Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Iku afurasi da wahala sile n'Ilorin, ileese olopaa loun ko mo nipa e
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
Lati Owo Stephen Ajagbe, Ilorin


Iku afurasi da wahala sile n'Ilorin, ileese olopaa loun ko mo nipa e


Oro odomokunrin kan to padanu emi e lasiko tawon soja ati otelemuye ya bo ibugbe e laduugbo Anifowose, lagbegbe Pakata, niluu Ilorin, ti da awuyewuye sile o. Bawon kan se n so pe afurasi ohun je okan lara awon a-femi-diku, Boko Haram, bee lawon mi-in n so pe janduku to n fooro emi awon eeyan lasan ni.


Isele to waye lose to koja lo da iberu-bojo sile lagbegbe naa nitori bawon agbofinro pelu afurasi odaran ohun ti ko seni to mo oruko e titi di bi a ti n soro yii, tabi iru ese to se gan-an ti won fi seku pa a dana ibon bo ara won.


Iwe Iroyin Yorubagbo pe afi bii igba ti won wa loju ogun loro ohun ri lasiko tawon agbofinro to ya bo ile ti afurasi ohun pelu iya re ati iyawo re kan n gbe doju ibon ko ara won. Lasiko yii lawon omo-ogun ti fi ota ibon re e bale, toun naa si yin okan lara awon agbofinro to wa sibe nibon lapa.Enikan to se e fokan tan tisele ohun soju e salaye pe o ti pe ti won ti n fura si omokunrin naa, ati pe awon agbofinro ti n dode e fun bii ojo meta ko too di pe owo pada ba a.


O ni o see se ko je pe irin omokunrin naa ko mo rara nitori se lo maa n lo to si maa n bo tawon eeyan ko mo pato ohun to n se. Pelu bi afurasi ohun se koju awon agbofinro to wa sibe pelu ibon, o fi han pe o see se ko je ogbontarigi odaran.


Ohun ta a ri gbo ni pe awon agbofinro bale gude sile okunrin yii ni nnkan bii aago meji oru, won si jo woya ija titi tile ojo naa fi mo. Lasiko to sakiyesi pe agbara awon agbofinro ohun ju toun lo lo sare loo farapamo si ori aja ile naa. Gbogbo orule ibe ni won fi ota-ibon fo, nise lawon agbofinro si yi gbogbo ile onipeteesi ohun ka. Ojo ibon n ro keukeu lakolako ni gbogbo agbegbe naa, se ni onikaluku si fori pamo sinu ile.


Akoroyin wa gbo pe lowo okan lara awon agbofinro to wa sibe lo ti ja ibon gba. Leyin to yin gbogbo ota inu e tan ni won pada mu un bale. Se ni won yinbon fun un lagbari ati ese, lojuese naa lo dagbere faye.


Gege bi eni yii se salaye, ni nnkan bii aago meji oru ojo Sannde to lo lohun-un lawon bere si i gbo iro ibon to n ro lakolako. ƒOhun ta a ro ni pe awon janduku oloselu lo n ba ara won ja, sugbon nigba to ya la sakiyesi pe okunrin Ebira, omo Kogi, to gba ile fun iya re ati iyawo e lagbegbe naa lo n ba awon agbofinro fa a. Lara awon agbofinro ohun lawon soja atawon omo-ogun ofurufu.


ƒOhun ti mo fura si ni pe awon agbofinro ti n so o fun ojo die, koda eni to ni ile to n gbe ohun ti fee le e kuro ninu ile naa tele. Pelu bo se gba ibon to si dojuko awon agbofinro fi han pe o see se ko je odaran paraku.«« Gege bi onitohun se salaye, saaju kawon agbofinro too dojuko afurasi naa ni won ti koko le gbogbo awon to n gbe inu ile naa jade, ti won si gba foonu owo won, sugbon afurasi naa ko bawon ara ile ohun jade, se lo loo sapamo. Leyin naa ni won keefin pe ori aja ile lo loo farasin si ti won si bere si i rojo ibon si gbogbo orule titi towo fi ba a.


Kete ti won ri i pe o ti ku ni won gbe oku e lo tefetefe, ti ko si seni to mo pato ibi ti won gbe e lo. Sugbon ohun ta a gbo ni pe awon agbofinro mu iya ati iyawo afurasi naa si ahamo.


Lasiko ti Iwe Iroyin Yorubape alukoro ileese olopaa nipinle Kwara, Ogbeni Ajayi Okasanmi, lati fidi isele naa mule, o ni ileese olopaa ko lowo ninu isele naa. O ni awon soja ati otelemuye lo lepa afurasi ohun, leyin ti gbogbo agbegbe naa daru ni won too ranse pe awon olopaa.


O fi kun un pe titi di bi a se n ko iroyin yii, oun ko le so pato ohun ti okunrin ohun se tabi pe o je omo egbe Boko Haram. Bakan naa lo ni ko sohun to jo aheso kan tawon eeyan n gbe kiri pe ileese olopaa fi panpe oba gbe iya oloogbe ohun pelu iyawo re nitori awon eeyan naa ko si ni ago awon rara.


Sugbon o, ohun to si sokunkun sawon araalu ni pe iru ese wo gan-an lomokunrin ohun se to fi deni tawon agbofinro n lepa, ati pe nibo gan-an ni iya ati iyawo re wa bayii. Bakan naa, bawon agbofinro se ko lati so nnkan kan nipa oro oloogbe ohun si n ko awon araalu lominu.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 06:45:43 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"Iku afurasi da wahala sile n'Ilorin, ileese olopaa loun ko mo nipa e" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: