Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun
[ Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun ]

·Gbigba Kadara Gbo - Al-Imaan Bi-l-Qadar (Ayanma Tabi Akosile)
·Umaru Gbe Oogun Wo Kootu, Ladajo Ba Da Igbejo Duro Kia
·Fasasi Ko Iyawo e Sile N'Ibadan, O Ni Ko Ro Amala Fun Baba Oun
·Adajo Ni Ki Won Fi Emmanuel, Ayederu Looya, Sogba Ewon Kirikiri
·Alake To Fee Ko Oko Dero Ewon N'Ilorin
·Yekeen Fee Ko Munira n'Ilorin, O Ni Latigba Tawon Ti Fera Loun Ti n Ru, Tou
·Adajo Ni Kawon Ebi Oko Medinat Da Ogun Oko Re Pada Fun un
·Igbeyawo Ogun Odun Daru L'Osogbo
·Lori Oro Ti Ko To Nnkan, Awon Olopaa Fibon Fa Femi Lorun Ya, Ni Won Ba Sa Lo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nje Oba Ooni Lee Sun Re Bayi Ti Wahala Ti Be Sile Laarin Awon Olomooba Ile-Ife?
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Taofeek Surdiq

Nje Oba Ooni Lee Sun Re Bayi Ti Wahala Ti Be Sile Laarin Awon Olomooba Ile-Ife?

Ni bayii to ku ojo merinlelogbon pere ti won yoo kede eni ti yoo je Ooni tuntun ni ilu Ileefe, o da bii eni pe awon idile to letoo soye naa ko ti i fori ikoko soodunrun, bi awon kan se n sekilo fawon afobaje lati te e jeje, lawon kan fori le ile-ejo pe dandan ni kawon fese ofin to oro naa.

Latojo kejidinlogbon, osu keje, odun yii, ti Oba Okunade Sijuwade ti waja lorisiirisii igbese ti bere lori eni ti yoo je Ooni tuntun, niwon igba to si je pe ko seni ti ipo ola ko wu, atawon to letoo si i atawon ti ko letoo si i ni won ti bere si i lo kaakiri lati fa oju awon afobaje mora.

Koda, iwadii fihan pe bawon kan se n ru owo kaakiri, lawon kan n se oniruuru ise idagbasoke sagboole won lati fi jewo pe omo ile oba tooto lawon je.Oro naa bere si i mu ifura dani nigba ti Oloye Bode George fesun kan awon oloselu kan pe won fee koju bo oro yiyan eni ti yoo je Ooni tuntun, ko si pe sigba naa ti aare orile-ede yii tele, Oloye Olusegun Obasanjo, wa siluu Ileefe, nibi to ti parowa fun won pe eni to ba kunju osunwon ni ki won fi je Ooni tuntun.

Bayii lawon odo kan niluu Ileefe bere si i fi ojoojumo fon iwe kaakiri ilu pe oro ipo Ooni ki i se eyi ti enikeni gbodo maa fi dunaa-dura rara, ati pe Ile-Ife yoo mu enikeni to ba gbabode laarin awon ti won n wo lati yan Ooni tuntun.

Lojo Aje, Monde, to koja lo lohun-un, lawon afobaje merindinlogun niluu Ileefe kede fun gbogbo aye pe gege bii akosile to wa nile latodun 1980, idile Giesi lo ku ti yoo fa Ooni tuntun kale.

Gege bi atejade ti mefa ninu awon afobaje naa fowo-si se salaye, abala kokandinlogun ninu akosile naa fi han gbangba pe idile Giesi ni oye naa kan, won si ro awon idile meteeta to ku, iyen Osinola, Ogboru ati Lafogido lati loo senpe, ki won duro de asiko tiwon.

Won fi kun oro won pe ojo mejilelogoji pere ni gbogbo igbese naa yoo gba tawon yoo fi kede eni ti yoo je Ooni tuntun.

Awon afobaje ti won fowo-si iwe naa ni: Oba Folorunso Omisakin to je Obalufe ti Iremo< Oba Joseph Ijaduola to je Lowa Adimula ti Ife; Oba Yaya Elugbaju to je Obajio ti Moore Oba Adekola Adeyeye to je Jaran ti Ife Oba Sakariya Olawusi toun je Obaloran ti Ilode pelu Oba J.A. Awe ti i se Arode ti Ife.

Oro yii ko jo pe o lo deede lara awon idile Lafogido, idi niyi ti won fi fori le ile-ejo pe arumoje ni akosile 1980 ti awon afobaje fee fi se ategun fun yiyan Ooni tuntun, ati pe o kun fun eru ati iyanje lopolopo.

Gege bi won se gbadura niwaju ile-ejo, laarin idile gbooro mejeeji to letoo si Ooni niluu Ileefe, iyen ile Lafogido ati idile Lajodogun. Akosile fihan gbangba pe won ti fowo ro ile Lafogido seyin lopolopo igba, ati pe lati idile Lajodogun ni won ti yo ile Geisi, Ogboru ati Osinkola, nigba ti ile Lafogido si da duro ni tie.

Iwe ipejo naa tun se e lalaye pe ile Ogboru labe Lajodogun ni Oba Okunade to waja ti wa, ko si ni i bojumu ki enikeni tun so pe ile Giesi labe Lajodogun kan naa loye yii tun kan, tori pe laarin odun 1894 si 2015, akosile fihan pe ogun odun pere, iyen laarin odun 1910 si 1930 ni ile Lafogido je Ooni, to si je pe ile Lajodogun lawon Ooni yooku ti n wa.

Ninu iwe ipejo nomba HOS/16/2015 ti Sooko Bunmi Adegoke pe loruko idile Lafogido ni won ti ro ile-ejo lati pase fawon olujejo, iyen Gomina Aregbesola atawon afobaje lati ma se gbe igbese kankan titi tile-ejo yoo fi gbe idajo kale lori oro naa.

Ninu idajo ile-ejo giga tilu Osogbo ohun, Adajo Adeyinka Aderibigbe, ti pase pe ki awon olujejo kora ro lori igbese won ohun titi di ojo ketalelogun, osu ti a wa yii, toun yoo sedajo ejo naa.

Bakan naa ni idile Ogboru fori le ile-ejo pe awon ko faramo ile Giesi tawon afobaje so pe ki won fa eni ti yoo je Ooni sile nitori pe ile Ogboru gan-an ni ipo naa to si lasiko yii.

Sugbon egbe kan to pe ara re ni 'Ife Cradle Youths' ti bu enu ate lu igbese awon idile Lafogido ati Ogboru pelu bi won se lo sile-ejo lati ka awon afobaje lapa ko lori yiyan Ooni tuntun.

Ninu atejade ti adari egbe naa, Kunle Elusayo, fowo-si lo ti salaye pe o je ohun itiju fun idile kankan lati fowo pa ida awon afobaje loju lori ipinnu won lati tele ilana to wa nile, paapaa ti ko si eni to soro lasiko ti anfaani iru e yi kan irufe idile naa.

Elusayo ni awon idile mejeeji ti won lo si kootu gbodo tun ero won pa kiakia nitori pe itan ni ohunkohun ti won ba se lonii yoo da lojo iwaju fawon iran to n bo, ati pe ko si arumoje kankan ninu ilana odun 1980 tawon afobaje fee tele.

Lowolowo bayii, lara awon ti won n du oye naa lati idile Lafogido ni: Omowe Charles Adedokun Adesanmi, agboole Okiti, niluu Ileefe.

Omooba Adesanmi ni oun ti pinnu, oun si ti setan lati lo opolopo iriri ati imo toun ti ni kaakiri agbaye fun idagbasoke ati itesiwaju ilu Ileefe. O ni oun yoo bere nibi ti Oba Okunade Sijuwade fi adagba ise naa ro si, ti alaafia yoo si tubo maa joba niluu Ileefe ti i se orirun Yoruba.

Lati idile Giesi la ti ri Omooba Adesoji Fadehan to je oludari ileese redio tipinle Osun lowolowo. Fadehan ni oun mo tifun-tedo ilu Ileefe atawon eeyan inu e, ati pe oun yoo lo iriri oun lati fi mu ilosiwaju ti ko legbe ba awon eeyan ilu naa.

Bakan naa ni komisanna foro asa tele nipinle Osun, Onarebu Sikiru Ayedun, ti fi erongba re han lati je Ooni latinu idile Giesi. Adetona ni oun mo daju pe oro ipo Ooni kuro ni kereemi, sugbon oun ti setan lati ru eru naa.

O fi kun oro re pe ko si oju tawon afobaje fee fi wo eni ti won yoo mu ti oun ko ni i ni awon amuye ti won fe, ati pe gbogbo ipa oun loun ti maa n lo lateyinwa lati wa ire ilu Ileefe ni gbogbo aaye ti oun ba wa.

Ayedun ni oun ni awon amuye to ye fun ipo naa nitori pe oun ko figba kankan kuro nile, afi akoko toun wa imo kun imo lo. O ni ko seni ti ko mo iran oun niluu Ileefe, pelu ileri pe tawon afobaje ba mu oun, itesiwaju olokan-o-jokan ni yoo tun maa ba ilu Ileefe atawon omo bibi ibe nile ati leyin odi.

Ju gbogbo re lo, otito ponbele ni pe atari ajanaku ni ipo Ooni ilu Ileefe, ki i se eru omode. Enikeni to ba setan lati gbe eru naa gbodo je eni to nifon leekanna, to si kaju e nipa tara ati nipa temi.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 16:23:25 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Nje Oba Ooni Lee Sun Re Bayi Ti Wahala Ti Be Sile Laarin Awon Olomooba Ile-Ife?" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: