Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Nitori jenereto, toko-tiyawo na iyawo onile daku
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Lati Owo Akoroyin Olootu

Nitori jenereto, toko-tiyawo na iyawo onile daku

Bi ki i baa se opelope awon araadugbo Ilupeju, Asero niluu Abeokuta, die lo ku ki toko- tiyawo kan lu iyawo onile won pa sinu ile. Bo tile je pe won ko pa obinrin naa, sibe won fi aburo iku han an nipa bi won se na an daku, jenereto lo fa wahala laarin won.

Nirole ojo Abameta, Satide, ni nnkan bii aago marun-un ni wahala naa be sile nigba ti oko toruko e n je James ati iyawo e, Rebecca, lu obinrin naa lasiko tiyen so pe ariwo jenereto won n da awon araale laamu.

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe ko ti i pe tawon toko-tiyawo naa de adugbo yii ti won si ko wahala ba awon alajogbe won.

Lara esun ti won koko fi kan won ni pe ni gbogbo igba tawon araadugbo ba n sun lowo, nise lawon toko-tiyawo naa yoo maa lu sekere, ti won yoo maa korin, ti won yoo si maa fi tiwon di awon eeyan lowo.

Bee ni won ni James ati Rebecca ko baluwe ile won sile, ori apata kan ni won ti maa n we.

Won ni bi won ba si bi won leere pe ki lo fa eyi, won yoo so pe awon n we iwe isegun ni.

Sugbon ti ojo Satide to koja yii, won ni iyawo onile naa loo ba won pe ki won din ariwo jenereto won ku nitori pe o n pariwo ju.

Odi ni won ni oro naa ba wo eti Rebecca, bee lo ki iyawo onile won mole, oko e to si de ba a nibi to ti n lu mama ohun da si i, bi won se lu iya oniyaa daku niyen. Loju-ese tisele naa waye ni won ni okan lara awon omo iya naa ti loo pe olopaa ni Adatan, sugbon ki omo naa too de pelu olopaa, won ti ji iya naa, won si ti ko ejo lo sodo Baale ilu. Won ni Baale ilu naa lo ni ki olopaa maa lo, awon yoo yanju e ni itubi-inubi.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe awon agbaagba agbegbe naa da Rebecca lebi iwa to hu yii, won si ni ko sanwo itanran egberun meji aabo naira pelu igo Sinaapu kan, sugbon se ni obinrin naa yari pe ko si nnkan to kan won nibe, awon ko le sanwo kankan.

Titi di akoko yii, inu irora ni won so pe iyawo onile naa wa.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 18 @ 07:03:11 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Nitori jenereto, toko-tiyawo na iyawo onile daku" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: