Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
[ Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise ]

·Ni Ti Ooni, Alaafin Ati Aare Ona Kakanfo
·Sugbon Ta La Ri Ba Wi, Bi Ko Je Baba To Fi Omo Re Foko L'oru
·Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo
·Leyin Odun Mokanla, Bose Fee Ko Oko Re Sile l'Abeokuta: Nitori Orekunrin Re
·Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
·Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
·Iyaale Ile To Fi Kokeeni Soyun Ti n Ka Boroboro
·Lati Ekiti Ni Wasiu Atawon Ore Re Ti Waa Fi Owo Ayederu Raja n'Ilorin
·Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Sugbon Iro Gidi Niyen O: Enu Won Wo Wowo
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Oluseye Iyiade

Sugbon Iro Gidi Niyen O: Enu Won Wo Wowo

Enu awon oloselu dun, ko si si ohun ti won ko le se lati ba ara awon je, ati lati ba tara won paapaa je. Won yoo puro, won yoo soro didun, won yoo si maa fi gbogbo awon nnkan wonyi tan araalu je ni. El-Rufai yii naa tun ni o, gomina Kaduna.

Ariwo to pa nijerin ni pe inu oun dun si kinni kan, nje kin ni? O ni owo ti Buhari na ti won fi sayeye ayajo odun ominira to koja yii je milionu lona aadorin pere, iyen seminti milionu.

Sugbon El-Rufai fi kun un pe nigba aye Jonathan, oun ko fi milionu sise re, bilionu ni i fi i sayeye, o ni apapo bilionu to si lo je ogojo bilionu, nitori awon kan n nawo lo ni. Eleyii ki i se bee, oro awon oloselu lasan ni. Ohun ti i ba dara ni ki Rufai ko awon eri ati iwe owo ti won na naa kale, nidii eyi leeyan yoo ti mo pe ododo ni okunrin oloselu to koriira Jonathan naa n so.Sugbon ko le ri bee, El-Rufai ko si le so pe oun ri iwe kan nibi kan, gbogbo iru awon oro bayii si je lati ko okan awon araalu soke, ati lati tubo je ki won koriira Jonathan si i. Eleyii ki i se pe Jonathan atawon eeyan re ko kowo je o, sugbon ko le je ona yii ni won gba kowo naa je, bee ni ko si le je bo se ri niyen.

Idi ni pe ninu awon odun marun-un ti El-Rufai so pe Jonathan fi n sodun ominira yii, ko si odun kan ti won fi raaye sayeye ominira, awon Boko Haram ko je, nitori bee ni won se maa n pariwo pe awon ko sayeye odun kankan, to si je ninu Aso Rock nibe ni won maa n jokoo se iwonba ayeye ti won ba fee se, ko si si ayeye kankan ti won se nigba naa ti won na to aadota milionu lati fi se e, nitori won ko raaye sayeye ohun tabi nawo to to bee rara.

Bi won ba ji owo ko, o see se ko je ona mi-in ni won fi kowo yii o, ki i se ona ti El-Rufai n so yii. Bi ko ba waa je bee, ko si igbagbo ninu ohun ti okunrin gomina yii so, iro ni! Ewo la waa n puro funra wa fun, asiko oselu ti koja, asiko ise ilu lo kan bayii, kawon oloselu ile yii je kawa mekunnu sinmi.
Enu won wo wowo

Bi oro aye ti ri le ri yii, bi oro awon oloselu si ti ri niyen. Eni ba deju sile yoo ri imu, bi eeyan ba si mo iran i wo daadaa, yoo ri ohun tawon oloselu Naijiria n se funra won. Lati ose to koja bayii, lenu won ti wo wowo. Awon wo. Awon oloselu ati alariwo ti won n pariwo pe Babatunde Fasola kowo je l'Ekoo, o ji owo ko, o na owo ni inakunaa, o si ye ko foju ba odo awon ti won n mu awon to ba kowo je. O ye bee loooto, bi Fasola ba kowo je, bo ba fi obe eyin je awon araalu nisu, o ye ki won mu oun naa ni, ko le je eko fun gbogbo awon oloselu to ku, ki Naijiria le ni ilosiwaju ni.

Sugbon ohun to maa n dun ni lokan ni pe awon oloselu ki i se nnkan tiwon bee, ki i se pe won n se oore, won n fee ba tara won je ni. Latigba ti ariwo ti n lo niluu pe Aare Buhari fee fi Fasola se minisita, ti awon oga re ko si fe ohun to jo bee, latigba naa ni asiri orisiirisii ti bere si i tu jade, ti gbogbo iwe si n fon kaakiri pe Fasola se igba, Fasola se awo. Bi oro ti ri bee, kia lawon ti won jo n sore, awon ti won jo se gomina tele, awon oba ilu ti won maa n paara odo re, kia ni won ti yaa sare yera fun un, won si se bii eni pe won ko mo on ri, won rin jinna si i. Bo ba se pe ko si ori re leyin re ni, bi won yoo se ba tire je niyi, bi aye yoo se pada leyin re niyi, ti awon ti won ba a je ti won ba a mu yoo si sare pada leyin re, ti won yoo so o di eni ti ko je nnkan kan mo. Bi aye se buru to le ri yen o.

Sugbon nigba ti Buhari ko gbo tawon elegan ati awon ti won fee ti i si koto, to fi i se minisita bayii, kia ni nnkan ti yipada. Tabi ta lo tun gbo o ninu iwe tabi nibi kan pe Fasola kowo je, awon ti won sa fun un tele yoo ti maa wa ona bayii lati tun pada waa ba a, nitori won mo pe agbara ti wa lowo re.

Koda, ijoba Eko to bere si i tu asiri orisiirisii paapaa jade tele ti se medo, won ti gbe jee, enikan ko si ni i gbo kinni kan lenu won mo. Bi oro oselu se ri niyen, eni ti agbara ba wa lowo e laye n ba se. Bee ni bi won ba n soro eeyan kan daadaa, ti won n sare girigiri leyin re, ki i se pe won feran re o, ohun ti won n je nibe ni won n tori e sare kiri. Loooto loooto, owo epo laraye n ba ni la o, bi owo ba di owo eje tan, araye a sa lo bamubamu ni!

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 16:41:39 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Sugbon Iro Gidi Niyen O: Enu Won Wo Wowo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: