Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
[ Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu ]

·Deji Binu Si Titi Afesona Re, Lo Ba Dana Sun Eeyan Mesan Mole L'Ondo
·Victoria Fi Obe Gun Oko Re Pa; Ladajo Ba Ni Ki Won Loo Yegi Fun Un
·Awon Olopaa Fee Mu Baba Atiya Ti Won Lu Omo Won Pa L'Akure
·O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
·Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
·Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
·Nibi Ti Sunkanmi Ti N Gbeja Iya Re Lo Ti Gun Ojo Nigo Pa l'Ondo
·Tope To Pa Lanloodu e L'Ondo Ti Wa Lewon
·N'Igbokoda, Tegbon-taburo Ri Ore Meji Mole Laaye Nitori Ti Won Ji Iya Won L

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nnkan De! Oro Awon Minisita Buhari Ti Da Wahala Sile Ninu APC
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Olowale Adejare

Nnkan De! Oro Awon Minisita Buhari Ti Da Wahala Sile Ninu APC

Ni gbara ti oruko awon ti Aare Muhammadu Buhari fee fi se minisita re ti jade lawon ti won mo nipa oselu ti mo pe wahala loro naa ba de, sugbon awon asaaju egbe naa gbogbo n pa kinni ohun mora, won ko fee so o sita. Inu awon kan dun pe ibi ti oro ohun yoo yori si ree, sugbon inu awon kan baje patapata.

Oro naa ko le se ko ma ri bee, nitori ninu gbogbo awon ti Buhari mu, ko senikan to lenu ninu awon asaaju APC, Buhari lo yan won funra re, awon to fe lo pe mora, ko si fi tawon olori egbe naa se. Ninu gbogbo awon gomina APC paapaa, Gomina Ibikunle Amosun nikan ni Buhari je ko fa eeyan kale, ko faaye gba gomina mi-in mo rara, eyi si fa ibinu ati ikunsinu repete. Eyi to tile waa mu wahala ati ede-aiyede to si le pada waa bi Ige ko bi Adubi lowo bayii ni pe gbogbo awon ti Buhari yan yii, paapaa awon to yan lati ile Yoruba, awon tawon olori egbe APC lagbegbe naa ko faramo rara ni.Awon eeyan ti ro pe adehun ti Buhari se, ko ni i le mu un se mo, nitori funra e lo ti kede pe ninu osu kesan-an loun yoo too yan awon minisita oun, ki enikeni ma si se reti won ko too di igba naa. Nigba ti osu kesan-an tun n lo si idaji ti olori Naijiria naa lo si Ghana, ohun tawon oniroyin koko bi i ni pe se ko ni i yan awon minisita naa ni, osu kesan-an to so lo maa n pari lo yii. N lo ba da won lohun pe osu kesan-an ko ti i pari, kawon oniroyin duro digba ti osu kesan-an ba pari ti won ko ba daruko minisita oun, igba naa ni ki won too maa bu oun. N ni gbogbo eeyan ba n reti loooto, won n reti ojo ti osu kesan-an yoo dopin, ki won le ki Buhari mole, ki won so pe ko mu adehun se.

Die lo si ku ki oro naa ri bee, nitori titi di aago meta l'Ojoru, iyen lojo ti osu kesan-an yii pari, awon asofin ko ti i ri iwe toruko awon minisita yii wa gba lowo Buhari atawon eeyan re. Aago meta ni ile igbimo asofin pari ise lojo naa, nigba tawon asofin si n lo, ohun ti won so ni pe Aare ko ti i fi oruko awon minisita re ranse.
Sugbon Abubakar Bukola Saraki ti i se olori ile igbimo asofin agba ko kuro lofiisi re, bo tile je pe awon asofin to ku ti lo. Nitori pe oun pe yii ni ko je ki oro naa bo sori, nitori nigba to di aago marun-un aabo nirole pata, ti opo osise ti lo, asoju lati odo Buhari mu leta gbooro naa wa, nibi toruko awon eeyan gbogbo to fee fi se minisita wa, oruko awon mokanlelogun lo si koko fi ranse, o so pe awon oruko to ku yoo tele e laipe jojo, ki won koko maa ba ise lo lori iyen.

Bo tile je pe Saraki so pe oun ko ni i ja leta tawon oruko yii wa ninu e titi di aaro yii, ojo Isegun, Tusde, ojo kefa, osu kewaa, tawon asofin to ku yoo ti peju, ti awon yoo si jo jokoo lati ka leta naa, awon oniroyin ti wadii ifin-inkooko, won si ti mo ohun to wa nibe, ati oruko awon minisita wa tuntun. Olori olu ileese Aare, Chief of Staff, Abba Kyari, ati Ita Enag ti i se oludamoran Aare lori oro ile igbimo lo gbe iwe ohun wa, ti Saraki si gba a lowo won.

Lara awon oruko to wa ninu iwe naa ni ti Audu Ogbeh lati ipinle Benue; Ogbonaya Onu lati Abia; Rotimi Amaechi lati Rivers; Babatunde Fasola lati Eko; Kayode Fayemi lati Ekiti; Rahman Dambazzau lati Kano; Abubakar Malami lati Kebbi; Kemi Adeosun (Ogun), Aisha Alhasan lati Taraba; Amina Muhammed lati Ademola Adejare Gombe; Hadi Sirika lati Katsina; Chris Ngige lati Anambra; Adebayo Shittu lati Oyo Solomon Dalong lati Plateau, Ibe Kachikwu lati Delta; Osagie Ehaniere lati Edo, Udoma Udo-Udoma lati Akwa Ibom, Ahmed Isa Ibeto lati Niger, Sulaiman Adamu lati Jigawa ati Ibrahim Jubril lati Kaduna.

Awon oruko mi-in si n bo o, sugbon awon to ti jade ree, bi oruko naa si ti wo eti awon eeyan ni ariwo so kaakiri ilu, oro naa ba gbogbo awon oloselu lojiji, o si da omi tutu si okan awon asaaju APC ju lo. Iwe Irohin Yoruba gbo pe ki oro tile too da bee, won ni bi Buhari ti ko oruko naa siwee tan lo fi okan ranse si Alagba egbe APC, Odigie Oyegun ati Asaaju Apapo fun egbe won, Asiwaju Bola Tinubu.

Sugbon nigba tawon mejeeji ja iwe naa ti won si ri oruko to wa nibe, to si je pe won mo pe oruko naa ti de odo awon asofin, o ti de gbangba, oro naa jo won lara koja afenuso. Ohun to sele ni pe Tinubu ti ba Buhari soro, nigba to si n lo, o mu Akande dani, o si ti tun fun un loruko awon eeyan to n fe lati ile Yoruba, paapaa ni Eko toun funra re wa. Sugbon ko si oruko Babatunde Fasola nibe, bee ni ko si ti Kayode Fayemi. Yemi Cardoso to ti ba Tinubu sise nigba to n se gomina loun faramo fun minisita lati Eko, oruko re lo si fi ranse, bakan naa ni won gbimo lati fa Femi Falana kale lati Ekiti, tabi pe ki awon agba egbe nibe mu elomiran jade fun won. Gbogbo oruko ti won waa ko lo, ko si eyi to te Buhari lorun nibe, ko si mu won.

Eyi to jo awon eeyan naa lara ju ni ohun to sele nipinle Oyo, nibi ti Buhari ko ti ba enikeni won soro to fi fa Adebayo Shittu kale, to ni eni toun fee fi se minisita niyen. Adebayo Shittu yii ki i se eni tawon APC ipinle Oyo fe rara, ija to si wa laarin oun ati Gomina Abiola Ajimobi lori eni to ye ko je gomina Oyo ninu awon mejeeji ko ti i tan nile paapaa, gomina yii si ti lero pe bi won ba da a sile ti won tun un sa, oun loun yoo fa eni ti yoo se minisita lati ipinle naa kale.

Sugbon Buhari ko ro gbogbo eleyii ni tire, ohun to ranti ni pe leyin oun ni Shittu ti wa lati ojo yii wa, nitori lodun 2007, abe re lo ti du ipo gomina, lodun 2011 abe re naa lo ti mura lati du ipo naa lodun yii ko too di pe won darapo mo egbe APC, toun ati Ajimobi si du asia egbe naa, ko too ja sowo Ajimobi. Nitori aforiti to ti ni lati ojo yii leyin Buhari yii ni aare se fa a kale lati waa se minisita re, eleyii ko si dun mo awon APC ninu rara. Koda, bi a ti n wi yii, egbe naa ni ipinle Oyo ti jade si gbangba, won si ti kowe pe awon ko fe ko je Shittu ni Buhari yoo mu lati odo awon, nitori ki i se enikan to ba egbe se, ko si feran Ajimobi.

Egbe naa ti ni ki won ja ipo minisita gba kuro lowo re, ki won si gbe e fun elomiran to je ojulowo omo egbe won. Sugbon ko jo pe Buhari yo da awon wonyi lohun, nitori ileese aare paapaa ti so pe awon ti won n binu lori iru oro yii kan n fese hale lasan ni, afi eni ti ko ba fe oriire fun Naijiria ni yoo so pe ori ti Buhari ko jo yii ko tun dara to. Pelu iru oro bayii, o ti di isoro fun Tinubu ati awon eeyan re lati jade pe inu awon ko dun si kinni ohun, bee loooto ni inu won ko dun si i.

Ohun ti won si se n binu ni pe bii igba bi won gba gbogbo agbara lowo Tinubu, ti won waa gbe e fawon omoleyin re ni. Bi Fasola ba di minisita, ti Fayemi naa di minisita, nigba ti won ti mo pe oga awon ko fe kawon debe, won ko ni i foribale fun un. Oruko ipele keji ti Buhari yoo fi ranse lawon eeyan tun n duro de, sugbon awon Tinubu ti mo pe eyi to ja ju ninu oruko naa lo koko gbe jade yii, nitori yoo soro fun un lati mu eeyan meji l'Ekoo ati l'Ekiti pelu Oyo pe ki won waa se minisita, eni kookan naa ni yoo mu lati ipinle kookan.

Iwe Irohin Yoruba tile gbo pe Bisi Akande ti i se alaga egbe yii tele ti ba Buhari soro lori oro yii pe ki lo tun de ti ko fi tawon se, ki lo de ti ko lo oruko tawon fun un, sugbon Buhari fesi pe ohun to le fese egbe mule loun se, nipa riri i pe awon ti won jiya fegbe awon janfaani egbe awon. Won ni okunrin naa so pe Fasola lo seto ikowojo oun, Fayemi lo seto akoso, Amaechi si wa lara awon ti won ri i pe eto gbogbo kese jari, bawo ni oun yoo se waa fi awon yii sile, ti oun yoo mu Cardoso ti oun ko mo, ati Falana ti ko nise kan to se fawon.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 17:14:10 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Nnkan De! Oro Awon Minisita Buhari Ti Da Wahala Sile Ninu APC" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: