Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ipo oba da wahala sile n'Ido-Ani, lawon omooba ba lura won lalubami
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Akoroyin Olootu


Ipo oba da wahala sile n'Ido-Ani, lawon omooba ba lura won lalubami


Wahala ipo oba Alani ti Ido-Ani, nijoba ibile Ose, nipinle Ondo, tun gbona mi-in yo lose to koja yii pelu bi won se ni okan ninu awon omo Oba Olufemi Olutoye, to gba opa-ase losu kewaa, odun to koja gege bii Alani ti Ido-Ani lu die ninu awon ti won je alatako baba e atawon olori kan lalubami ninu aafin.


Gege bi iwe esun ti agbejoro agbarijo awon omooba ilu Ido-Ani, Amofin C. Olufunmilola Abitoye, ko si komisanna olopaa ipinle Ondo, o ni bii ere nisele ohun bere lojo Abameta, Satide, ti i se ojo kejidinlogbon, osu to koja, lasiko ti won n sayeye isinku olori awon afobaje niluu Ido-Ani, iyen Oloye S.O.AOniye, ninu ijo ‘Anglican Holy Trinity' to wa niluu naa.


Ninu iwe esun to je oju iwe meta ohun ni won ti fidi e mule pe okan ninu awon omo oloogbe, Eni-Owo Gbenga Oniye, to je ore igba ewe Omooba Jackson Agunloye Falade (eni toun naa n dupo oba pelu Oba Olutoye) wa nileejosin lojo naa, ohun gbogbo si ti n lo letoleto ko too di pe Agbo;pa¯a; Oba, Alaaji Ibrahim Kamaru Agbede, eni ti inagije re n je Kakuleto wole, ko si ri ibomi-in jokoo si ju iwaju Omooba Jackson Falade lo.Won ni bo ba se pe eni to gbe opa-ase ohun jokoo e jeeje ni, o see se ko ma si wahala kankan. Sugbon nise lo n fi opa-ase naa sako si Omooba Falade, eyi to bi iyen ninu to fi dide loo ba a lati gba opa lowo e. N ni ija ba be sile ninu soosi pelu bawon mejeeji se bere si i lo opa-ase mora won lowo. Opelope alufaa atawon omo ijo to tete da sija naa, iba da eto isinku ohun ru.


Leyin ti wahala yii lo sile die ni won leni to je omo kabiyesi to wa lori oye bayii, iyen Dokita Segun Olutoye, loo ko awon olopaa wa ki won le fi panpe ofin gbe Omooba Falade fun ohun to se yii, sugbon omo olokuu, Gbenga Oniye, yari pe oun loun pe okunrin naa lati wa sibi ayeye oku baba oun. Oro naa ni won fa titi, sugbon won pada yanju e tawon olopaa ko fi ri Falade mu lo.


Se ni won ro pe ohnu gbogbo ti pari sibe, afi bi awon idile awon omooba to ku se pejo siwaju aafin lati sepade, ninu eyi tawon omooba bii Folasade Falade, Adeseye Falade atawon mi-in wa. Akoko naa l'Iwe Iroyin Yoruba gbo pe Dokita Segun Olutoye ohun ko awon toogi ya bo won nibe, koda won ni Segun ati agbopa, iyen Kakuleto lo saaju awon toogi ohun pelu apola igi, ibon, obe ati ada lowo, ti won si bere si i lu awon omooba ohun bii eni lu bembe.


Omooba Adegboro Falade ni won lawon janduku ohun koko tawo si, ti won si din dundu iya fun un titi to fi daku. Won ni gbogbo akitiyan awon omooba yooku lati ran Adegboro lowo lawon eeyan naa ko je ko seso rere. Awon olopaa ti won so pe won pe lati waa ran won lowo gan-an ko yoju, se lo da bii eni pe won da won da wahala ohun ni.


Lara awon ti won tun fara gba ninu isele naa ni Omooba-binrin Folasade Falade, eni ti won so pe won fi kokoro ya lagbon, bee ni won tun lu u bii eni lu bara. Bakan naa ni won so pe won fowo ba Omooba-binrin Folasade Aladekoba, eni ti won gba lesee nikun, leyii to mu keje maa jade lati oju-ara re.


Omooba-binrin Adekemi Aladekoba naa o gbeyin ninu awon ti ko faraare lo lojo ta a n wi yii pelu bi won se so pe won gun un lobe lapa, bee ni won lo si soobu to ti n taja, nibi ti won ti ko keegi ororo marun-un lo, ti won si tun pa merin ninu awon aja to n sin.


Agbejoro yii waa ro komisanna olopaa nipinle Ondo lati tete wa nnkan se soro ohun ko too di pe Dokita Segun to je omo Oba Olufemi Olutoye tun tesiwaju ninu iya to fi n je awon omooba ohun pelu bi won se so pe tosan toru lo fi n wa Jackson Falade lati pa a.


Sugbon nigba ti eni ti won lo da wahala ohun sile n b'Iwe Iroyin Yoruba soro lori ohun to pile rogbodiyan naa, Alaaji Ibrahim Kamaru (Kakulato) so pe iro buruku lawon omooba ohun pa pelu gbogbo ejo ti won ro sile yii.


O ni ko sohun to kan oun lori wahala to n waye nitori oun ki i somo bibi ilu Ido-Ani.


O salaye pe loooto loun gbe opa-ase lo si soosi lati soju kabiyesi, sugbon ko si ohun to jo o pe oun n fi opaase la Omooba Jackson loju. O ni jeje ohun loun jokoo nigba ti Falade deede waa ba oun to si n mura lati gba opa-ase naa. Eyi lo fa bi awon se n du u ko too di pe alufaa soosi ohun da si i, ti won si yanju ija naa.


Alaaji Kamaru ni loooto lawon olopaa wa sibi isele yii, sugbon bi awon eeyan to wa nibe se yanju e ni ko je ki won mu enikeni lo. O ni ko sohun to jo pe Dokita Segun Olutoye ko toogi waa da ipade awon omooba ru< Segun ohun o tie si n'Ido-Ani ni gbogbo igba ti rogbodiyan ohun fi waye.


Elomi-in to tun ba wa soro lasiko ta a sabewo siluu naa, sugbon to ni ka foruko boun lasiiri da e¯bi gbogbo isele ohun ru awon omooba ti won din dundu iya fun naa. O ni ko si idi ti ko fi ye ki won ni suuru niwon igba toro naa ti wa nile-ejo, ati pe bi Jackson Falade ko ba gbiyanju lati ja opa-ase gba, wahala ohun ko ni i waye rara.


Bakan naa leni to ti figba kan ri se adele oba niluu naa, Omooba-binrin Falade, so pe bi won o ba waa lu won ki won si se won lese, ko le see se kawon omooba se ara won lese. O ni ooto ni gbogbo esun ti won fi kan Segun ati Kakuleto to gbe opa-ase lo si soosi, bee lo fidi e mule pe bi ki i baa se oro iyanselodi eka eto idajo to n lo lowo, o see se koro ejo ti won pe oba naa ti de ibi kan.


Saaju kawon omooba lati idile Falade too fiwe esun tiwon fi sowo si komisanna olopaa ipinle Ondo lojo karun-un, osu ta a wa yii, lawon oloye Ido-Ani ti koko ko iwe esun tiwon ranse sofiisi ‘Area Commander' olopaa to wa niluu Owo, nipinle Ondo, lati fi to o leti pe idile Falade ti ru ofin iwe adehun tilu naa towo bo ki alaafia le joba. Won ni Omooba Falade la Alaaji Dada Alagbede (bi won se ko oruko re niyen) nigbaaju ninu soosi lasiko ti eto isinku Oloye Samuel Oniye n lo lowo, ti omooba naa atawon ebi re kan si tun n da ilu ru pelu ada ati aake.


Ibi toro ohun yoo yori si lenikan ko ti i le so bayii pelu bo se je pe igun kin-in-ni ati ekeji lo n naka abuku sira won pe lagbaja bayii lo n da ilu ru, to si n se awon eeyan lese. Gbogbo akitiyan wa lati ba eni to je alukoro olopaa ipinle Ondo, ASP Wole Ogodo, soro lo ja si pabo, nomba ero ibanisoro re ko wole lasiko ta a pe e.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 06:48:53 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Ipo oba da wahala sile n'Ido-Ani, lawon omooba ba lura won lalubami" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: