Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Awon obinrin rinhooho losan-an gangan l'Emure Ekiti, won ni afi ki Kabiyesi
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Akoroyin Olootu


Awon obinrin rinhooho losan-an gangan l'Emure Ekiti, won ni afi ki Kabiyesi tu awon odo to ti mole sile


Nise niluu Emure-Ekiti, nijoba ibile Emure, nipinle Ekiti, gbona girigiri lojo kokanla, osu yii, ti i se Ojoru, Wesde, ose to koja nitori bi awon obinrin ilu naa tinu n bi se fehonu han lori bi Kabiyesi ilu ohun, Oba Emmanuel Adebayo, se n fowo ola gba awon mekunnu ilu loju, to si n lo ipo naa ni ilokulo.


Nise lawon obinrin ti won rinhooho pelu ewe lowo yii n ko orisiirisii orin, ti won si n te e mo Kabiyesi naa leti pe dandan ni ko wa ona tawon odokunrin to to ogbon niye tawon olopaa ti mole lojo kesan-an, osu yii, latari pe won n fehonu han lori aini nnkan amayederun yoo fi ri itusile.


Oba Emmanuel Adebayo, eni to ti je igbakeji oga-agba olopaa ri nipinle Eko ati Abuja ko too joba lawon obinrin naa so pe inu awon ko dun si bo se n tuko ilu naa.


Akoroyin Iwe Iroyin Yoruba sabewo siluu Emure, nibe la si ti ri i gbo pe wahala naa bere lojo Aje, Monde, ojo kesan-an, osu keta, nigba tawon odo tinu n bi lori aisi ina ati bi banki kankan ko se sise lati bii osu meje seyin n fehonu han.Gege bi okan lara awon odo ilu naa to ba wa soro, Ogbeni Olaoye Olayinka, se so, nise ni inu bi Kabiyesi nitori igbese tawonodo gbe yii, eyi to mu un fibinu fi aafin re sile lati loo koju awon odo naa. Kete to debe lo pase fawon odo naa lati dawo ifehonu-han won duro, ki won si pale gbogbo igi atawon nnkan ti won ko di ona abawole ilu kuro lai fi akoko sofo.


Okunrin naa tisele ohun soju re so pe nise ni Oba Adebayo tile tun mura lati yowo ese si asaaju awon odo naa, o ni oun yoo fere lu u pa bo ba di oun lowo. Eyi lawon odo tinu n bi naa ri ti won fi fariga pe awon ko ni i gba, afi ti oba naa ba dahun si gbogbo ibeere awon.


Bi awon odo yii se n gbo oba lenu lo je kinu e ru soke, lo ba kuku bere mole lati ko awon nnkan tawon odo naa ko di ona kuro funra re, sugbon won ko gba fun un lati se bee rara.


Okan ninu won gba owo e danu, eyi lo si fa a to fi fibinu kuro lodo won.


Olayinka salaye pe, "Nnkan to fa ifehonu-han naa ni aisi ina monamona lati ileese 'Benin Electricity Distribution Company'(BEDC) lati bii osu meje seyin, to si je pe tipatipa la fi n nina ni eemaarun-un losu kan. Ti awon osise ina monamona naa yoo ba mu ina wa, oru oganjo topo eeyan ti sun ni won yoo mu un de.


"Ki lo de ti won fi fee maa fi aye ni wa lara. Laarin gbogbo awon ilu to wa nipinle Ekiti, ilu Emure lo n sanwo ina ju, koda, e le loo sewadii oro yii wo. Bee, ti a ba fowo ra ooyi, o ye ko ko ni loju ni, sugbon eyi ko ri bee rara loro ina niluu Emure, bee owo goboi ni won tun n mu wa fun wa lai lo ina ohun." O ni opolopo igba lawon ti sekilo fawon ti won pe ara won losise ileese ina ohun pe ki won dawo a n ja ina kiri niluu naa duro, sugbon won ko da awon lohun.


Gbogbo oro wonyi lo n dun awon odo, sugbon lojo kokanlelogun, osu keji, odun yii, tawon osise ileese amunawa naa tun gbe ise won de lati waa ja ina ni won taku, won lawon o lowo kankan i san afi ti ina ba wa daadaa.


N lawon osise ileese monamona naa ba fariga pe awon o ni i gba, eyi lo mu kawon odo ilu woya ija pelu won ko too di pe won ba ese won soro.


Olayinka tesiwaju pe awon ko tete mo pe awon osise amunawa naa ti lo ogbon alumokoroyi fawon, won ti fogbon yo okan ninu awon fuusi (fuse) to gbe ina wo adugbo ohun, awon kan deede ri i pe awon adugbo to mule ti awon nina, awon ko ni ni. Ibinu ni awon odo yii fi ya lo sofiisi ileese amunawa ohun, ti won si taku pe afi bi won ba fi fuusi ti won yo le awon lowo lai fakoko sofo, sugbon se lawon osise ileese naa gbonri nu, won ni awon ko yo nnkan to jo bee rara.


Iro ti won pa yii lo tubo ta epo si wahala naa, eyi to fa a tawon odo fi gbiyanju lati mu lara awon osise yii, sugbon won sa lo, bee lowo te eni kan. Lesekese lo pe awon yooku re pe ki won da fuusi naa pada, ko si pe sasiko naa tina fi tan.


O ni sadeede lawon ri i pe won ge ina adugbo awon lojo keji latara okun ina adugbo kan to wa nitosi awon, iyen Ise, ko si sina latigba naa. Opolopo ipade ati leta lo lawon ti ko lati wa ojutuu soro naa, sugbon pabo ni gbogbo re naa ja si.


Nnkan keji tawon tun fi pinnu lati fehonu han ni bi ileefowopamo kan soso, First bank, to wa niluu yii se ko lati sise, bee awon olowo ati oloye ilu nikan ni won maa n gba eyinkule da lohun. O ni latigba isele idigunjale to sele niluu Ikere, losu meje seyin lawon ti n lo Ado lati gbowo, awon adigunjale si maa n da awon lona.


"Idi ree tawon odo naa fi fehonu han, sugbon Kabiyesi ko petu si won ninu, o ranse pe awon olopaa lati ko opolopo ninu won timole ni. Ko ju ogoji iseju ti oba fi ibe sile lawon olopaa digboluja de pelu oko bii meeedogun, won yinbon mo okan ninu awon odo naa lese, won ko si naani eyi ti won tun fi wo odo naa pelu ogbe ibon lara e wonu oko.


"Opo okada to wa nitosi ibi ifehonu-han yii lawon olopaa tun gbe wonu oko won lo, eyi si tun bi opo awon eeyan ninu tawon eeyan bii ogota mi-in tun fi sa ara won jo lati tun loo fehonu han laafin Kabiyesi. Ti a ba n ka a, o ti fere to ogota ojo tawon odo to wa lakolo awon olopaa ti wa nibe." Die lara awon osise ileese amunawa BEDC to ba Iwe Iroyin Yoruba soro, sugbon ti won ko lati daruko won salaye pe aisanwo ina lo fa a tawon fi ja ina won.


Iwe Iroyin Yoruba tun ba opo awon obinrin ilu naa soro, ohun ti won si n so ni pe ki Kabiyesi tu awon omo awon sile, bi bee ko, awon yoo gbe igbese to le yo o nipo laipe jojo. Okan lara awon obinrin ilu naa to je asaaju, sugbon to ko lati daruko re fun wa so pe, "Awa obinrin mo nnkan ti a le se topin yoo fi de ba isejoba Oba Adebayo, sugbon awon oko wa ni ko gba wa laaye." Won fi ye akoroyin wa pe oja kan wa tawon maa n na nigba ti oba ba waja nikan, bee lawon ko ni i besubegba lati naja yii ti iye ojo tawon da fun Kabiyesi ba pe.


Gbogbo akitiyan akoroyin wa lati ri Oba Adebayo ba soro lori esun yii lo ja si pabo, bee ni ko gbe ipe re.


Iwe Iroyin Yoruba sabewo saafin re losan-an Ojobo, sugbon awon ijoye re ko foju rere wo wa rara.


Akowe aafin so pe Kabiyesi ko si nile, o si se pataki ka towo bowe mo-fee-ri-o (appointment book). Nigba ti a gba lati se bee, o ni ka fi ateranse sowo si i. Lati ojo naa ni akoroyin Iwe Iroyin Yoruba ti fi ateranse sowo si Kabiyesi, bee ni ko ti i da esi pada titi di akoko ti a n ko iroyin yii jo.


Nigba to n soro lori isele naa, komisanna olopaa nipinle Ekiti, Taiwo Lakanu, so pe oun loun saaju iko awon olopaa digboluja lo si Emure-Ekiti lojo tawon odo naa fehonu han, ati pe nise ni won kolu aafin, ti won si ba opolopo dukia olowo iyebiye je. Koda, won dunkooko mo oba pe awon yoo sun aafin re nina.


Lakanu so pe ibi toro naa de, nise lawon odo naa ni awon yoo jo tesan olopaa Emure kanle, opelope awon yen ti won ji giri si ise won.


Ni bayii, oga olopaa ni owo awon ti te awon janduku to to metalelogbon lori isele yii, tawon si ti n fi oro po won nifun po.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, June 02 @ 07:17:38 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Awon obinrin rinhooho losan-an gangan l'Emure Ekiti, won ni afi ki Kabiyesi" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: