Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


O Sele L'Egba! Seun Bimo Kan Fokunrin Meji L'Abeokuta
 
 
Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
Lati Owo Olootu Irohin Yoruba

O Sele L'Egba! Seun Bimo Kan Fokunrin Meji L'Abeokuta

Opo awon to fee lo sibi isomoloruko kan to waye lojo Aje, Monde, ose to koja, laduugbo kan ti won n pe ni Ita-Balogun, Ago-Oko, niluu Abeokuta, ni won dogbon feyin rin pada nigba ti wahala deede bere lori omo tuntun ti won fee fun loruko lojo naa.

Ohun to fa wahala to mu ki gbogbo aga ati atibababa ti won gba lojo naa bere si i di nnkan tawon kan baje ko seyin bi won se ni okunrin meji ni iya omo naa bimo fun, tawon oko iyawo naa si n ja pe awon lawon lomo.

Seun Ojo ni won pe oruko obinrin ti won ni ko mo eni to le gbomo fun ninu awon mejeeji to n ja ohun.Ojo kejo ti Seun bimo obinrin ti won si fee se isomoloruko omo naa lawon kan de ti won so pe omo awon lawon waa gba lowo iya re, nise lawon to wa nibe si ya enu pe iru ki leyi.

Ere lawon eeyan koko pe e, won si n ba awon to wa naa dapara pe omo wa ninu ile, ki won loo gbe e, n lawon eeyan naa ba wole loooto. Bi won se ri Seun to bimo ni okunrin kan to n je Simon ninu won so pe ki lo de ti obinrin naa se fee gbe omo Oba f'Osun, o ni ko gbe omo tuntun naa le oun lowo koun maa gbe e lo nitori omo oun ni, nibe si ni oro ti di isu-ata yanan-yan-an.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe Hammed Ogunseye ati Simon ni Seun n fe po leekan soso, bee lo si je pe awon mejeeji naa lo n ba a lajosepo toko-taya, sugbon awon okunrin naa ko mo pe awon pe meji lowo re, ogbon ni Seun n da soro ara e ti ko si je ki won mo ko too di pe oyun de.

Won ni omobinrin tojo ori e ko ti i le ju ogun odun lo yii ko tete mo pe oyun ti wa lara oun, eyi lo si fa a ti ko se mo eni to loyun ninu awon mejeeji, nitori gbogbo igba lawon yen n ba a lo po gidi.

Pelu bi won se ni ko mo eni to le gboyun naa fun ninu awon mejeeji, awon mejeeji naa lo pada so fun pe oun loyun, to si n gbowo eru omo lowo won. Awon ebi Hammed ni tiwon so pe awon lomo naa jo, won ni iya to bi Hammed to ti doloogbe ni nnkan bii odun meta seyin lomo ohun jo.

Sugbon ohun tawon ebi Simon n so ni tiwon ni pe lati nnkan bii osu mejo aabo ni Seun ti wa pelu awon, tawon ti n toju e pelu oyun ninu. Won lawon tun n toju iya Seun naa pelu, bawon se n fun won lowo lawon n fun won laso.

Ogbeni Waheed Ogunseye to ku fun Hammed ni baba so ninu oro e pe ni nnkan bii osu mejo seyin ni Hammed mu Seun wa pe oun ti fun un loyun, atigba naa lawon si ti n fi nnkan ranse si i lati fi toju ara e atoyun inu e.

Baba naa so pe, ''Nigba ti oro yen sele ti Hammed so pe oun ti fun obinrin kan loyun, a ni ko mu un wale, omo mi ko si so fun mi pe oun atenikan n ja si oyun naa. Sadeede la ri awon kan ti won de lojo ikomo pe awon lawon lomo. Eko ni Hammed n gbe, eekookan lo n yoju sile lati waa wo iyawo e, Seun si maa n wa sodo mi daadaa ti mo n toju e titi to fi bimo.

''Ko seni to yoju nigba to bimo tan, afi bo se di oni tawon kan de pelu wahala, ti won n so pe awon fee gbe omo awon. Ere ni mo koko pe e, sugbon nigba to ya ni won bere si i na gbogbo awa ti a wa ninu ile, ti won n pariwo.

''Awa la ra eru omo, awa la gba omo ati ikeji e pelu iya omo funra e losibitu, ko seni to yoju nigba yen. Isomoloruko ni Hammed waa se lati Eko to n gbe, ko si mu iyawo ati omo e lo to ba n lo, afi bi wahala se sele o.

''Iya mi to ku ni omo yen jo ti e ba ri foto omo ati iya mi yen. Nigba to ya ni won so pe ki i se pe awon fee gba omo naa, awon fee fi tabuku iya e ni. Sugbon to ba je pe mo ti mo tele pe awon meji ni won ni oyun naa ni, ma a ti so fun omo wa pe ko je ki Seun gbe oyun lo foloyun, ko ma fi da wahala sile nitori iru nnkan bayii ko sele ri ninu ebi wa.''

Ohun to je kayeefi ninu oro naa ni bi won se so pe iya to bi Seun ti n gba owo lowo Simon atawon ebi e tipe, sugbon ti iya naa so pe oun ko gbowo lowo won. Bee ni iya naa tun so pe eelo ni gbogbo owo won ati ounje ti won fun oun.

Oun ta a tun ri gbo ni pe okan lara awon egbon Seun bebe fun aforiji lori asise ti aburo e se pelu oro omo to bi naa, won lo be awon ebi Simon to waa ja, o si fun won ni egberun merin naira lati fi mu oti ki oro naa si tan ninu won.

Sugbon oro tun beyin yo nirole ojo keji isomoloruko, iyen ojo Isegun, Tusde, lori bi won se so pe Seun pe Simon lori aago pe oun ko so pe oun ko ni i gbe omo e fun un, sugbon owo ti ko si lowo e lo je koun gbe omo lo felomi-in lati se isomoloruko omo.

Kin ni Simon gbo oro naa fun ni, nise lo so fun egbon e, ni won ba tun gbera lati loo doju ija ko won nile Hammed pe kawon tete loo gba omo naa ko too pe ju. Nigba ti oro tun pada dariwo nibe ni won loo foro naa to awon olopaa to wa ni Oke-Itoku leti.

Won ni tesan olopaa ni Seun ti jewo pe Simon lo ni omo loooto, sugbon Hammed loun fee gbe omo fun.

Ninu oro Simon lo ti ni nigba toyun ti wa losu kan si meji ni Seun ti wa lodo oun to n sun, to n ji, toun si n se eto fun un gege bii baba omo tuntun to n bo lona.

O ni iya Seun maa n waa wo awon, toun si n fun un lowo atounje to ba ti wa. O tun so pe gbogbo igba ti iya naa ba waa ki awon lo maa n sadura pe awon a pe funra awon, iyalenu lo si je foun nigba ti iya naa so pe oun ko mo oun ri.

Gbogbo igbiyanju wa lati ba iya yii soro lo ja si pabo nitori nise lo n yo boro mo akoroyin wa lowo, ti ko si fee fesi si ohun ti a bi i, ohun to n tenumo ni pe oun ko gba owo lowo eni kankan.

Ohun ti a tun ri di mu ninu oro iya Seun nigba to n soro ni pe oun ko ti i fa omo oun feni kan ninu Simon ati Hammed, sugbon Hammed lo wa lokan oun lati fa Seun fun. O ni awon ti n se ipalemo bawon se maa se eto mo-mi-n-mo-o laarin won.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 17:16:36 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara:
Asiri Nla Alaaji Amosa So Itan Igbesi Aye Re, O ni: Anjonnu Ni Mo Fe Niyawo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara

"O Sele L'Egba! Seun Bimo Kan Fokunrin Meji L'Abeokuta" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: