Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nigba wo ni Obasanjo yoo fi oju ogun sile fawon omode
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin OlootuNigba wo ni Obasanjo yoo fi oju ogun sile fawon omodeE je ka foro sile soro o, nitori bi a ba sorosoro, ka ma gbagbe eni a de lokun, enikeni ti a ba de lokun ko ni i kuro ninu inira. Bee irorun igi ni irorun eye o, bi adie ba ba lokun, ara ko le ro okun, ara ko le ro adie. Bi a ko ba yanju oro idibo to wa lona yii, ara ko le ro enikeni, afi ka yanju re, ki Olorun si ba wa gbe e ka ibi to dara, ibi ti yoo ti ro wa lorun, ti a oo si le je gbogbo anfaani to ye ka je. Mo ri awon atejise yin, mo si mo pe ohun ti yoo wa lokan yin bayii ni eni ti emi funra mi yoo dibo fun, niwon igba to ti di dandan fun mi lati dibo, nitori bi enikeni ba n pariwo pe oun fe ilosiwaju fun Naijiria, ko si ohun meji to le fi fi eyi han lasiko ta a wa yii ju ki tohun dibo lo. Eniyan kan ko le so pe egbe kan ko dara, tabi ko ni awon oloselu ko sunwon, ko waa tori e so pe oun ko ni i dibo feni kan, tohun ko tun nnkan se, o n ba nnkan je si i ni.

Se e ri i, asiko ta a wa yii, asiko to le gan-an fun wa ni Naijiria ni, eni ti ko ba si mo bi oro ti je ko ni i mo bo ti lewu to. Nibi ti Naijiria ti ba oro ara re de, ko ye ki a tun wa ninu isoro ti a wa yii, nitori pe a ti ni awon agbalagba to ye ki won to wa sona, ko ye ka le sina rara, bo ba se pe ohun gbogbo lo bo se ye ko lo. Sugbon ohun gbogbo ko lo bo se ye ko lo, kaka ko lo deede, o tubo n daru si i ni. Lose to koja yii, Egbon Segun (Obasanjo) se ohun to ya mi lenu, koda bi mo se so pe mo rile mo rode to yii, oro naa jo mi loju, o ya mi lenu koja afenuso. Pe Obasanjo lo si gbangba, o mu kaadi egbe oselu re, iyen PDP, o mu un fun alaga egbe re laduugbo won, o ni ki iyen ya a perepere bii aso loju awon onitelifisan, awon oniredio, ati awon oniwee iroyin gbogbo. O ya mi lenu.

Bi awon kan ba wa ninu egbe PDP, bi won ba tori eyi gba ilu, ti won n jo pe awon reyin ota, awon reyin odi, won ko tan enikeni je o, ara won ni won n tan je. Idi ni pe bi adete ko ba le fun wara, iyen ko so pe ko le da wara nu, ko si si ija to le ju laye yii bi ija orogun-owo, nitori orogun-owo le ju orogun-oko lo. Ohun ti Obasanjo yoo ko ba won, paapaa niwonba gere ti ibo ku yii, apa won ko ni i ka a. Ki i se iye ero ti yoo ba Obasanjo kuro ninu PDP ni mo n so o, sugbon iye awon orile-ede agbaye ti won yoo ri egbe PDP ati ijoba won bii oniyeye lasan, nitori awon yii ko mo elomiiran ju Egbon yii lo. Oruko Obasanjo ni won n gbo kaakiri, eni kan naa ti won si ro pe o see foro lo, o see pe soro, o see ba se nile yii niyen.

Ibi gbogbo ni won ti n bowo fun oruko Egbon Segun, ohun ti lilo re yoo fi se akoba fun PDP niyen.

Bi egbe APC ba si waa n ro pe awon ta tete awon je, awon ti ri eja nla gbe bo Ifa, Obasanjo ti ba ti egbe re je, o ti waa jokoo ti awon, awon yoo lo Obasanjo lasiko ibo, ninu ajadii apere lawon naa n ponmi si, oniyeye gidi ni won. Bo ba ye won ni, won yoo mo pe ko si oore kan bayii ti lilo Obasanjo, tabi yiya kaadi PDP, tabi wiwa sinu egbe APC Obasanjo yoo se fawon. Oore kin ni@ Se ti ero repete ti Obasanjo n ko bo waa dibo lodo won ni abi ti atileyin ti ko legbe ti yoo se fun won. Egbeji somo fun agan, agan n yo, se agan ko mo pe egbeji to somo foun le pada gba omo e ni. Bi Obasanjo ba satileyin kan fun won ni APC ti won wole, ohun ti Obasanjo se ninu egbe re naa ni yoo se fun won. Tabi ki lo le Obasanjo ninu PDP gan-an!

Ko sohun meji to le Obasanjo ninu PDP ju ija agba to maa n sele laarin awon oloselu lo.

Ohun ti ki i ye opolopo wa ni pe egbe oselu ti a n ri yen, opolopo awon egbe keekeekee ni won parapo ti won di egbe oselu nla yii, bee ni awon egbe keekeekee yii a maa ba ara won jija agba ninu egbe nla. Eyi lo se je ninu PDP ti e n ri yen, awon omoleyin Obasanjo ni egbe tiwon, awon ti Yaradua ati Atiku ti ko kuro nibe wa nibe, awon omoleyin Babangida ni tiwon, bee si ni awon eeyan ti won n sejoba lowolowo bayii ti Jonahtan je olori won pelu awon egbe mi-in lati adugbo orisiirisi. Awon egbe keekeekee yii ni won n ja laarin ara won, egbe to ba si lagbara ni yoo te egbe keji ba, tabi ko le won jade pelu olori won. Ohun to sele si Obasanjo ati awon omoleyin re bii Lagun (Oyinlola), Segun (Oni) ati awon to ku won niyen.

Bi enikeni ba ro pe Egbon Segun n ba Jonathan ja nitori pe iyen ko se nnkan si ile Yoruba, tabi pe o n jale, tabi pe o n kowo je, nitori pe ko ba Boko Haram ja, tabi pe Obasanjo funra re feran APC, tohun ko mo bi awon oloselu ati awon agbaagba ta a ni nile yii se n huwa rara. Egbon Segun n ba Jonathan ja nitori Jonathan ko foribale fun un mo, Jonathan ko gboro si i lenu mo, Jonathan ko gba ase ti Obasanjo n pa wole mo, o si koyin si Egbon yii pelu gbogbo ise owo re ati awon omoleyin re gbogbo, ka sa so pe o gba agbara lowo Obasanjo. Ohun to faja niyen. Bee eleyii ki i se tuntun rara, bi eni to ba gbajoba lowo elomi-in ti n se niyen.

Sebi awon Babangida, Abdu-Salaami ati awon bii Atiku ni won loo mu Egbon funra re wa ni 1998 pe ko waa se aare, meloo loun naa gboro si lenu ninu won.

Ti won ba waa beere pe ta ni yoo pada jiya ohun to sele yii, e so fun won pe Egbon Segun funra re ni. Bii igba ti eeyan fi owo ara re se ara re ni. Bi Jonathan ba wole, iyonu ni fun un, nitori won yoo ri i pe gbogbo anfaani to to si i, gbogbo ase ti i ba maa pa, gbogbo bo ti le wole lai kanlekun, ti yoo si ranse pe eni to ba fee ba soro ninu minisita ati awon alase gbogbo, won yoo gbegidina fun un, won yoo si ri i pe awon so o di korofo, afi ko wa nile re ko kan maa pariwo lasan, asiko yii ni gbogbo agbara ati iyi ara re yoo si bo danu pata gege bii olori ijoba atijo. Bo ba si waa je Buhari lo wole, ohun ti yoo sele si Egbon yii yoo buru ju ki Jonathan wole lo. Idi ni pe awon wonyi gbon tayo awon PDP, won si mo pe bi Obasanjo ba sunmo awon, yoo ba ti egbe won je ni, kia ni won yoo si le e seyin laarin won.

Se gbogbo won lo mo pe nitori won ko je ki Obasanjo pase fun won ninu ijoba Jonathan lo se ba won ja, to si n tu asiri orisiirisii, awon yii ko ni i je ko sunmo won rara debii pe yoo ri asiri kan tu, bo ba pe won, won ko ni i dahun, won yoo kan maa gbe okeere rerin-in si i ni. Bo ba ri bee, ta ni ka bu@ Ko si elomiiran ti a oo bu ju egbon funra re lo. Agbalagba ki i binu to bayii, nitori oye lagba n wo. Bi agbalagba ba ri aja digbolugi lenu ona ile kan, ohun ti yoo se ni lati rora fi ogbon pada seyin titi ti won yoo fi mu aja naa kuro lona.

Sugbon bo ba se agba funra re lo koju si aja digbolugi to n ba a ja, ti aja ba se baba lese, tabi to so o di alaabo ara ti ko le jade mo, ko sohun ti won yoo fi aja se. Bee bo ba fogbon yera fun aja ni, nigba tawon omode ba pa aja yii tabi won le e lo, yoo tun pada waa wole ti aja yii ko je ko wo lojosi.

Odun merindinlogun ni Egbon ti fi se PDP, oun se olori ilu nibe, omo re se seneto, awon ore re di ipo nla nla mu, opo awon to si mu jade ni won wa nipo titi doni yii. Se iru ile ti eeyan fowo ara re ko bee yen lo ti ye ko ko jade, ko gbe katapila dani, ko ni oun yoo wo o dandan, ko waa maa ko eru re lo ile ti ko mo awon ti won ko o, nje iyen ko ni i le die. Lara ohun to n fa wahala fun wa niyi, awon agbalagba lo ye ko maa to wa sona, sugbon awon agbalagba wa ko ye ogun i ja, won ko kuro loju ogun fawon omode. Awon ni won fee maa jagun saa. Lara isoro to n koju ijoba demokiresi ati eto oselu wa gbogbo nile yii ree o.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 05:59:25 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Nigba wo ni Obasanjo yoo fi oju ogun sile fawon omode" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: