Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nibi Ti Oni Atawon Egbe E Ti Fee Ta Eru Ti Won Ji Lowo Ti Te Won N'Ibadan
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Taofeek Surdiq

Nibi Ti Oni Atawon Egbe E Ti Fee Ta Eru Ti Won Ji Lowo Ti Te Won N'Ibadan

Olawale Ajao, Ibadan Adanu ti iba se obinrin ontaja kan loja Sango, n'Ibadan, ti pada sori awon obayeje eeyan to fee ba a laye je pelu bi awon odomokunrin merin kan ti won ti so ole jija di ise se ja ilekun soobu re wole, ti won si ko gbogbo oja to wa nibe pata, sugbon towo awon olopaa pada te won, ti won si da gbogbo dukia obinrin onisowo naa pada fun un.

Laaaro ojo Aiku (Sannde), ojo ketadinlogbon, osu kesan-an, odun yii, nigba ti onikaluku awon ontaja ti gbe ilekun soobu won ti pa fun ijosin ojo naa tabi isinmi opin ose ni okunrin eni odun merindinlogbon kan, Godbless Oni, ko awon emewa e meta ti won n je Alaka Babatunde (eni odun metalelogun), Jamiu Alabi (eni odun mejidinlogbon) ati Benjamin Segun, eni ti ko ju omo odun mejidinlogun pere lo, ti won si loo ja ilekun awon soobu ti won ti n ta awon ohun eso ara, ni won ba ko gbogbo oja ti won ba nibe lo pata.Ninu awon eru ti won ji ko naa la ti ri orisiirisii aso, bata, aago owo, egba orun atawon ohun eso ara mi-in repete, ti won si ti n seto ati ta won fun awon to maa n ra oja ole, ti won yoo ra a ni pooku-lowo-e, ti won yoo si ta a bi won se n ta bosikoro fawon eeyan loja.

Oni to je balogun awon afurasi ole yii lowo awon olopaa to n gbogun ti idigunjale (SARS) n'Ibadan koko te. Ona ti won gba mu un ko yato sigba ti aja ode ba fi imu fin enu isa okete, to gbo oorun eranko naa, to si de isa kan an titi to fi pa a. Idi ni pe nigba ti okunrin eni odun merindinlogbon yii n ko awon eru naa lo lati ta lawon olopaa da a lona, ti won si ti yara mo pe olubi eda ni, ati pe eru ole lo gbe lowo.

Oga-agba awon olopaa nipinle Oyo, CP Leye Oyebade, fidi e mule fawon oniroyin, n'Ibadan, pe laduugbo Apete lawon agbofinro ti mu meji ninu awon afurasi ole ohun ni nnkan bii aago marun-un irole ojo Sannde kan naa ko too di pe won mu awon meji yooku leyin iwadii.

Orisii aadota bata, awotele obinrin meeedogun, orisii aago owo mejo, egba orun mefa atawon nnkan mi-in ni won ko ninu soobu obinrin naa gege bi oga-agba awon olopaa se fidi e mule fawon oniroyin.

CP Oyebade so siwaju pe leyin ti asiri Olu atawon emewa e ti tu gege bii onise ibi lawon agbofinro lo si ile won lati tubo sewadii nipa won, ti won si ba ero POS meji ninu ile won.

POS yii ni ero alagbeeka tawon onisowo nla maa n lo lati gba owo lowo awon onibaara won ti won ko ba fe maa di owo kiri, to je pe kaadi ti won fi n gba owo lenu ero apowo ni banki ni won yoo lo, to si je pe bi eeyan ba ti ti kaadi ohun bo o ni ero naa yoo yo iye owo oja kuro ninu akaunti e bo sinu akaunti eni to ta a.

Gbogbo eru tawon eni ibi wonyi ji ko lojo naa lawon olopaa gba pada lowo won, ti won si da won pada fun eni to ni won. Opo ibanisoro ti won n pe ni siimu mokanlelogoji pelu irin ti won fi maa n fo ilekun ile onile lawon agbofinro tun ba ninu ile okan ninu won to n je Jamiu.

Oga awon afurasi ole yii, Oni, eni to fidi e mule pe inu oja Sango lawon ti loo ji oja oloja ko tun jewo pe ole toun ja yii ki i se akota okiti fun obo oun, ati pe oun ti jale jale debi toun ti loo se faaji ninu ahamo ogba ewon ri nigba tawon olopaa SARS mu oun fun esun idigunjale nigba kan, ti won si gbe oun lo si kootu.

Ni ibamu pelu ibeere awon oniroyin, oga awon afurasi ole yii so pe, "Oke Parde ni mo maa n ta awon eru ta a ba ji ko si nitori o ti ni enikan to maa n ra iru awon oja bee lowo mi.

Bo tile je pe eyi to n je Jamiu ninu awon afurasi ole to ko si pampe awon agbofinro yii so pe oun ko ba won kopa ninu eyi to di oran si won lorun yii, sibe o fidi e mule pe loooto loun je okan lara won, ati pe o pe tawon ti jo maa n fo ile onile tawon yoo si ko eru eleru ta ni gbanjo.

"Emi o ba won lo sibi eyi ti won loo ja ni Sango yii. Loooto la jo maa n jale tele, mo wa nibe nigba ta a loo ko waya irin ninu ileese kan to ti denu kole niluu Oyo, sugbon mi o ba won lo lojo ti won loo fo soobu ni Sango, Godbless (Oni) lo kan daruko mi fawon olopaa ti won fi waa mu mi."

Gege bi awijare e lori ero igbowo ti won ba ninu ile e, Jamiu so pe oun ko mo bi awon kinni ohun se de inu ile oun, o ni o see se ko je eni to n gbe ibe tele lo ko won pamo soke aja nibe.

Lori awon kaadi siimu ti won tun ba ninu ile e bakan naa, okunrin eni odun mejidinlogbon yii so pe booda oun to n je Mutiu, eni to n sise awako tirela l'Ekoo lo ko awon kaadi naa wa sile oun to ni oun fee se iforukosile fun won ko too di pe oun ko won pada si Eko, sugbon nise lo sa lo nigba to ri awon olopaa lojo ti won waa mu oun nile.

Nigba to n ba awon oniroyin soro, obinrin ti won ja lole, Abileko Bolanle Ogunmuyiwa, gboriyin fun awon olopaa fun ise takuntakun ti won se lati ri awon ole naa mu. Bee lo fi idunnu e han si bi won se da awon eru re pada fun un.

Gege bo se so, "Laaaro ojo keji ti mo de soobu ni mo ri i pe won ti ko gbogbo oja towo e to egberun lona aadojo naira (N150,000) ti mo ni ninu soobu tan pata. Mo dupe lowo Olorun atawon olopaa fun bi won se ba mi mu awon ole yen, ti won si tun da awon oja mi pada fun mi. Bi ko ba se bee ni, nise laye mi iba baje, nitori nise lawon ole yen iba da mi pada si ese aaro, ti ma a kan maa runpa kiri igboro."

Sa, oga-agba olopaa ipinle Oyo ti so pe oun ti setan lati gbe Oni atawon egbe e lo si kootu fun esun ole. O waa kilo fawon ole atawon onise ibi gbogbo lati tete tun ero won pa, ki won si jawo lapon ti ko yo nitori oun ko ni i siju aanu wo enikeni ti won ba ka mo idi ohun to lodi sofin nipinle naa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 15:57:33 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Nibi Ti Oni Atawon Egbe E Ti Fee Ta Eru Ti Won Ji Lowo Ti Te Won N'Ibadan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: