Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Wooli Fe Gbemi Omo Re Omo Odun Meje To Nka L'Akure, Lo Ba Ni Dandan Bi Ki W
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Stephen Ajagbe, Ilorin

Wooli Fe Gbemi Omo Re Omo Odun Meje To Nka L'Akure, Lo Ba Ni Dandan Bi Ki Won Foun Lori Ewure

Oro omodebinrin omo odun meje kan, Marvelous, to ka laduugbo Oluwole, lagbegbe Olu Foam, niluu Akure, ti fee di wahala nla sawon araadugbo ohun lorun bayii pelu bi won se ni baba e, Wolii Oluwafemi Ayodele, n leri pe afi dandan koun gbemi e leyin to ti ka pe oun loun wa nidii gbogbo idaamu ti wolii naa n dojuko.

Gege bi ohun ta a fidi e mule nipa isele ohun, Baba Marvelous to je oludasile ijo kan niluu Akure ni won lo loo gbadura lodo wolii kan niluu ohun lori oro aye e to dojuru bii ese telo.Nigba ti alagba ohun debe ti wolii gbadura fun un tan, ohun to so ni pe ko loo ko gbogbo awon omo to bi wa. Loju-ese ni won so pe alagba naa sare pada sile lati ko awon omo re lo sodo wolii, leyin ti wolii bere adura ni Marvelous si bere si i ka.

Ninu oro omodebinrin ohun lo ti jewo pe oun loun wa nidii gbogbo wahala ti baba oun to je wolii n dojuko. Won lo soro debii pe ki wolii ohun ma wule sise mo nitori ko si bo ti le se e to le ni akojo.

Inu eeru lo so pe oun bo gbogbo aseyori wolii ohun mo, o si ni ko sohun ti baba ohun le se to tun fi le ri i gba pada mo.

Omodebinrin ohun jewo pe oun ko ti i paayan pupo, emi eni kan soso lo ti i towo oun bo, inu ijamba oko lo ni oun gbemi okunrin to ko ti ko daruko re ohun si, bee lo ni oun tun ti n gbiyanju lati gbemi araadugbo mi-in toruko re n je Michael Faloye.

O so ninu oro e pe oko okunrin ohun loun atawon egbe oun maa n gbe lo sipade, afi bi won ba ra odidi agbo nla kan, ki won si gbe ori e foun lokunrin ohun too le jajabo.

Nigba ti Michael funra re n soro lori isele yii, o fidi e mule pe nise ni moto oun maa n yonu ni gbogbo igba.

Ka too kuro nibi isele ohun leni to je baba omodebinrin naa ti n leri leka pe se loun maa pa a, eyi to mu kawon kan gba awon araadugbo naa nimoran lati tete loo fi to ajo Sifu Difensi leti ko too di pe baba yii gbe igbese to le ko gbogbo won si wahala.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 16:51:08 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Wooli Fe Gbemi Omo Re Omo Odun Meje To Nka L'Akure, Lo Ba Ni Dandan Bi Ki W" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: