Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
[ Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise ]

·Ni Ti Ooni, Alaafin Ati Aare Ona Kakanfo
·Sugbon Ta La Ri Ba Wi, Bi Ko Je Baba To Fi Omo Re Foko L'oru
·Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo
·Leyin Odun Mokanla, Bose Fee Ko Oko Re Sile l'Abeokuta: Nitori Orekunrin Re
·Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
·Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
·Iyaale Ile To Fi Kokeeni Soyun Ti n Ka Boroboro
·Lati Ekiti Ni Wasiu Atawon Ore Re Ti Waa Fi Owo Ayederu Raja n'Ilorin
·Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Se dandan ni ki Obanikoro tun se minisita ni ! E ma puro tan araalu je mo, ko da
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Akoroyin Olootu


Se dandan ni ki Obanikoro tun se minisita ni ! E ma puro tan araalu je mo, ko daa o


Oro awon oloselu yii ki i ye enikan, ko si ohun ti won ko le se bi won ba ti ha tan pata. Abi e ko ri Jonathan ti ko ri elomiran mu ni gbogbo Eko ju Musiliu Obanikoro to ti se minisita to ti se seneto lo. Iru iwa ibaje ati iwa ailero wo niyi jare. Eeyan n se minisita lowo, o fi ipo re sile, o ni oun ko se mo, oun fee loo du ipo gomina nipinle oun. Sebi o te e lorun ni, tete kuku loro ile aye, bo ba wole, deede, bi ko ba si wole, ko maa wa nnkan mi-in se. Sugbon okunrin yii lo lati du ipo naa, ko wole, kaka ki Jonathan si je ko maa lo, won ni ko tun maa bo waa se minisita. Iyen ni pe nigba ti Obanikoro fi n se minisita re, o kuku se awon ise agbayanu kan to fi je pe bi iru re ko ba si ninu ijoba, Naijiria yoo daru pata ni. Bo ba je pe Obanikoro se ise nla kan gege bii minisita ni Jonathan se da a pada, awa araalu ko mo, a ko gbo nnkan kan, ko ye wa paapaa. Sugbon awon ti won gbon modi oro, nitori alakatanpo lo se bi obo ko gbon, obo si logbon lori, tinu obo lobo n se ni. Ki i se pe Jonathan feran awon ara Eko, ki i se pe o feran Obanikoro, ko si nigbagbo pe Obanikoro ni ise ribiribi kan ti yoo se fun aabo oun, sugbon ko fe ki okunrin naa da ibo to n bo yii ru, iyen lo se fi ipo minisita tu u loju.


Nibi ti won ba ti wa n se iru iyen, ti won n fi ipo gidi tu oloselu loju, boya o mose tabi ko mose, boya o wulo tabi ko wulo, iru ijoba bee ki i se aseyori, lara ohun to si ko ifaseyin ati aseeri ba ijoba ti Jonathan n se niyen. Abiru kin ni gbogbo eleyii, bawo lawon eeyan wonyi kuku se ya alaimokan bii eyi. O ma se o, o tan lara omo to n je eeru!E ma puro tan araalu je mo, ko daa o Bi eniyan ba n ko orin ti ko dun, oun naa yoo kuku maa fi eti ara re gbo o. Eni buru mo, enikeni to ba n se ohun ti ko dara mo pe ohun ti oun n se ko dara, sugbon eni ti yoo so fun un ti yoo so oro naa di ija ni yoo maa wa kiri. Won ni ijoba ipinle Osun ko sanwo osu, awon osise binu, won tori e se iwode, awon kan si bere si i gbe ohun ti ko sele ati iro ojukoju jade.


Oto ni awon ti won bere si i ko oro si ori ero ayelujara pe awon egbe alatako lo wa nidii oro naa, won ni awon PDP ni, awon ni won ni ki awon eeyan maa sewode, won fee ba oruko ijoba ati gomina je ni. Se iru oro bee yen mu ogbon kankan dani sa, oro omugo pata gbaa ni.


Ki lo kan egbe alatako, e gbaayan lesee, e ki atori mole e tun n na an, e ni ko gbodo ke, e tun waa ni ko gbodo gbin, nibo ni won ti n se iru iyen! Bi Osun ko ba je awon osise re ni owo osu marun-un, ta ni yoo ni ki osise kan jade ko maa ba oruko ijoba je, ta ni yoo ba ibi to ba ti n jeun je, ko seni ti yoo se bee o jare. Nigba ti won so iyen ti ko ta, awon mi-in tun gbe e, won yi ohun pada, won ni bi Osun ba je owo osu marun-un, ko si ohun to buru ninu e, nigba to je awon ipinle kan wa ni ile Hausa ti won ti je owo osu mefa, awon mi-in je osu meje. Se oro tun niyen, eni ti aye re baje lo ye ka farawe ni abi eni ti aye re ba dara. Bi awon ipinle ile Hausa ba jewo osu repete, ti won ko san an fawon osise won, sebi iyen ba won lara mu ni, o waa ye ki awa se bee ni. Nibi ti awon osise yoo ti ran omo won nileewe, ti won yoo ti jeun, ti won yoo si wo moto debi ise, ki won too gbo bukaata gbogbo to wa lori won. Bee bi inu ko ba dun, ise ko le se, ko si eni kan ti yoo gbari mo iwe ti yoo maa kowe akolaagun nigba ti ko ba ti i jeun, opolo paapaa ko ni i sise. Awon ti won fo oro naa loju ni awon ti won so pe Jonathan ko owo pamo ni, ko fee fun Osun lowo.

Iranu! Rotimi Amaechi, omo egbe APC to n fi ojoojumo bu Jonathan kiri, ijoba ko ko owo e pamo, Aregbesola ti oun ati Jonathan ko ni ija kan ti ni yoo ko owo re pamo. Sebi ose to koja lohun-un ni ijoba Jonathan sese tun fowo si i pe ki ijoba Osun ya owo ti won fee ya, awon yoo se oniduuro fun won. Se ijoba koriira won l'Osun niyen. Ohun ti awon oloselu yii ko jewo ni pe ijoba Osun je gbese, ijoba yii ti yawo repete nita, owo ti won si ya lawon olowo n gba ele ori e, koda won ko ti i gba oju owo.

Nigba ti Gomina Aregbesola ko ti i gba ipinle Osun, ariwo ti a n gbo ni pe Olagunsoye Oyinlola lo ko gbogbo owo je, oun lo ko gbogbo owo si banki agbaye, Olorun si kuku se e, Oyinlola ohun ti wa ninu egbe won bayii, ki lo de ti won ko beere ibi to ko owo to ji nigba naa lo. Bi oro ti n ri niyi, nigba ti a ba n soro ibaje ati abuku nitori ati gbajoba, ti a gbajoba tan ti a ri i pe gbogbo ohun ti a n so ko ri bee, ti a waa bere si i yawo lati fi sare tu araalu loju, bo pe bo ya, awon olowo yoo beere owo won, bi nnkan yoo si ti daru naa ree o.


Afi ka gbadura, Olorun ko ni i je ko le ju bayii lo fun wa l'Osun o!

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 07:08:21 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Se dandan ni ki Obanikoro tun se minisita ni ! E ma puro tan araalu je mo, ko da" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: