Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Rilwan gun Suraju nigo pa, o tun gbe telifisan ore e lo
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo Lati Owo Akoroyin OlootuRilwan gun Suraju nigo pa, o tun gbe telifisan ore e loBeeyan ba gbo bi awon araadugbo omodekunrin eni odun mokandinlogun kan to n je Saludeen Rilwan se n royin e gege bii ipanle omo ti ko ko ki ile su ninu oorun osan gangan, bi eni naa ba fi oju gan-an-ni Rilwan, yoo soro fun un lati gba iroyin ohun gbo nitori apeere esin Islam han lara e daadaa, o si jo pe irun kiki ti mo on lara gidi pelu bi iwaju ori e se dapaadi, to si dudu fafa fun irun kiki. Sugbon ba a se n ko iroyin yii, omokunrin naa ti gba oye kun oye, oju ipanle lawon araadugbo fi n wo o, o ti di apaayan, o si ti di jaguda-paalibaba-ole.

Lojo Eti (Fraide), ogbonjo, osu kin-ni-ni, odun yii, la gbo pe Rilwan wo ile ore e kan to n je Olayiwola Femi laduugbo ti won n pe ni Oke-Oloro, lagbegbe Omi-Adio, n'Ibadan, to si ji telifisan re gbe lo leyin to ti gun omo lanloodu okunrin naa to ba ninu ile ohun nigo pa.

Gege b'Iwe Iroyin Yorubase gbo, nigba ti Rilwan de ile Femi ni nnkan bii aago kan osan ojo naa, omo lanloodu e ta a wi yii to n je Kareem Alaba Suraju lo ba ninu yara e. Leyin to beere Femi tiyen ni ko si nile ni Rilwan lo si idi telifisan pelebe ti won maa n de mo ara ogiri ninu ile (Plasma) to si bere si i tu u lai se pe o gba iyonda lowo oni-nnkan tabi eni to ba nibe. Eyi lo mu ki Suraju pe e nija, sugbon Rilwan taku pe oun yoo saa gbe telifisan naa lo dandan ni.

Oro yii la gbo pe won n fa mo ara won lowo ti Rilwan fi taju kan-an ri igo oti elerindodo ti Suraju sese mu tan, o fo o mole poo, o si fi ibi somusomu ara akufo igo naa gun un lori. Bi Suraju se subu lule to bere si i ja raparapa nile fun irora nla niyen.

Nigba naa ni Rilwan sese waa farabale tu telifisan to fee tu, to si papa gbe e lo. Won ni ara Suraju ko ya lojo naa, iyen ni ko je ko le lo si mosalasi lati ki irun Jimoh to fi lo si yara ore e lati reju die. Inu yara yii ni Femi fi i si ti oun fi gba ibi ise tie lo. Nibi ti Suraju ti n fi oti elerindodo tutu re ongbe lowo ninu yara naa ni Rilwan eruuku ti wole, igo elerindodo ohun naa lo si fo to fi gun un lori pa.

Iba se pe bi Rilwan se gun Suraju nigo tan lo gbe telifisan to fee gbe to ba tie lo jeje, boya iba san, boya awon araale iba tete ri i gbe lo si ileewosan nigba to si n japoro iku lowo, sugbon nise ni Rilwan tun mu kokoro to tun tilekun yara naa pa mo Suraju nibi ti iyen ti n japoro iku.

Ko pe pupo ti Rilwan jade ni Ogbeni Kareem ti i se Baba Suraju de, iyen ni nnkan bii aago meji aabo osan. O lo enu ona yara Femi ti i se ayalegbe e lati ki won ku ile pelu bo se je pe Femi nikan ti won da gba sinu ile ohun gege bii ayalegbe e naa lo sikeji won nibe. Sugbon ti;ti¯ to ba ilekun lo je ko gba pe awon omokunrin naa ti lo sibi ise ni, laimo pe Suraju si wa ninu ile to n japoro iku lowo, iyen bi ko ba ti i gbemin-in mi lasiko naa. Nigba ti Femi silekun yara e nigba to ti ibi ise de ni nnkan bii aago mejo ale ojo naa ni won too ri oku Suraju ninu agbara eje nileele nibe.

Ero akoroyin wa nigba ti iroyin yii koko te e lowo ni pe nise ni Femi je Rilwan lowo to si fee fi dukia okunrin naa di gbese to je e. Sugbon o se ni ni kayeefi lati gbo pe Femi ko je Rilwan lowo kankan, nise lomokunrin naa kan fee ja a lole lasan, ori eyi lo fi fi odidi emi eeyan kan sofo. Bee, ati Femi ti won ja lole ni o, ati Suraju ti won pa o, titi dori Rilwan funra e ti won lo hu awon iwa odaran mejeeji yii, ore ni won, adugbo Omi-Adio kan naa ni won jo n gbe.

Bo se je pe Suraju nikan ni Rilwan ba ninu ile ko je ki Rilwan ri enikeni sofofo e pelu ise ibi to se, sugbon sibesibe, Oloun pada tu u lasiiri. Awon araadugbo ohun ti won gbo iroyin iku aimodi ti Suraju ku ati ona iyanu ti telifisan Femi gba sonu so pe Rilwan fi telifisan kan lo awon lojo kan naa ti awon isele kayeefi ohun waye, sugbon awon ko ra a lowo e.

Eyi lo mu ki awon ebi Suraju ati Femi fi isele ohun to awon olopaa leti, ti awon agbofinro si mu Rilwan ti mole leyin ti won ti fidi e mule pe oun lo hu awon iwa odaran naa.

Rilwan naa ko tako esun apaayan ati ole jija to so o di ero atimole olopaa, o ni loooto loun gbe telifisan Femi ti oun si gun Suraju nigo, sugbon oun ko ni i lokan lati paayan, bee ni ko si ninu erongba oun lati ja Femi lole nigba ti oun n pinnu lati loo ba a lalejo. Bi oun se de ile e ti oun ko ba a loun fee pada sile ki ero naa too so si oun lokan pe ki oun loo ji telifisan daadaa ti okunrin naa kan mo ara ogiri yara e, sugbon nitori ti Suraju n di oun lowo lati mu ero buruku okan oun se loun se gun un nigo lati pa a lenu mo.

Gege bo se salaye oro naa, ƒBi mo se wo yara Femi, Suraju ni mo ba, mo beere lowo e pe Femi nko, o lo jade. Mo ba peyinda, mo n lo. Sugbon bi mo se de enu ona ita ni ero kan so si mi lokan pe ki n tun pada, bi mo se pada niyen. Suraju waa beere pe se mo ti ri Femi ni, mo ni mi o ri i. Leyin iyen ni Suraju jade, o ni oun fee sare de toileeti, mo si bo sidii telifisan Plasma re, mo bere si i tu u lara ogiri ti won de e mo.

“Nigba ti Suraju pada de to ba mi nibi ti mo ti n tu awon waya ti won fi de telifisan mo ogiri, o ni ki lo de, mo ni mo fee gbe e lo ni. O ni se mo ti so fun Femi ni, mo ni mi o ti i ri Femi, o si ni oun ko ni i je ki n tu u.

Nibi ta a ti n fa oro yen lowo ni mo ti ri igo miniraasi kan nile, mo fo o mole, mo si fi gun un lori ki n too gbe telifisan lo.” Ni ibamu pelu ibeere akoroyin wa, Rilwan to pera e ni onisowo aso laduugbo Omi-Adio, n'Ibadan, so pe Femi ko je oun lowo kankan, ko tile se oun lese kankan paapaa, oun kan wa a lo sile lasan ni.

Nje nibo ni telifisan to ji gbe ohun wa, afurasi ohun ni oun ti so o sinu odo nigba ti oun ko ri eni ra a lowo oun. Sugbon a gbo pe odo ohun ko jin rara, won si wa gbogbo odo ohun, won ko ri telifisan kankan nibe, eyi to fi han pe o see se kawon kan ti ri i nibe ki won si ti gbe e lo.

Alukoro ileese olopaa ipinle Oyo, DSP Adekunle Ajisebutu, eni to fidi isele yii mule so o di mimo pe Rilwan ti wa ni SCID, iyen eka to n sewadii isele odaran, eyi to wa laduugbo Iyaganku, n'Ibadan.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 06:02:48 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"Rilwan gun Suraju nigo pa, o tun gbe telifisan ore e lo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: