Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Olootu Irohin Yoruba

Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori N'Ibadan, Nitori Ija Oun Ati Akintola Ni

Won ti pari ipade Egbe Olope, Action Group, (AG) niluu Jos, Ladoke Akintola ati Ayo Rosiji pelu awon minisita merin ti won si kuro nipade naa ko pada sibe, bo tile je pe awon agbaagba egbe won parowa fun un lati lo, ki won jo ri Obafemi Awolowo, ki won le yanju ede-aiyede nla to be sile ninu egbe won. Awon eeyan Akintola ni ko je ko lo sipade ohun, won ni anfaani to wa ninu ko ma lo sibe po fun un ju ko lo lo.

Won tile ni ko si anfaani kan fun un bo ba lo sibe, yoo kan tun pada si oko aaro re ni. Oun naa si gbo, ko yaa lo mo. Pelu bi ko se lo nni, awon omo re ko je ki nnkan sinmi niluu Ibadan ati ile Yoruba lapapo, won n rin kaakiri, ipade n lo lorisiirisii, ohun ti won si n wa naa ni bi won yoo ti se fi ese ominira ti Akintola gba lowo Awolowo yii rinle, ti SLA yoo gba agbara kun agbara, ti won ko si ni i so pe Olorun lo mu un.

Awon omo-eyin Awolowo paapaa ko mu nnkan rogbo nibi ipade won ni Jos. Won ti fibinu yo Ayo Rosiji kuro nipo akowe agba egbe ohun, won si ti fi Sam Ikoku si i. Bee ni won ti fun Bola Ige ni oye kan pataki ninu egbe AG, oun ni alukoro pataki bayii, Publicity Secretary' lapapo, gbogbo oro to ba si jade ninu iwe iroyin, tabi to ba jade lori redio, to ba ti je oro egbe won, ki e ti mo pe lati enu Bola Ige lo ti jade.Adeola Odeku ni won fi se igbakeji akowe egbe AG nipade yii, awon omoleyin Awolowo naa ni won yan an sibe, won si yan Anthony Enahoro ati Alaaji Ibrahim Imam si ipo igbakeji aare egbe fun guusu ati ariwa. Sugbon ko senikan to ba S O Gbadamosi du ipo Akapo egbe Olope, gbogbo eeyan lo fohun sokan pe oun naa ni yoo maa se akapo egbe AG naa lo. Awon ohun ti won se ti ipade naa fi pari niyen.
Sugbon inu n bi awon omoleyin Awolowo yii pe Akintola ati Rosiji ribi sa lo mo awon lowo, awon ohun ti won ti seto fun won bii abuku ati ifinisesin, o dun won pe won ko ribi se e rara, nitori koto ti won gbe sile de ajanaku loro naa da, erin moju, erin ko ba ibe loo mumi.

Awon naa wa n leri bo n'Ibadan, won ni nigba ti awon ba pada de ile Yoruba, nibi ti Akintola ti n sejoba, nibi ti ijokoo egbe AG si wa, awon yoo tun oro naa pin, gbogbo ohun ti Akintola ati awon ti won n tele e si sa fun yii, gbogbo re naa ni won yoo gba pada ni ekunrere. Ileri ti awon n gbe lo s'Ibadan niyen. Sugbon awon eeyan Akintola naa ti gbile s'Ibadan, won ti rin kaakiri, won ti sepade titi, won ti seto, opo si ti gba pe ko si yiyipada kan ninu ohun to ti sele, Akintola naa ni yoo maa se olori awon lo, gbogbo ohun to ba gba lawon yoo fun un.

Nidii eyi, eto ti awon naa ti se kale ni lati dena de Awolowo ati awon eeyan re, ki awon si fihan won pe won ti jabo, ija to wa nile yii, apa won ko le ka a. Awon naa ti sepade tiwon, bi awon ti Awolowo si ti n mura ija bo, bee ni awon ti Akintola ati Rosiji pelu awon minisita to wa leyin won ti seto ohun tawon naa yoo se. Sugbon gbogbo eni to ba mo nipa oselu, yoo ti mo pe oro naa ti dorikodo, nitori ona meji ti awon omo egbe AG pin si yii, okan ju okan lo.

Akoko ni pe awon ti won wa leyin Akintola yato si awon ti won wa leyin Awolowo, bee omo egbe kan naa ni won jo n se. Ni odo Akintola ni awon alagbara wa, awon minisita, awon asaaju egbe, awon olowo inu egbe, awon ti ase ijoba si wa lowo won. Eleyii fun awon yii lagbara gidi, nitori owo ijoba wa lowo won, agbara ijoba naa si n be lowo won bakan naa.

Awon yii ni won ni olopaa lowo, awon naa ni won ni awon moto dende dende, awon yii gan-an ni won si n pe ni ijoba. Eeyan ko si le je ijoba bayii ko ma ni awon ero tire leyin, nitori awon kan naa ni yoo saa wa ti won yoo maa jeun lati inu ijoba. Awon olori ijoba yii, ati awon ti won n jeun ninu ijoba yii, awon ni won wa leyin Akintola, ka si so tooto funra wa, odo won ni agbara nla pin si. Agaga, Akintola funra re ti ri eni feyinti ninu ijoba apapo, nitori Rosiji si wa ninu ijoba naa, minisita loun, o si tun wa nile igbimo asofin. Ore ni Rosiji ati Tafawa Balewa ti i se olori ijoba Naijiria, gbogbo bi Balewa si ti n so pe oun ko feran ohun ti Akintola n se fun oga re, ati iwa to n hu to le fo egbe won, to si le di alaafia ilu lowo, bee ni Rosiji n so fun un pe ko ma so bee, ko mo idi oro ni, to ba mo idi oro naa daadaa, ko ni i so bee rara.

Rosiji lo n salaye fun Balewa pe Awolowo ki i seeyan daadaa, bee naa bi won ti n wo o si, enikan to je alaseju, to si lagidi bii si;si� atijo ni. Rosiji lo ti so fun Balewa pe Awolowo n fiya je Akintola ni, ko si je ko sejoba re bo ti ye ko se e, sugbon bi Akintola ba le se bayii ja ara re gba kuro lowo Awolowo, ijoba Western Region yoo dara gan-an, awon eeyan ibe yoo si gbadun daadaa. Bi Rosiji ti n salaye oro yii fun Balewa naa lo n salaye fawon asofin atawon minisita, nitori o lenu nibe, won si ti mo on latojo to ti pe, lati bii odun 1952 lo ti n soju egbe Action Group lodo ijoba apapo ati nile asofin won, eyi si ti je koun naa je gbajumo asofin ati minisita, ko seni ti ko mo on, ko si si alagbara ti oun naa ko mo. Bi oro ti ri yii lo ka Balewa lowo ko, nitori bo tile je pe o feran Awolowo, ko sohun to le se pelu alaye ti Rosiji se fun un.

Bi Rosiji ti n se tire laarin awon asofin ati Balewa, bee ni Akintola funra re mu Ahmadu Bello ti i se Sardauna ni Sokoto lorun mole, oun naa ko si je ko sinmi. Sardauna kuku ti n wa ona ti oun yoo fi mu Awolowo tele, eyi to si ri yii, to roye pe igbakeji Awolowo atawon ti won wa nijoba ti pada leyin re, o mo pe oun yoo ri ohun toun n fe. Eyi lo si se fa a to fi fokan akin bale, o si ti so fun un pe bi oro ba di girigiri sa, Awolowo ko ni olopaa to le ko sita, ijoba apapo lo ni olopaa, awon lo si ni ase lori won. Nitori bee, ki Akintola fokan ara re bale, bo ti se fee ja ara re gba leyin Awolowo ni ko se, sugbon ki i se ara re nikan ni ko ja gba, ko ja egbe oselu AG naa gba, ki egbe ohun si wa ni ikapa oun atawon ti won fe tire, eyi ni gbogbo ohun tawon ba fe yoo fi see se. Ohun ti Sardauna n fe ni tire ni ki Akintola saa gba egbe AG lowo Awolowo.

Eyi ni agbara se n kolu agbara, nitori Awolowo ni tire gba pe bi itakun ko ba ja, owo ko ni i te okere, bi awon alase egbe AG tawon sese dibo yan ni Jos, atawon mekunnu to n dibo fawon ko ba ti pada leyin awon, ibo lawon yoo fi yo Akintola danu, awon yoo yo o bii eni to yo jiga kuro ninu egbe, awon yoo si le e nipo to wa to n gun un garagara nni, ko si ni i je nnkan kan nidii oselu ile Yoruba mo, yoo kan da bii agbelehe lasan ni. Titi di asiko naa ti nnkan n le yii, tawon omoleyin re ti ra okun nla yi i ka yii, ti won si n fee fi okun naa mu un, Awolowo ko ti i gba pe nnkan kan n sele ti apa oun ko ka, ko si ri Akintola ati Rosiji bii enikan to le so pe nibo loun yoo gba nidii oro oselu, oun n wo o pe itakun to tobi to ope ko to erin i da duro, se oun ko tete mo pe bi ere ba ba edun nile, yoo di obo. Ibinu eyi loun naa n gbe bo n'Ibadan lati Jos.

Sugbon nigba ti Awolowo bo sile ni papa-oko-ofurufu kekere to wa n'Ibadan nigba naa, ohun toun naa ri ya a lenu. Se teletele, gege bii olori egbe Olope, egbe to wa nijoba West, egbe to si je olori alatako nile asofin agba, bi Awolowo ba lo sibi kan to ba n bo bee, ni papa-oko-ofurufu ni awon ero yoo ti ro waa pade re. Ki i se awon ero lasan o, awon olori ijoba, awon oba, awon ijoye, awon alase patapata, koda titi dori Ladoke Akintola ti i se Peremia fun Western Region. Ohun to si fa eyi naa ko ju pe Awolowo ni olori egbe won lo, egbe naa lo si wa nijoba, gbogbo eeyan lo si mo pe ase wa lowo re, agbara lati se ohun gbogbo. Bi won ti n se ni gbogbo igba ti Awolowo je olori ijoba niyi, iyen latodun 1952, bee naa ni won si n se latigba ti Akintola ti gbajoba re latodun 1959, dandan ni ki gbogbo awon alagbara egbe ati ijoba waa pade Awolowo bo ba de s'Ibadan.

Sugbon ti ojo yii ko ri bee rara. Bi Awolowo ti sokale lo ri i ti gbogbo ibe da paro. Awon ero to waa pade re ko to nnkan rara. Eni to je bo ba ti n bo sile bee ni awon onilu yoo ti so ilu won soke, ti won yoo si maa jo pade re, eleyii ko ri bee lojo naa, loooto lawon ero die wa nibe, sugbon won ko to bi won ti maa n to. Bo ba si de bee naa lati ibi kan, gbogbo oba Yoruba ni yoo fere pe sibe tan, afi Ooni nikan, nitori ipo re gege bii asaaju oba ati pe oun ni gomina agba fun Western Region. Bi ijoba kan ko ba fi le wa nigba naa, yoo ran awon ijoye re pelu opa-ase, eyi ni yoo fihan pe oba naa fee wa o, nnkan pataki kan lo di i lowo. Bo ba si ti n sokale bee, Akintola, olori ijoba, ni yoo koko ki, ti yoo ki awon minisita re, awon oba ni yoo si gba� lowo, ti yoo ki won daadaa tele awon eeyan ijoba, ibe ni won yoo si ti ko reirei tele e dele re.

Ohun to waa sele lojo yii lo fihan pe ija inu egbe Olope ti koja ohun tawon eeyan ro o si, o ti feju ju bee lo, ojo naa gan-an ni Awolowo paapaa si mo pe ohun toun n foju ko-to-nnkan wo tele ti di oran nla, bi oun yoo ti waa se e ti kinni naa ko ni i gbe oun lo lo ku, nitori o han soun paapaa pe awon ota ati alatako oun po ju bi oun ti n ro o lo. Ko si oba to waa duro de Awolowo lojo naa o, afi Oba Remo, iyen Akarigbo, Oba Moses Sowemimo Awolesi, ati Odemo Isara ti won ti jo n sore bo lojo to pe, Oba Samuel Akinsanya. Gbogbo oba to ku ni won ko wa, ko si si ohun to se won ju pe won beru ijoba lo, won beru Akintola, won mo pe Awolowo ko lagbara lati yo awon tabi lati ma se fun awon lowo, sugbon Akintola lagbara lati yo awon nipo oba bi inu re ko ba dun sawon, o si le ma fun awon lowo osu awon.

Nibi yii lo ti ko han pe agbara ju agbara lo. Oba C.D Akran atawon oba to ku ti won jo n sejoba ti salaye fawon oba ti ko si nijoba rara pe bi oro ba ri bo ti ri yii, oba ti ko ba sora re, yoo fori ko ohun aburu, ati pe eyin ijoba ni oba gbodo wa bi oro oselu ba fee dija, nitori ise ijoba ati ise ilu lawon oba yii naa n se. Won kilo fun won paapaa pe bi ijoba ba binu, iyen ni pe bi Akintola ba binu, ko si oba ti ko le yo nipo, oba to ba si ti gba opa-ase kuro lowo re to ni ki won le e niluu, iru oba naa ko ni i pada sori ite mo niyen o. Se gbogbo awon oba naa lo si ranti ohun ti ijoba Awolowo funra re se fun Alaafin Adeyemi Keji, ti won yo oba naa kuro nipo re, ti won si le e niluu Oyo, to se pe leyin odi ni oba naa pada waa ku si. Awon oba to ku waa ronu pe bi iru ohun to sele laye Awolowo naa ba le sele sodidi Alaafin, ko soba kan toloselu ko le fiya je.

Bi awon oba se se yii naa ni awon minisita se. Ko si minisita eyo kan bayii to waa pade Awolowo, boya minisita kekere tabi minisita to dagba, onikaluku jokoo sofiisi re ni. Se beeyan ba je minisita, olori ijoba lo n ba sise, olori ijoba lo yan an sipo to wa, ko si gbodo se ohunkohun to yato si ohun ti olori ijoba to gbe e sipo naa ba fe. Eleyii lo fa a to je nigba tawon minisita gbogbo pata ti mo pe Akintola n ba Awolowo ja, ti awon ti won je minisita to wa leyin re si ti fun un nimoran pe ko sohun meji ti awon yoo se fun Awolowo ju ki awon je ko mo pe awon ti pada leyin re lo, awon ti won feran Awolowo ko le jiyan, won ko le se ohun to yato si eyi tawon egbe won ti won je omoleyin Akintola se, awon naa saa mo pe ti awon ba ti se bee, awon pari ise minisita niyen, afi ki awon maa lo sile.

Eyi lo je kawon minisita sa lo, won ko yoju lati pade Awolowo, won yera fun un. Sugbon awon asaaju egbe Omo Oduduwa ko fi i sile, won waa pade re. Lara awon ti won wa ni Dokita Akinola Maja ti i se alaga egbe ohun, Dokita Akanni Doherty, Oloye Rotimi Williams, Oloye Timothy Odutola, Oloye Kosoko ati Toye Coker. Iba awon eeyan gidi ti won saaju awon to ku wa ree, gbogbo awon ti won lenu nijoba ti won si je eeyan taraalu mo, atawon oba ti won maa n waa se eye bayii fun Awolowo bo ba ti irin-ajo de, gbogbo won se bii eni pe awon ko gbo pe o n bo lona, won yaa sa fun un. Ko seni to fe ki ipo ola bo lowo oun. Bi oro oselu se ri ree, awon ti won wa nibe ki i fe ki ipo o bo, ohunkohun ti yoo ba si fa a ti ipo naa yoo fi bo lowo won ni won yoo jinna si, ko si sohun ti won ko le se lati duro sipo won.

Awolowo gbera atawon eeyan ti won waa pade re yii naa, won n ba a lo sile. Bi won ti n lo geere, tawon moto yii tele ara won, bee ni won de ikorita Mokola. Ko seni to mo eni to ko awon ero sibe, ko seni to mo bi awon ero se to lati igun kan si igun keji, awon ero saa po lo ni. Bi moto Awolowo se yo loookan ni won bere ariwo ta a wi yii, "Awolowo, oleee. Ooolee! Ooolee! Bee ni awon mi-in n se, "Heeeee, heee, heee, sio, sio, hooobiii! Awon alariwo mi-in ko si ba won da si eyi, ohun ti awon n pariwo ni, "SLA on top! SLA on Top! Sugbon awon ti won n pariwo Awolowo oole lo po ju, nitori bi moto naa ti n lo lariwo naa n po si i, "Awolowo ooole! Awolowo ooole! Ojo buruku gbaa ni.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 17:40:29 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 5
Awon Ibo Ni Oniyi: 1


E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: