Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ni Jonathan ba di metalokan Alaaji Pasito Oluwo Nitori atiwole: Iyen lo je ki Bu
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Akoroyin Olootu

Ni Jonathan ba di metalokan Alaaji Pasito Oluwo Nitori atiwole: Iyen lo je ki Buhari sare wale

Ti Jonathan ba mo wipe gbogbo asarekir oun lasiko ibo pabo ni yio jasi bo ya ki ba ti kuku gba kamu. Sugbon eni ti yio kuku sofo owo ati ti ibo bi won ba ka egberun Psam fun un ko kuku ni je.  Beeyan ba n wo orisiirisii foto Aare Jonahan to n jade lojoojumo, oluware yoo mo pe okunrin naa ti di ohun tawon eeyan n pe ni metalokan. Ki i se metalokan tawon onikristeni o, metalokan tawon abalaye ni, beeyan si pe e ni Alaaji Pasito Oluwo, oluware ko jayopa.

Oun nikan le o ri ti yoo maa kunle niwaju Baba Adeboye, bo si kuro nibe yoo kunle lodo Oyedepo, tabi ko je oun ati Oritsajefor ni won yoo jo maa fa ara won lowo kaakiri. Bi eeyan ba wa n wo awon foto naa to n so lokan ara re pe ara meriiri ree, nibi to ti n so naa ni yoo ti tun ri Jonathan laarin awon asaaju Musulumi ti yoo ko saarin awon onilawani ti yoo si maa sadura kikankikan, awon ti won si ri i ni Ileefe lose to koja nibi ti awon oba alaye ti na opa ase bii ogorun-un sori oun nikan mo pe oro to wa nile yii ki i se kekere, gbogbo ona ti Jonathan ba le gba ni yoo gba ko le wole ibo won. Jonathan nikan naa ni ni soosi, oun nikan naa ni ni mosalasi, oun naa tun ni lodo awon elesin-kan-abalaye, se nitori oro ibo yii naa ni!

Ohun ti a n wi niyen pe eletan lawon oloselu, ko si iyato kan bayii laarin won. Se awon oba sese wa niluu ni abi awon onisoosi ni won sese wa nibe, abi won sese da mosalasi sile ni!


Sugbon ni gbogbo igba yen, Jonathan ati awon eeyan re ko nilo won, won ko tile ranti pe awon eeyan yii wa nibi kan, sugbon nigba ti ibo wole yii, ti okunrin naa n wa eni ti yoo dibo fun un, o wa won de soosi, o kan won lara ni mosalasi, o sare tele won leyin lodo awon eriwo-ya gbogbo. Eleyii ki i se ife, ki i se pe Jonathan feran awon eeyan yii, ohun ti yoo gba lowo won lo gbe e debe, bo ba si ti gba a tan, ti won ba ti dibo fun un, won ko tun ni i gburoo e mo, afi ojo ti Olorun ba ko o.

Iyen lo je ki Buhari sare wale Bo ba je pe ara Buhari ti ya daadaa, ti okunrin naa si se semusemu bi awon alariwo inu APC se n wi, oun lo ye ko saaju irin ti won rin l'Ekoo lose to koja yii. Oun lo ye ko saaju, oun lo ye ko maa rin faufau, ki awon to ku si tele e. Sebi oun ni won fee dibo fun, oun lo fee se aare wa. Eyi ti Tinubu ati Osinbajo pelu awon gomina saaju yii ko to, Buhari laye fee ri. Awon naa si mo o, won mo daadaa, sugbon etan oselu ile yii ko ni i je ki won so ododo.

Awon naa mo pe bi Buhari ba rin iru irin bee, Olorun ma je ki iran di meji loja-oba, ko ma je ambulansi ti won fee fi ko awon alatileyin egbe to ba subu ni won yoo fi gbe baba funra re, oro naa ko si ni i see so sita. Iyen ni won se fogbon yi oro naa, won ni ero yoo ti po ju bi won ba pe Buhari, ero yoo ju milionu kan tawon fe lo, ero ti won ri naa ni ko to nnkan yii o. Ko si ohun to buru bi ara Buhari ko ba ya, ko si ohun to le nibe rara, nitori eni kan ki i se okuta, gbogbo wa la maa n saisan, gbogbo wa la si maa n lo si osibitu tabi ileewosan lati wa itoju lo. Eyi ti ko dara ni ki awon to ye ki won so ooto maa puro, ki won maa tan awon araalu nitori oro ibo, ati nitori oro oselu, ohun to le fa ibinu Olorun fun won ni.

Ara Buhari ko ya, kaka ki won si fi i sile ko gba itoju re pe daadaa, won sare di i meru, won ni ko maa bo nile nitori iberu ohun ti awon eeyan fee so. Ki lawon eeyan fee so, kin ni won iba wi to ju alaafia ati ilera okunrin yii lo. Se nitori ipo olori Naijiria yii naa, nitori ile aye afowoba-fi-sile yii naa.

O ga o! Ki Olorun je ki emi Buhari gun, ko si pe laye, sugbon ko sora e, ko ma je ki awon afoselu-jeun ti i pa. Bi ara re ko ba ya, ko kuku gbatoju, nitori eni to ba gbadun ni i roju sejoba.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 06:31:35 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Ni Jonathan ba di metalokan Alaaji Pasito Oluwo Nitori atiwole: Iyen lo je ki Bu" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: