Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


O d'oju e! Aisan-okan kolu Kate pelu oyun osu meje ninu, milionu mewaa lo n
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
Lati Owo Akoroyin Olootu


O d'oju e o! Aisan-okan kolu Kate pelu oyun osu meje ninu, milionu mewaa lo nilo fun ise-abe


Stephen Ajagbe, Ilorin Lati igba ti Abileko Kate Onimisi ti wa ninu oyun osu mefa lo ti n ba wahala ohun finra, aisan to lagbara kan lo kolu u to fi dero ileewosan ekose Fasiti Ilorin, UITH. Nigba tawon dokita se ayewo fun un, won sakiyesi pe aisan-okan lo n se obinrin alaboyun naa, latigba naa lo si ti wa lori akete aisan.


Ipo ti Kate wa yii lawon dokita so pe o lewu fun omo inu re, nitori ohun to daju ni pe ko ni i le bi omo naa to ba fi le wo osu mesan-an, idi niyi ti won fi sise-abe fun un ti won si gbe omo osu mefa ohun jade ninu re. Won setoju omo naa sinu igo ti won maa n gbe awon omo ikoko ti osu won ko pe si nileewosan, o si ye.


Loooto lomo naa n se daadaa, sugbon ipo ti iya re wa bayii buru jai, o si n kigbe fun iranlowo awon eleyinju-aanu ati ijoba lorile-ede Naijiria lati saaanu re ko ma je pe aisan yii lo maa mu emi re lo. Se lobinrin ohun ti ru ku eegun, beeyan ba si ri asiko to segbeyawo nibi toju re ti gun rege si ipo to wa bayii, onitohun yoo kaaanu re.Gege bawon onimo-isegun akosemose nileewosan UITH se so, aisan-okan to n da a laamu je eyi to je lati ipase oyun to ni, ati pe oro aisan-okan ti won lo n se obinrin yii je ajogunba.


Won ni baba re gan-an, aisan naa lo pa a latari airi owo toju re.


Oko obinrin naa, Ogbeni Yusuf Onimisi, to je akekoo-jade nileewe Fasiti Ilorin ko nise kankan lowo bayii to n se. Ile-ejo ko-te-mi-lorun, iyen 'Sharia Court of Appeal' to wa niluu Lokoja lo ti n sise tele ko too di pe won da a duro lodun 2009, latigba naa lo ti deni to n wa ise kiri.


Isoro nla gbaa ni okunrin ti iyawo re ti bimo merin fun naa n koju lowo bayii, bee, gbogbo ona to maa fi doola emi iyawo re lo n wa kaakiri.


Gege bi Ogbeni Onimisi se salaye, nigba ti iyawo re wa ninu oyun osu mefa, sadeede lo taji lojo kan to si loun ko le min daadaa mo. Loju-ese lo loun gbe e digbadigba lo sileewosan UITH, nibe ni won ti da a duro titi ti oyun inu re fi di osu meje.


"Awon dokita so fun un pe ko ni i le bi omo inu re to je eleekerin yii. Won sakiyesi pe ko si ayipada ninu ilera re, idi niyi tawon dokita fi so pe ise-abe lawon yoo se fun un lati gbe omo jade." O salaye pe won sise-abe naa to si yori si rere, sugbon ibi ti won ti n setoju iya omo naa lo wa, won ni pelu ipo ti obinrin naa wa, o see se ki okan re dase sile nigbakugba.


Oko obinrin naa to fere maa bomi loju so pe awon dokita ti ni orile-ede India ni won yoo ti sise-abe fun iyawo oun. Leyin ti won si sewadii lati odo ileewosan naa ni won so pe yoo na won ni milionu mewaa naira lati pari gbogbo e. Owo naa wa lara owo irinna, ounje, owo ileewosan, owo-oogun ati ise-abe pelu ti dokita ti yoo tele e lo sorile-ede India.


Oko obinrin eni odun metalelogbon ohun salaye pe soosi toun n lo atawon eka re kaakiri ni won ti n se iranlowo fawon lati maa toju obinrin naa nileewosan.


Omo merin ni toko-tiyawo ohun ni bayii, omo odun mejo ni akobi je tawon ibeji to tele e si je omo odun meje. Omo to gbeyin tawon dokita gbe jade ninu obinrin naa lasiko ti aisan ohun kolu u ti pe omo osu mewaa bayii.


Eni to ba fee ran obinrin naa lowo le pe oko re sori aago yii: 08187445339 tabi 07035235403. Bakan naa le le fi ohun te e ba ni ranse si akaunti re: Zenith Bank, Yusuf Onimisi 2084702090 tabi First Bank, Yusuf Onimisi 3035223156.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 06:21:46 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"O d'oju e! Aisan-okan kolu Kate pelu oyun osu meje ninu, milionu mewaa lo n" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: