Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Eyi ni bi eeyan marun-un se re somi n'Ibadan
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Akoroyin Olootu

Eyi ni bi eeyan marun-un se re somi n'Ibadan

Ofo nla lo se laduugbo ti won n pe ni Idunnu, titi de ibi ti won n pe ni Alaku;ta niwaju Apete, n'Ibadan, nibi ti idile meji otooto ti padanu baba ati iya won pelu obinrin kan lati idile mi-in, bee lawon araadugbo naa padanu odidi eeyan marun-un leekan soso.

Inu e¯kun; omi to sele nibi odo Eleyele lawon eeyan naa segbe si nigba ti won n ti ibi ise won lo sile pelu oko oju omi leyin ojo nla to ro ni nnkan bii aago meje si mejo ale ojo Isegun, (Tusde), to koja.

Oruko awon to kagbako iku ojiji ohun ni Ogbeni Nafiu Tunde Yusuf ati iyawo e to n je Moriliat Alaba Yusuf, Sulaiman Ahmed ati Mulikat Ahmed, nigba ti enikarun-un won toun naa je olugbe adugbo Idunnu n je Abileko Ramotalahi Mudashiru.Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, lanloodu lawon eeyan naa laduugbo won, won ko si sese maa gba ori omi naa koja pelu oko oju omi nigba yoowu ti won ba n lo tabi ti won n dari bo lati ibi ise.

Moto tabi okada nikan la gbo pe gbogbo awon araadugbo naa maa n wo tele, ona Eleyele si A®wo;ta;n ni won maa n gba. Sugbon lati nnkan bii odun merin seyin ti ekun omi ti gbe afara (biriiji) ori odo Apete lo lo ti je pe oko oju omi ni awon kan maa n wo lati Eleyele koja si adugbo won nitori ona mi-in ti won tun le gba dele jinna die.

Leyin ti ojo to ro lale ojo Isegun ohun da lawon eeyan wonyi mu irin ajo won pon pelu oko oju omi gege bii ise won. A gbo pe Ogbeni Yusuf paapaa ti mo kinni ohun i wa, ati pe oun lo maa n wa a funra e to si maa n gbe awon ti irin-ajo won ba bo si asiko kan naa pelu tie koja si bebe odo lohun-un ni gbogbo igba tawon awako ba ti siwo ise. Oun naa lo wa oko lojo ti ijamba oju omi yii waye.

Bi won se de oju agbami la gbo pe iji ta a wi yii bere, o si jo pe iji ohun lo re; gbogbo won bo sinu omi lokookan laise pe oko naa dojude. Idi ni pe gbogbo eru ti won ko sinu oko si wa ninu e nigba ti won pada ri oko ohun legbee kan ori odo naa lojo keji.

Gbogbo igbiyanju ebi awon eeyan yii lati wa won ri lale ojo naa lo ja si pabo, afi laaaro ojo keji nigba ti won deede ba oku Abileko Moriliat Yusuf ati Abileko Mulikat Ahmed ni tente ori omi. Ojobo (Tosde) ni won too ri oku Abileko Ramotalahi Mudashiru. Ojo kerin isele ohun, iyen ojo Eti, (Fraide), to koja ni won si sese ri oku Ogbeni Yusuf ati Ahmed ti won je okunrin inu won lori omi bakan naa.

Oloogbe Yusuf la gbo pe o je alaga egbe awon onile gbogbo lagbegbe Idunnu, titi de adugbo ti won n pe ni Alakuta. Awon eroja to n lo ina ninu ile lo n ta loja Gbaremu to wa lona ileewe gbogbonise, Poli Ibadan, oun naa si ni olori awon Musulumi ti won je olugbe adugbo Idunnu ati Alakuta.

Omo meta ni Ogbeni Yusuf ati iyawo e fi saye lo, meji ninu won lo si ti wa nileewe giga.

Ipele eko kerin ni Zainab ti i se akobi idile Oloogbe Yusuf wa nileewe Fasiti OAU, Ile-Ife, nigba ti Uthman ti won bi tele e wa ni ipele keji nileewe gbogbonise (Poli) ijoba ipinle Oyo to wa niluu Saki. Ileewe lawon mejeeji wa tawon aladuugbo won fi pe won ni ipe pajawiri pe ki won yara maa bo n'Ibadan kia.

Igbagbo opo ninu awon to gbo nipa isele to ba ni ninu je yii ni pe nise ni orisa odo Eleyele lo awon eeyan naa lati fi bo ori ara re nigba ti olaju ati awon esin atohun-rin-wa ko je ki enikeni roju bo o mo lati igba pipe wa. Sugbon Zainab so pe ko si nnkan kan ti iku awon obi oun ni i se pelu orisa odo kankan nitori ninu akosile Oloun ni ohun gbogbo to ba sele si eda laye wa.

Gege bo se so, “O le je ojo to ro yen lo fa a, o si le je iji to ja lori omi lo re won bo sinu odo.

Sugbon oro pe orisa kan lo se kinni kan yen ki i se ara e. Iyen ko tie nitumo rara ni. Nnkan ti mo kan mo ni pe o see se ko je baba mi ni won wa oko oju omi yen nitori lati nnkan bii odun merin seyin ta a ti de adugbo yii lawon ati Uthman aburo mi ti ko o ti won si ti mo on wa.'' Nigba to n salaye bo se gbo iroyin ibanuje ohun, Zainab ti won pe lomo odun mokadinlogun so pe, ƒMo n mura lati lo si kilaasi laago mejo aaro ojo Wesde ni aburo mi (Uthman) pe mi pe okan ninu awon alabaagbe wa ni ki oun maa bo n'Ibadan. O ni oun gbiyanju lati pe nomba awon obi wa ati Islamiyyat to je abikeyin wa, sugbon ko wole.

“Lesekese lemi naa pe baba mi, nomba won ko lo, mo pe iya ati aburo wa naa, ibi kan naa lo ja si. Mo waa pe eni to pe Uthman, won ni ki emi naa maa bo wale. Mo ni ki ore mi kan tele mi wa lati ileewe, ba a se n bo lona ni mo bere si i gba ipe awon molebi wa lorisiirisii ti won n ki mi pe bawo ni ileewe, se daadaa ni mo wa ati bee bee lo. Latigba yen ni ara ti bere si i fu mi pe o ni lati je pe nnkan kan ti sele nile nitori opo ninu awon to n pe mi lojo yen ki i deede pe mi, bee ni mo n gbo ekun awon eeyan labele. Iyen lo je ki n gba pe nnkan kan sele ni, sugbon mi o mo pe nnkan to le to bayii ni, mo ro pe boya ijamba kan lasan lo kan se enikan.

Ori odo Eleyele la maa n gba wa sile lati nnkan bii odun merin ti biriiji Apete ti baje nitori ori omi yen ya ju ona mi-in tawon eeyan n gba lo. Eekookan, boya ta a ba loo ra ounje tabi ta a ba ni eru pupo la maa n gba ona titi Apete yen. Emi ati ore mi lo si eti odo Eleyele lati wo oko oju omi ka le tete dele, sugbon nise lawon eeyan di mi mu ti won n so pe omo won naa niyen. Iyen lo je ki n mo pe nnkan to sele yen ni i se pelu ijamba omi ati pe o see se ko je okan ninu awon obi mi ni nnkan yen sele si.

“Sugbon nnkan kan ti mo tun n ro to tun n ba mi leru ni pe awon obi mi ki i saaba fi ara won sile, opolopo igba ni won jo maa n wa papo. O da mi loju pe baba mi ko le se ki won ma wa ninu isele yen nitori won maa n fi oko oju omi gbe awon eeyan koja lori omi nigba ti won ba n bo wa sile lati ibi ise lale. Sugbon a ko gba ori omi wale lojo yen nitori awon eeyan mu mi wo inu moto kaa kan, a si gba ona Apete wa sile.

“Won ko je ki n lo sinu ile wa taara. Ile aladuugbo wa kan ni won koko gbe mi lo. Igba yen ni mo too mo nnkan to sele gan-an. Ba a se n bo wa sile ti awon eeyan bere si i soro nipa odo ti won n soro nipa oja ni ara ti fu mi.

“Inu ile yen ni aburo mi obinrin (Islamiyyat) naa wa. Bo se ri mi lo bu sekun. Mi o wule sese maa beere lowo e pe ki lo sele, mo ni se awon obi wa mejeeji saa ni, o ni bee ni. Nigba ti emi funra mi ti mo nnkan to sele yen, enikeni ko ni lati tun sese maa so fun mi mo.'' Nigba to n soro lori agbekele oun atawon aburo e leyin iku awon obi won, omobinrin akekoo Fasiti Ile-Ife yii so pe, “Inu Oloun Oba nikan la fi igbagbo wa si. Loooto ni mo kere lojo ori, sugbon mo ti ni iriri die nipa ile aye. Mo mo pe ko si eda to le ba eeyan gbe eru re leyin Oloun. Ti Oloun ba waa ran enikeni si wa lati ran wa lowo o, ope ni f'Oloun, a si maa dupe lowo eni naa. Bi a ko ba ri eni ran wa lowo naa, deede naa ni. Ohun ti mo saa mo ni pe kadara ti Oloun ba ti ko mo eeyan laye, ko ni i tase e, ohun to ba ti wa ninu akosile pe eeyan maa je laye, bo pe bo ya, eeyan maa je e lojo kan naa ni.

Musulumi ododo ni won pe Oloogbe Yusuf ati iyawo e ti opo eeyan mo awon mejeeji si Dadi Zainab ati Momi Zainab. Gbogbo awon to mo won ni won n royin won gege bii omoluabi eeyan pelu bo se je pe ife gbogbo eeyan lo joba lokan won.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe Oloogbe Yusuf ni eni akoko tawon onisowo oja Gbaremu koko ti oja fun ninu itan isedale oja naa. Won ni ko si enikeni to pate oja ninu awon olutaja oja yii lati aaro dale ojo Eti to koja nitori oju aanu ti okunrin naa ni si awon olutaja egbe e ko legbe, ko si si eni to ba iranlowo de odo e ti ki i se e fun bi Oloun ba se fun un lagbara mo.

Olugbe adugbo ohun kan, Ogbeni Sodiq Maruf Adeniyi, to tun je akowe-owo fun egbe awon onile lanloodu adugbo naa, labe isakoso Oloogbe Yusuf fidi e mule pe gbogbo eeyan ni toko-taya yii maa n se daadaa si, yala oluwa e je musulumi tabi elesin mi-in. O ni bee naa ni won maa n pon gbogbo eeyan le, ibaa je pe won ju eni naa lo.

Nitori ipo ti won wa laarin wa, ipa takuntakun ti won ko ati iwa rere ti won hu si gbogbo eeyan ni awa egbe lanloodu adugbo yii se sagbekale igbimo kan ti yoo maa toju awon omo ti won fi sile, ti won yoo si maa mojuto eto eko won.

Iya kan to n taja nitosi soobu Oloogbe Yusuf loja Gbaremu, sugbon ti a ko mo oruko e royin oloogbe naa pelu omije loju, o ni, ƒHaa! Asiri mi tu. Alaaanu mi ti saaju mi ku. Oloore mi ni Dadi Zainab, awon ni won ya mi ni egberun meeedogun naira ti mo fi sanwo idanwo NECO omo mi lojo Fraide to koja yii, mi o si ti i da owo yen pada fun won di bi mo se n soro yii.'' Iwe Iroyin Yoruba gbo pe eti odo ni won sinku Ogbeni Ahmed ati aya re si ni ibamu pelu ife okan awon ebi won.

Sugbon ilana isinku Musulumi ni won gba sin Yusuf ati aya re pelu obinrin kan yooku leyin tawon agbofinro tesan Eleyele, nibi ti DSP Moses Olawole Ayoola ti je olori, ti se gbogbo iwadii to ye.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 02:07:30 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Eyi ni bi eeyan marun-un se re somi n'Ibadan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: