Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Sebi e gbo ti ariwo awon ti won so pe won ri soja nile Tinubu: Olorun ni yoo gba
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Akoroyin Olootu

Sebi e gbo ti ariwo awon ti won so pe won ri soja nile Tinubu: Olorun ni yoo gba Jega

Bi eniyaan ba n tele ariwo awon oloselu, tohun-un yoo siwa-hu, bi eeyan si n tele opo ohun to ba ka ninu awon iwe iroyin, tabi lori awon ero ayelujara, oluware yoo maa wo inu igbo lo ni. Gbogbo awon nnkan wonyi lawon oloselu ti baje, won ko si fe ki enikeni mo nipa ododo ohun to n lo.

Lose to koja ni ariwo gbale, ariwo gba oko, iroyin naa si kaakiri agbaye, won ni awon ogunlogo soja ni won ri nile Asiwaju Bola Ahmed Tinubu, okan ninu awon olori egbe APC. Awon iwe iroyin nla nla to je awon ti egbe APC n lo lo fo kinni naa loju, won fi iroyin naa se akole gadagba, won si gbe e jade pe awon soja ti ya bo ile Tinubu o, won fee pa Tinubu ni, won fee ji i gbe ni ati bee bee lo.Sugbon iroyin ti won gbe jade yii, ko seni kan to foju ri soja nile Tinubu ninu won o, ohun ti won n so ni pe okan ninu awon akowe iroyin to n ba Tinubu sise lo kowe naa jade. Nnkan itiju pata waa ko ni iru iroyin bee je fun awon ileese iroyin wonyi, Eko ni gbogbo won wa, Eko ni won n gbe, Eko naa ni oro yii ti sele, sugbon ko si eyi to le lo si ile Tinbu lati ri awon soja ti won wa nibe ati lati ya aworan won bo ba see se, kaka be, won sare gbe iroyin to le da ilu ru, to le ba aye je, to le da ogun sile bee jade.

Titi di bi a se n wi yii, won o ri foto awon soja naa ya, sibe gbogbo ilu ti daru latari iroyin naa, iroyin pe awon soja wa nile Tinubu. Bo tile je pe awon ileese ologun so pe ko si soja ka nile Tinubu, nitori awon ko ran won nise sile oloselu naa, sibe, awon iwe iroyin wonyi n ko o jade.

Bi awon ti ko o lawon oloselu bere si i da si i, bee ni awon ajijagbara ti won ko nise meji bayii ju ibi ti oro oselu yoo ti dowo lo naa n so tiwon, won n pariwo pe soja fee pa Tinubu.

Bee won o ri soja, won ko ri aworan soja, won ni oru lawon soja n wa sile Tinubu. Iro buruku ati aheso awon oloselu ni, nigba ti awon eeyan sese bere si i soro pe nibo ni aworan awon soja naa wa, tawon ileese ologun soja naa pariwo pe ko si soja nile Tinubu, nigba naa lawon eeyan adaluru, a ko-mekunnu-lokan-soke yii too sinmi. Awon oloselu ile yii ko feran awa mekunnu, ohun ti won fe nitori atije ati atimu tiwon ni ki okan wa ma bale, ka maa sare kiri, ka maa wa ninu ijaya ni gbogbo igba. Tabi bawo ni eeyan yoo se gbe iru iroyin adagun-sile bee jade ti awon iwe iroyin nla nla yoo si maa gbe e jade lai se iwadii kankan lori re. Se nitori pe won fee le Jonathan lo yii naa, se nitori oro oselu yii naa! Haa, eleyii ma ga o!

Olorun ni yoo gba Jega Bee ni, Attahiru Jega to n seto ibo yii, Olorun ni yoo ko o yo. Nigba ti nnkan koko bere, ariwo ti a n gbo lati enu awon APC ni pe Jega ati PDP ti di awo kan naa, won jo n sepade, won fee sojooro ibo, won ti jo mule pelu ileese aare, egbe APC si logun pe o see se ki awon ma gba ibo ti Jega ba di wole, nitori o ti di awo kan naa pelu PDP.

Afi bi nnkan ti se yipada biri lojiji, to waa di pe egbe PDP lo ku to n pariwo pe awon ko fe Jega, Jega ti mura lati sojooro ki Buhari le wole, won ni ko pin kaadi idibo PVC bo se ye ko pin in, won ni oun atawon APC ni won jo sepade ni Dubai. Bayii ni APC gbe ewu ija wo ni tiwon, awon ti won si ti n bu Jega tele ba di ore re, won ni awon ko ni i gba laelae ki elomiiran seto idibo afi Jega, won ni okunrin ogun ni Jega, o dara ju leni to ye ko seto ibo, ati pe nitori ti ko ba awon PDP sojooro ni Jonathan se fee fibinu yo o. Ta waa ni ki eeyan gbagbo o, ewo si ni araalu mo ti Jega fee se. Iroyin to tile n jade lenu ojo meta yii ko dara rara, ko fi han bii eni pe owo Jega paapaa mo.

Won ni won ri awon iwe idibo kan ti won ti te ojo kerinla, osu keji, si, ti won si ti teka mo on lori legbe oselu kan, bee ni won tun ri iwe idibo mi-in ni London, ti won tun teka egbe oselu mi-in si i. Boya ni ko je gbogbo eyi ni egbe PDP ro papo ti won fi ni ki Jonathan le e lo, eyi naa si ni awon egbe APC ro ti won fi ni awon o le gba ki Jega ma seto idibo. Eni ti yoo ba esu jeun loro awon oloselu Naijiria, afi ki sibi re gun daadaa.

Bi Jega ba fee pe laye, tabi to fee je ki oruko oun wa ninu iwe iranti rere, awon mekunnu ile yii ni ko sise fun o, ko ma sise fun egbe oselu kankan. Bo ba sise fun egbe PDP, bo pe bo ya, asiri re yoo tu ni, bo si je egbe APC naa lo sise fun, asiri re yoo tu gbeyin ni, ete ati abuku ni yoo si keyin oro re, aye yoo se eleya re gbeyin ni. Sugbon ti eeyan ba gbe iru ise to wa lowo e yii dani, ko si ohun to ye ko maa ranti ju pe oruko rere san ju wura ati fadaka lo, ati pe ise ilu lo wa lowo oun, araalu ni ki oun sise fun. Bi Jega ba se bee, yoo maa daa fun un o, sugbon to ba se idakeji, oun pelu awon alagbara aye re mekunnu je, alagbara orun yoo mu un o!

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 01:57:58 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Sebi e gbo ti ariwo awon ti won so pe won ri soja nile Tinubu: Olorun ni yoo gba" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: