iroyin Yoruba n foro wa Kehinde lenu wo, okunrin to pe ara re lomo bibi ilu Ondo ohun so pe lati ilu Ondo lawon ti maa n lo si Ore loo jale, bee lo daruko enikan toruko re n je Obasi gege bii oga patapata fun iko adigunjale ohun. O ni kowo awon olode too te awon ni Obasi to saaju awon lo ati enikan to ku ti raaye sa lo ni tiwon.

Kehinde fidi e mule pe loooto loun pelu Akeem ti figba kan fo soobu ri, leyii ti won tori e ran awon lewon odun kookan nigba naa. O ni lasiko tawon fi wa logba ewon ohun lawon salabaapade Obasi to tun fona ole jija han awon si i leyin ti won tu awon sile. Omokunrin ohun soro taanu-taanu pe ki i se ife inu ohun lati maa jale, sugbon nigba tebi fee yo oun loju loun sawari Obasi, tawon si jo n jale.

O ni ise sobata loun ko, ati pe airowo ra irinse wa lara idi toun tun fi yan ole jija laayo, bee omo pupo ti baba oun bi ni ko je ko rowo to awon titi to fi teri-gbaso. O tun so o di mimo pe agbara kaka lowo iya oun to si wa laye fi n to enu, awon nnkan wonyi loun si ro toun tun fi darapo mo iko adigunjale ti Obasi n dari ko too di pe owo te awon.

Ekun ni eni keta won, Henry Obu, n wa mu bii gaari ni tie, to si n ge;ka abamo je. O salaye fun akoroyin wa pe igba akoko toun yoo ba awon eeyan ohun jade lowo te oun, airi ile gbe lo je koun loo maa gbe lodo Obasi.

O ni Obasi kan so pe koun tele awon de ibi kan lojo tisele ohun waye ni, ati pe ita loun duro si ni gbogbo igba tawon Obasi fi n pitu loru ojo naa, afi boun se deede ri i ti ina toosi kan n se yanran-yanran soun loju, koun si too mo ohun to n sele, awon olode ti yi oun ka. O ni boun se fee dogbon sa mo won lowo ni olode kan fa obe yo to gun oun lowo.

Olopaa kan to ba Iwe Iroyin Yoruba soro fidi e mule pe nigba ti ileese olopaa sabewo sile ti won n gbe, won ba ibon oloju meji kan pelu opolopo ota, ibon oloju kan (meji), aake, iboju meji ati egberun mokanlelogun ati eedegberin naira (#21,700) ninu yara won.

Komisanna olopaa nipinle Ondo, Isaac Eke, ti so pe awon eeyan ohun o ni i pee foju baleejo ni kete tiwadii ba pari lori esun ti won fi kan won.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 01:46:52 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Leyin towo te Kehinde to digunjale niluu Ore, o ni kawon olopaa pa oun ti won ba" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: