Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Se won ro pe won yoo wole ni, abi ewo ni ija: Ajimobi, ma ma ba won ja...
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

Se won ro pe won yoo wole ni, abi ewo ni ija: Ajimobi, ma ma ba won ja...

Awon oloselu, won ki i gba, bi won gba won lesee nimu, ti won se won nigbo ti gbogbo agbari won n seje suuru, won yoo si tun maa lewo ese ni, won yoo so pe awon yoo ja titi ti iku yoo fi mu awon lo ni, sakara lasan ni. Ariwo ti awon PDP Ogun n pa ko ye enikan, ati ipade a-a-ni-i-gba tawon ati SDP n se. Ohun to n yaayan lenu ni bi won se ro pe awon yoo se bee yen mu Amosun mole, ti awon yoo si gba ijoba lowo re, nigba ti awon eeyan ti won po n so pe ijoba re te awon lorun. Ohun ti awon eeyan ko mo ni pe nigba ti awon araalu ba wo eyin oloselu kan wo, awon ti won ba ri leyin re nigba mi-in a maa je ki won dibo fun iru eni bee tabi ki won ma dibo fun un. Oro Gbenga Daniel ko ti i tan ni okan opolopo awon eeyan, bee ni won ko ti i ri aburu ti Amosun se ti won yoo fi so pe awon ko fe e mo, bee egbe PDP ko ni awon asaaju mi-in ju awon ti oruko won ko fi bee dara niwaju awon araalu yii lo, nitori bee, yoo soro fun won lati wole. Ohun ti iba tun mu ki Gboyega Isiaka ribi ba wo o ni ti pe omo Yewa loun, omo Yewa ko si ti i se gomina ri, o ye ki awon ara Yewa fi eyi dibo fun un. 

Sugbon omo Yewa meji lo jade, okan lati inu PDP okan lati inu SDP, ile ti mo tan, oro si ti bo sori pata, ibo ti ku ola, nigba tawon omo Yewa mejeeji waa pade, ti Odunsi so pe oun fi aaye sile fun Isiaka ko se gomina, lasiko to n soro naa, ko seni kan to gbo mo, ibo ti ku ola. Ohun ti i maa se awon oloselu yii ko yeeyan, won yoo fete sile won yoo maa pa lapalapa kaakiri, bi awon asaaju SDP ba mo pe awon fe eeyan lati Yewa, sebi o ye ki won ti jo to o lati ile, ko ni i di igba ti ko si kinni kan ti enikan yoo se si i mo ki won too maa so pe awon bere ajose, iru ajose buruku wo niyen. Ki Isiaka jokoo ko ma ba enikan rojo o, o kuku sese di eekeji ni, boya ori eleekerin loun naa n lo bii ti Buhari, o see se ko di gomina Ogun nijo kan.

Ajimobi, ma ma ba won ja...

Ohun to maa n ba awon amoye ninu je ju ninu oro oselu Naijiria yii ni bi awon oloselu se maa n ya alaigboran, ti won yoo si da ara won loju koja bo ti ye, ti won yoo si fi owo ara won ba nnkan won je. Nigba ti eto oselu yii bere, ohun tawon ara Oyo ro ni pe lasiko yii, bi o ba se pe loooto ni awon egbe alatako mura lati gba ijoba lowo Abiola Ajimobi, ko sohun meji ti won yoo se ju ki gbogbo awon jo pade po, ki won si fa eni kan kale laarin ara won lo, paapaa nigba to se pe omo egbe kan naa ni gbogbo won tele. Ninu gbogbo oro naa, awon meji lo si se pataki ju, Alao Akala ati oga re, Rasheed Ladoja, ni. Awon mejeeji ni ko ye koro won le rara, nitori won ti jo ba ara won sise, won si ti jo wa po. Sugbon awon ni oro won waa pada le ju, won ko le jo se po, won si leri titi pe awon yoo jo se, afi igba ti ojo idibo sunmole ti won ni awon ko le jo se. Ladoja ni awon ara Ibadan ati Oke-Ogun fe oun, awon ni won yoo fi ibo gbe oun wole. Alao Akala ni awon ara Ogbomoso ati Ibarapa ko le pada leyin oun laye, won yoo dibo akunfaya foun ni. Bi Akala ti n so pe oun loun yoo wole ni Ladoja n so pe oun ni. Sugbon adura kan soso lawon ti won feran Ajimobi n se fun un, adura naa ni pe enu awon ota re ko ni i ko laye laye, loooto si ni, enu awon mejeeji to lenu ju ko ko, igbeyin oro won si di abamo ni. Awon mejeeji lo wole, Akala wole, o wole l'Ogbomoso, Ladoja naa wole, o wole n'Ibadan, bi a ba si pa ibo ti awon mejeeji ri po, o ju ibo Ajimobi lo. Sugbon nigba ti Olorun ti da won lede ru lati ile nko, to je oselu afemi afemi ni won n se, kaka ki eku ma je sese ko fi se awadanu, kaka ki n fun o kin n kuku fun ile, ki waa ni igbeyin e fun won! Iyen lawon eeyan Ajimobi se n korin kiri ilu pe, “Ajimobi ma ma ba won ja, funra won, funra ara won ni ki won o maa funra won loogun je!”
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 18 @ 07:12:48 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Se won ro pe won yoo wole ni, abi ewo ni ija: Ajimobi, ma ma ba won ja..." | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: