Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Asiko ree fun Buruji Kasamu lati de Amerika ki won: Omo egbe PDP gbe Kashamu lo
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

Asiko ree fun Buruji Kasamu lati de Amerika ki won: Omo egbe PDP gbe Kashamu lo sile-ejo l'Ogun, o ni ko niwee-eri

Gbogbo awon ti won gbe enu won ni igbekugbee, ti won n so pe Buruji Kasamu ko ni i fese ara re te Amerika laelae, asiko ree fun Kasamu lati jewo fun won pe ore loun ati Obama, ko si si ohun to sele ti oun ko le de ile ore oun ki i. Okunrin naa ti di okan ninu awon omo ile igbimo asofin bayii, bee ni ki i se ile igbimo asofin kekere ni, ile igbimo asofin agba, o si daju pe bi eeyan ba de ibi ti Olusegun Obasanjo ba wa bayii, ara baba naa yoo maa gbona ti oju re yoo ma pon kankan ni, abi sebi nitori eni ti baba se so pe oun ko le se egbe PDP mo ree, pe oun ko le je ki omo kan ti won n wa l'Amerika koba oun. Omo ti won n wa l'Amerika naa lo ti di Seneto yii o, kin ni baba yoo waa se. Oloun kuku si se e, baba paapaa ti rin siwaju, ohun ti ko sele ri lo sele lojo idibo, gbogbo ibo ti won di lodo Obasanjo, APC lo ni in, Buhari ni baba ba lo. Eeyan ti Baba wole laduugbo baba, Kasamu naa si wole laduugbo tire, ko sija kan mo niyen. Sugbon bo ba se pe Kasamu yoo yanju oro yii, ti gbogbo ohun to n run nile yoo si tan yanga, ti oniyeye gbogbo yoo si tenu yeye bapo, ki okunrin naa yaa tete ra tikeeti bayii bayii, ko sare lo si Amerika paa, bi ko ba ba Obama nile, ko de odo awon asofin egbe re, ko sa kan so poun waa woran bi won ti n sofin won nitori asofin Naijiria tuntun loun. Bo ba ti le se bee, ati Obasanjo o, ati gbogbo awon ti won n bu u o, kaluku yoo sinmi iregbe ni. Buruji Kasamu, Seneto tuntun fun Naijiria, asiko ree lati de Amerika ki won!

Omo egbe PDP gbe Kashamu lo sile-ejo l'Ogun, o ni ko niwee-eri Johnson Akinpelu, Abeokuta Oro ti n beyin yo fun oludije ipo seneto labe egbe oselu PDP ni ekun Ila-Oorun Ogun (Ijebu), Omooba Buruji Kashamu, nigba ti okan ninu awon omo egbe naa to n gbe ni Ago- Iwoye, Mogaji Dele Ajayi, gbe e lo sile-ejo giga ijoba apapo to wa niluu Abeokuta, nibi ti won ti ni ki okunrin naa ko iwe-eri awon ileewe to lo sita.

Latigba ti igbejo naa ti bere la gbo pe Kashamu ti n lo agbara e le okunrin to pe e lejo naa lori, won ni awon olopaa lo loo ko wa lati Zone 2, ti won waa mu okunrin naa, ti won si ti i mole fojo merin ki won too gba beeli e.

Osan ojo Abameta, Satide, ni nnkan bii aago meta osan ni won lawon olopaa bii marun-un ti won dihamora lai wo aso ise, sugbon ti won gbe ibon dani ya wo ile Dele, ti won si mu un.

Nigba to n salaye ohun ti oju e ri, Dele Ajayi so pe iwe ipe lawon olopaa naa so pe awon mu wa lojo Abameta naa pe ki oun yoju si won lojo Aje, Monde, ose to koja, iyen ojo kerindinlogun, osu yii. Sugbon si iyalenu oun, nise lawon to wa naa ko je koun soro ti won fi di oun mu, ti won si ju oun sinu moto won.

O ni bi oun se debe ni okunrin kan to je olopaa waa ba oun to si so pe Buruji Kashamu lo ko leta ehonu sawon pe oun ko fi oun lokan bale. Won ni koun ko nnkan toun ba mo nipa e, oun si salaye pe oro naa ti wa nile-ejo, oun tawon si n beere lowo Kasahmu ni pe ko je kawon ri iwe-eri e pe o lo sileewe ati iwe to gba niluu oyinbo ti won fi da a lare pe ko mo nipa oogun oloro ti won lo gbe to fi sa kuro lohun-un.

Dele Ajayi ni leyin eyi lawon olopaa ju oun satimole, toun si sun oorun ojo meta nibe ko too di pe won gba beeli oun. O ni ki lo buru nibe tawon ba ni ki oludije fiwe-eri e han nita gbangba ati iwe to gba lati ilu oyinbo pe won ti da a lare.

Okunrin naa so pe inu opo awon ni ko dun si Kashamu nitori awon ko le fi eni ti yoo maa dojuti awon nigba toro ba di pe ki won soyinbo se asoju awon nile igbimo asofin. Ajayi waa pariwo pe kawon omo Naijiria gba oun, nitori ojoojumo ni won n lepa emi oun.

Nigba to n soro nipa esun ti Dele Ajayi fi kan Buruji Kashamu, Ogbeni Austin Onyiokor to je akowe iroyin fun Kashamu so pe awon olopaa lo le tan imole si idi ti won fi mu Dele, sugbon ohun toun le so ni pe loooto ni okunrin naa gbe oga oun lo sile-ejo lori esun meji kan, lara e si ni pe ayederu iwe-eri lo ko sile fun ajo INEC lati dije nitori ko niwee-eri.

O ni nitori e ni oga oun se ko leta sawon olopaa ni Zone 2 lati ba oun sewadii lowo Dele boya o ni eri gidi, awon naa si ti lo sile-ejo pada lati so pe ko si ooto ninu ejo to pe.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 18 @ 06:51:16 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Asiko ree fun Buruji Kasamu lati de Amerika ki won: Omo egbe PDP gbe Kashamu lo " | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: