Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Owo te awon to n ta ori eeyan n'Ibadan, oko atiyawo to loyun wa ninu won
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Owo te awon to n ta ori eeyan n'Ibadan, oko atiyawo to loyun wa ninu won

Bo ba se pe lati inu oyun ni omo ti maa n jogun ba ise ti iya e yan laayo ni, bi obinrin oloyun kan n'Ibadan, Adeniran Saki, ba bi oyun inu e, Olorun lo mo iru eeyan ti omo naa iba ya, abi nigba to se pe oun ati oko e ni won jo n de isa oku kiri iboji, ti won si n hu awon oku eda eeyan egbe won ta nitori owo.

Saki, eni odun meeedogbon ati oko e, Mojeed Adeniran, pelu awon akegbe won meta mi-in lowo awon olopaa te n'Ibadan fun bi won se n ra ori eeyan gbigbe, ti won si n tun un ta, eyi to mu ki won maa loo sigun ba awon oku ti won sun jeje tiwon ninu saree ti won si n ge won lori lo feu, egberun meji si merin naira ni won si n ta odidi ori eeyan kan.

Nigba to n safihan awon afurasi eeyan naa lojo Isegun, (Tusde), to koja, oga-agba ileese olopaa ipinle Oyo, CP Mohammed Katsina, so pe awon olopaa otelemuye sewadii awon afurasi odaran naa leyin ti won ta won lolobo pe awon kan maa n gbe awon saree ni ite oku awon Musulumi to wa lagbegbe Liforte, laduugbo Awotan, n'Ibadan, ti won si maa n hu awon oku naa lo.

CP Katsina fidi e mule pe oru lawon obayeje eeyan yii maa n lo sise ibi naa. Bi won se gburoo awon olopaa leyin ti asiri won ti tu ni won sa lo raurau, sugbon kinni kan ti okan ninu won gbagbe sile nibi to ti n sa lo lawon agbofinro lo lati mu gbogbo won. Awon meta yooku ti owo te yato si toko-tiyawo yii ni Tayo Akinrinola, Abati Kolade ati Ramon Korede.

Pelu bi o¯wo¯ ti awon eeyan wonyi yan laayo se je eyi ti ko bofin mu to si tako iseda omoniyan, adape oro ti won n lo fun ori eeyan ni 'Bisikiiti', awon ti won jo mo nipa oja okunkun yii nikan lede ohun si jo ye titi ti Saki fi tu asiri naa fawon oniroyin lolu ileese olopaa to wa ni Eleyele, n'Ibadan.

Obinrin oloyun yii so pe okoowo ewe ati egbo loun n se ni toun ko too di pe okunrin kan ti won n pe ni Aafaa Korede fi ona ise odaran yii han oun.

Gege bo se so, "Ewe ati egbo ni mo n ta, Aafaa Korede ti maa n ra ewe lowo mi, nigba to ya lo ni se mo ni bisikiiti, mo si ni mi o mo nnkan to n je bee. O ni eegun ori eeyan ni won n pe bee, o si ye ki emi naa maa ta a. Mo ni won ko ti i ko emi nise debe yen o, o waa ni se mo le ra a ti oun ba wa a wa fun mi, mo ni ti ko ba ti ni i da wahala si mi lorun.

'Bo se gbe bisikiiti (ori eeyan) kan wa fun mi lojo kan niyen. A tun maa n pe bisikiiti ni 'monu'. Mi o wule beere ibi to ti ri i ti mo fi ra a. Egberun meta naira ni mo ra a lowo e, mo si ge e si wewe, mo n ta okookan ni ogorun-un naira tabi igba naira, o wa lowo bo ba se tobi to. Apapo iye ti mo ta odidi bisikiiti kan je egberun merin naira. Awon onibaara mi ti won maa n ra ewe ati egbo ni mo maa n ta a fun.'' Taiwo Akinrinola so ni tie pe oun wa ninu awon to maa n lo kaakiri iboji oku. O ni bi awon ba ti hu oku jade ninu saree, ori e nikan lawon maa n ge tawon yoo si ta a fawon onisegun to nilo won fun aajo.

Okunrin eni odun metadinlogbon yii so pe Alaaji kan ti oun ko mo oruko e lo to oun sona ise buruku naa, egberun mewaa naira lo seleri lati fun oun ati eni keji oun to ran nise naa lojo to koko ran oun nise, eyi to mu ki oun tara sasa wa ori eeyan fun un loooto nitori owo ohun jo oun loju gidigidi.

Taiwo salaye pe, " Lojo yen, Alaaji ni won mu wa lo si ibi ti won n sin awon oku si, won ni awon yoo fun emi ati eni keji mi ni egberun mewaa naira ta a ba le ba awon wa ori oku. Bi emi ati ekeji mi se lo sibe ni nnkan bii aago mesan-an ale niyen.

''Ori oku ta a ri lojo yen ti fo, sugbon a ko ri eni to ran wa nise yen mo. Iyen lo je ki n loo gbe e ba Aafaa Korede pe ko waa ra a. Egberun meji naira lo ra a, ojo keta lo si too fun wa lowo e.'' Sa, oga-agba awon olopaa ipinle Oyo ti kilo fun awon eeyan ti won feran lati maa huwa odaran tabi sise ti ko bofin mu lati tete jawo nibe nitori ko si ibi ti won le gbe e gba ti owo awon agbofinro ko ni i te won lojo kan.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 18 @ 06:37:18 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Owo te awon to n ta ori eeyan n'Ibadan, oko atiyawo to loyun wa ninu won" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: