Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
 
 
Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
Lati Ori Minbari Yoruba

TITUBA KURO NIBI ẸSẸ (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)

Awọn erongba khutuba
- Sisẹri pada lọ ọdọ Ọdọ Ọlọhun
- Rire awọn eniyan lori bi wọn yoo se se atunse aarin wọn ati Ọlọhun
- Jijinna si ijakan ninu ikẹ Ọlọhun
Akoko Khutuba mejeeji: Isẹju marundinlogoji

Khutuba Alakọkọ

الحمد لله القائل في كتابه المبين : "وتوبوا إلى الله جميعا أيها المؤمنون لعلكم تفلحون" (النور 31) أحمده إذ فتح لعباده باب التوبة . ودعاهم إليها , ووعدهم أن يتقبلها منهم ويمحو بها سيئاتهم . واشهد أن لا إله إلا الله وحده لا شريك له ولا نعبد إلا إيّاه . وأشهد أن محمدا عبده ورسوله صلّ الله عليه وأصحابه وبعد

Ọpẹ ni fun Ọlọhun to sọ ninu tira Rẹ pe: "Nitorinaa, ẹ ronupiwada lọ si ọdọ Ọlọhun, gbogbo nyin patapata, ẹyin onigbagbọ ododo ki ẹ le baa la. (Suratul Nuru 31). Mo jẹri pe ko si ẹniti isin ododo yẹ, ayafi Ọlọhun nikan ti ko ni orogun, bẹẹni mo si jẹri pe Annọbi wa Muhammadu ẹrusin Ọlọhun ni Ojisẹ Rẹ si ni, ki Ọlọhun bawa kẹ Annọbi, awọn ara ile rẹ, awọn sahabe rẹ ati gbogbo ẹlẹsin isilaamu titi ọjọ ikẹyin.Ẹyin musulumi ẹ lọọmọ pe isẹ ọmọniyan laye yii ni ki o jọsin fun Ọlọhun, sebi tori ijosin naa ni Ọlọhun fi daa ti o ba se rere o see fun ẹmi ara rẹ ni, bi o ba si se aida, oun naa ni yoo da iya rẹ jẹ, se ẹluluu to pe ojo ni ori rẹ ni yoo da le, "Ẹni da eeru ni eeru tọ o. Ẹsẹ Ko ni ipalara Kankan ti yoo ko ba Ọlọhun, bẹni rere ẹda ko le se Ọlọhun ni anfani kankan.

Eeri ni ẹsẹ gẹgẹ bi Ojisẹ Ọlọhun ti sọ: sugbọn kii se idọti ti a le fi oju ri, tabi ti a le gboorun rẹ, sugbọn oripa ẹsẹ yoo maa han lọkan, bẹni yoo maa boo titi ti ọkan yoo fi dudu, wo suratu Mutọffifina: 14 Ojisẹ Ọlọhun sọ pe: Bi eniyan ba da ẹsẹ, ẹsẹ naa yoo di oripa dudu sinu ọkan rẹ, bi o ba tuba, wọn yoo ba si kuro lọkan rẹ, sugbọn ti o ba lekun lẹsẹ, oripa dudu naa yoo fẹ sii�.

Ọgọrọ eniyan lo ntọju asọ sugbọn to fi ọkan rẹ si pẹlu eeri ẹsẹ toti dudu ọkan naa, lalai ranti tuuba kuro nibi ẹsẹ, lotitọ gbogbo eniyan ni ẹlẹsẹ sugbọn kii se gbogbo wọn ni wọn nranti tọrọ aforijin ẹsẹ lọdọ Ọlọhun bẹni Ọlọhun si nrọwa pe ki a tuba, Oun yoo forijinwa . Wo suratu Sumar : 53.

Ninu awọn orukọ Ọlọrun Ni gafuuru (oba to nfi ori ẹsẹ jinni) ati A-ttawabu (oba to ngba tituuba ẹda). Wo suratul Kosọsi, 16 ati suratu Tahrimu; 8 ati Suratu AI-imran: 135. Ojisẹ Ọlọrun sọ pe: dajudaju Ọlọrun maa ntẹ ọwọ rẹ silẹ lọsan ki ẹniti o sẹ ẹ loru le tuuba, ko ni ye bẹẹ se titi ti oorun yoo fi yọ, ni ibuwọ rẹe Ọlọrun yoo fori ẹsẹ jin ẹniti o nigbagbọ si orukọ rẹ tin njẹ Al-gafuur, bẹni yoo si gba tutuba rẹ, pẹlu majẹmu fifi ara gbolẹ, titọrọ idarijin ẹsẹ lọdọ Rẹ lalaini jakan muna nibi ikẹ rẹ.

O jẹ dandan fun eniyan lati tete tuba lọ si Ọlọrun kuro nibi gbogbo ẹsẹ atipe lilọọ lara jẹ apẹrẹ ori buruku ati iyẹpẹrẹ wo suratu Nuru; 31 ati suratu Tahrimi :8 ati awọn aya miran to n tọkasi wipe dandan ni titara tuba nibi gbogbo ẹsẹ.

"وَتُوبُوا إِلَى اللَّهِ جَمِيعًا أَيُّهَا الْمُؤْمِنُونَ لَعَلَّكُمْ تُفْلِحُونَ".

Abu Urọera sọ pe mo gbọ lẹnu Ojisẹ Ọlọrun to nsọ pe: "Mofi Ọlọrun bura pe dajudaju emi maa ntọrọ aforiji lọdọ Ọlọrun mo si maa ntuba lọ sọdọ rẹ nigba to le ni aadọrin lojumo - buhari
Aliagaru ọmọ Yasaru sọ pe, Ojisẹ Ọlọrun (S.A.W) sọ pe ẹyin eniyan ẹ maa tuba lọ si ọdọ Ọlọrun, ẹ si maa tọrọ aforijin Rẹ, toripe dajudaju emi paapaa maa ntuba ọgọrun lojumọ. Musilimu
Awọn onimimo sọ pe: "bi eniyan ba tuba kuro ninu awọn ẹsẹ kan, tituba rẹ yoo jẹ itẹwọgba, sugbọn ẹsẹ yoku yoo wa ni ọrun rẹ titi ti yoo fi tuba".

Tituba Ni: sisẹri kuro nibi ẹsẹ lọ si bi titẹle asẹ Ọlọhun lalaini pada sibi ẹsẹ naa mọ. Majẹmu mẹta lo si mbẹ fun un:
1. Jijawọ kuro nibi ẹsẹ, koda ki o ti gbe ẹsẹ wọ bi asọ
2. Kikabamọ lori dida ẹsẹ naa
3. Ki o si pinnu pe oun ko ni debi ẹsẹ mo lailai
4. Dida ẹtọ pada fun ẹniti o nii.
Ki tituuba nibi ẹsẹ le pe Olutuba nibi ẹsẹ gbọdọ fi Ara rẹ silẹ fun ijiya to ba yẹ. Ọpọlọpọ Olutuuba ni yoo lero pe oun ti tuba kuro nibi ẹsẹ, sugbọn ti ko jawọ nibi ẹsẹ naa, pelu bẹẹ naa yoo maa rankan ikẹ ati aanu Ọlọhun, ti ko si ni bẹru iya Ọlọhun, iru awọn ẹda wọnyi ni wọn ti fẹmi balẹ si ete Ọlọhun, Ọlọhun sọ pe: "Njẹ nwọn le fi ayabalẹ si ete Ọlọhun bi? Nitorinaa, ẹnikan ko ni fi ayabalẹ si ete Ọlọhun ayafi awọn Olofo. Suratul Arọf: 99.

"وَتُوبُوا إِلَى اللَّهِ جَمِيعًا أَيُّهَا الْمُؤْمِنُونَ لَعَلَّكُمْ تُفْلِحُونَ".

Afa ibnu Kesiri sọ pe: Ete Ọlọhun ni iya, agbara ati ifi ọwọ iya gbanimun sikun ni asiko ti eniyan ti gbagbara.

Afa wa Asani sọ pe: "Mumuni yoo maa sisẹ, yoo maa tẹle asẹ Ọlọhun pẹlu bẹẹ naa ẹmi rẹ ko ni balẹ.

Ọmọ Afa wa Arrobiu bun At'am sọ fun baba rẹ pe: kinni o sẹlẹ ti gbogbo eniyan maa nsun, sugbọn ti irẹ baba mi ki sun? O si da lohun pe: Irẹ ọmọ mi baba rẹ nbẹru ki iya Ọlọhun ma ba lojiji ni. O nfi eleyi ranti ọrọ Ọlọhun kan to wa ninu suratul Arofu: 97.

"أَفَأَمِنَ أَهْلُ الْقُرَى أَنْ يَأْتِيَهُمْ بَأْسُنَا بَيَاتاً وَهُمْ نَائِمُونَ".

Lẹhin ti awọn majẹmu ti o ti siwaju yii ba ti pe tan, o se pataki ki Olutuuba se aluwala ki o yan nọfila raka meji, ni ibamu si ọrọ ojisẹ Ọlọhun (SAW) to sọ pe: ko si ẹniti yoo da ẹsẹ kan, ti yoo wa se aluwala, ti yoo si yan nọfila lehin rẹ ti yoo tọrọ aforijin ẹsẹ lọdọ Ọlọhun ayafi kọlọhun fori ẹsẹ naa jin-in Imam Ahmad lo gbaa wa. Ninu Sọhihu Musilimu, Ojisẹ Ọlọhun tun sọ pe: ko si ẹniti yoo se aluwala ninu yin, ti yoo si se aluwala naa daada, lẹhinna ti yoo sọ pe mo jẹri pe ko si ẹlomiran ti ijọsin ododo tọ si ayafi Ọlọhun nikan sọsọ, kosi orogun fun-Un, mo si jẹri pe anọbi wa Mohammad ẹrusin Ọlọhun ni Ojisẹ Rẹ si ni, ayafi ki wọn silẹkun alujanna mẹjọọjọ fun-un, ki o gba ibi to ba wuu wọle"

Ọlọhun yoo tẹwọ gba tituba ẹru Rẹ lopin igbati orun o baa ti yọ ni ibuwọ rẹ, Ọlọhun sọ pe: Nwọn ko reti nkankan ju pe ki awọn malaika wa ba wọn tabi ki apakan awọn ami Oluwa rẹ wa ba wọn, ọjọ ti apakan ami Oluwa rẹ ba wa, ki yoo se anfaani fun ẹmi kan ti ko ti gbagbọ siwaju tabi ti ko sisẹ rere kun igbagbọ rẹ, Ọlọhun sọ wipe: Ẹ maa reti awa na yoo maa reti Suratul Aniam 158. Awọn ami yi yoo maa foju han, bi o ba ku die ki alukiyamo to. Ojisẹ Ọlọhun sọ pe: Alukiyamọ ko ni to, titi ti oorun yoo fi yọ lati ibuwọ rẹ, bi awọn eniyan ba ti ri eyi, gbogbo ẹniti nbẹ lori ilẹ ni yoo gbagbọ, igba yii ni asiko ti igbagbọ ko nii wulo mọ fun ẹniti ko ti gbagbọ tẹlẹ. Buhari lo gbaa wa. Ninu adiisi miran: Ojisẹ Ọlọhun tun sọ pe: Dajudaju Ọlọhun yoo maa tẹ ọwọ Rẹ silẹ loru, ki ẹniti o da ẹsẹ lọsan le tuuba, bẹni o si maa ntẹ ọwọ Rẹ silẹ lọsan , ki ẹlẹsẹ oru le tuuba (yoo maa se bẹẹ) titi ti oorun yoo fi yọ ni ibowọ rẹ.

Bakannaa ni tituba ko ni jẹ itẹwọgba bi ẹmi ba ti debi gogongo, Ọlọhun sọ pe "ko si igba ironupiwada fun awọn ti nwọn se aburu titi ti iku fi de ba ọkọọkan wọn ti o wa wipe: Dajudaju emi ronupiwada nisinyi, bẹẹni ko si fun awọn ẹniti o ku sinu keferi sise. Awọn wọnyi, Awa ti pese iya oloro silẹ fun wọn". Suratu-Nisai: 18. Ojisẹ Ọlọhun sọ pe: Dajudaju Ọlọhun yoo gba ironupiwada ẹru bi ẹmi re ko ba ti de gogongo.

"وَلَيْسَتِ التَّوْبَةُ لِلَّذِينَ يَعْمَلُونَ السَّيِّئَاتِ حَتَّى إِذَا حَضَرَ أَحَدَهُمُ الْمَوْتُ قَالَ إِنِّي تُبْتُ الآنَ وَلاَ الَّذِينَ يَمُوتُونَ وَهُمْ كُفَّارٌ أُوْلَائِكَ أَعْتَدْنَا لَهُمْ عَذَاباً أَلِيما".

Ẹ jẹki a ronu piwada lọsi ọdọ Ọlọhun toripe tituba maa n fa orire ainipẹkun ati isẹmi toni itumọ ba ẹda laye ati lọrun.

Isẹ rere gbọdọ Ko nkan mẹta sinu:
1. Ki o se wẹku pẹlu ohun ti Ojisẹ Ọlọhun muwa, toripe Ọlọhun sọ pe: Atipe ohunkohun ti Ojisẹ naa ba fun nyin, ẹ gbaa, ohunkohun ti o ba kọ fun nyin, ki ẹ kọ ọ; suratul Hashri: 7.

"وَمَآ آتَاكُمُ الرَّسُولُ فَخُذُوهُ وَمَا نَهَاكُمْ عَنْهُ فَانتَهُواْ وَاتَّقُواْ اللَّهَ إِنَّ اللَّهَ شَدِيدُ الْعِقَابِ".

2. Ki o se afọmọ isẹ naa fọlọhun, Ọlọhun sọ pe: A ko pa wọn lasẹ ju pe ki wọn jọsin fun Ọlọhun lọ, ki nwọn fọ ẹsin mo fun-Un , Suratul Bayyinah: 5.

"وَمَآ أُمِرُواْ إِلاَّ لِيَعْبُدُواْ اللَّهَ مُخْلِصِينَ لَهُ الدِّينَ حُنَفَآءَ".

3. Ki isẹ naa wa lori ipilẹ adiọkan (igbagbọ) ti o lalaafia. Wo suratul Bayyinat.

Lataari ironupiwada, ifọkanbalẹ ati imọna yi maa jẹ ti ẹda, boya eniyan jẹ ẹlẹbọ to si tuuba ifokanbalẹ yoo jẹ tirẹ bẹni imọna. Wo suratul Anam: 82.

{الَّذِينَ آمَنُوا وَلَمْ يَلْبِسُوا إِيمَانَهُمْ بِظُلْمٍ أُولَئِكَ لَهُمُ الْأَمْنُ وَهُمْ مُهْتَدُونَ}
Bẹẹni Ọlọhun yoo sọ isẹ buburu rẹ di rere yoo si pa ẹsẹ aburu rẹ rẹ, Ọlọhun sọ pe: "Ayafi ẹniti o ba ronupiwada ti o si gbagbọ ni ododo, ti o si se isẹ rere; awọn wọnyi ni Ọlọhun yoo sọ isẹ buburu wọn di isẹ rere. Ọlọhun jẹ alaforiji, alaanu'' suratul Furkoni:70.

{إِلَّا مَنْ تَابَ وَآمَنَ وَعَمِلَ عَمَلاً صَالِحاً فَأُولَئِكَ يُبَدِّلُ اللَّهُ سَيِّئَاتِهِمْ حَسَنَاتٍ}
Ninu rẹ naa ni pe yoo jere iyọnu Ọlọhun, yoo si la kuro nibi iya ina. Wo suratul Al'imraan:135 -136.

"وَالَّذِينَ إِذَا فَعَلُوا فَاحِشَةً أَوْ ظَلَمُوا أَنْفُسَهُمْ ذَكَرُوا اللَّهَ فَاسْتَغْفَرُوا لِذُنُوبِهِمْ وَمَنْ يَغْفِرُ الذُّنُوبَ إِلا اللَّهُ وَلَمْ يُصِرُّوا عَلَى مَا فَعَلُوا وَهُمْ يَعْلَمُونَ(135) أُولَئِكَ جَزَاؤُهُمْ مَغْفِرَةٌ مِنْ رَبِّهِمْ وَجَنَّاتٌ تَجْرِي مِنْ تَحْتِهَا الأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا وَنِعْمَ أَجْرُ الْعَامِلِين".

Ninu Musnadu Imam Ahmod, ojisẹ Ọlọhun sọ pe: Dajudaju bi eniyan kan ba dẹsẹ kan, ti o si sọ pe Ọlọhun mi, mo ti da ẹsẹ kan fori jin mi, Ọlọhun yoo sọ pe: Ẹru mi sẹsẹ kan, o si mo pe, oun ni Ọlọhun To le fori jin oun, ti o si le fi iya jẹ oun, torinaa, mo ti fori jin-in. Lẹhinnaa to ba tun dẹsẹ miran, to tun sọ pe: Irẹ Ọlọhun mi, mo ti dẹsẹ fori jin mi, Ọlọhun yoo tun sọ pe: ẹru mi mọ pe oun ni Ọlọhun to le fori jin oun, to si le fi iya jẹ oun, Mo ti forijin-in. Lẹhinaa to ba tun dẹsẹ miran to tun sọ pe: irẹ Ọlọhun mi, mo ti dẹsẹ kan fori jin mi, Ọlọhun yoo tun sọ pe: ẹru mi mọ pe oun ni Ọlọhun to le fori ẹsẹ jinni, o si le fiya jẹni, mo nfi yin jẹri pe Mo ti fori jin ẹru mi, ki o maa se ohun ti o ba wu.

Ni ipari ẹ bẹru Ọlọhun ẹyin eyan mi, ẹ si tara ronupiwada siwaju ki asiko atise bẹẹ to bọ, toripe ko si ẹniti o mọ ẹniti iku kan. O n bọ loke, o n bọ nilẹ awọn la dẹ ẹ de e. Ki Ọlọhun se wa lẹniti yoo le jawọ kuro ninu ẹsẹ, ki o si fi orijinwa lapapọ.


فاتقوا الله - عباد الله  وبادروا بالتوبة قبل فوات أوانها . فإن الأعمار محدودة والمهلة مقدرة ولكل أجل كتاب وكل ما هو آت قريب وفقني الله وإيّاكم للتوبة النصوح والعمل الصالح . أعوذ بالله من الشيطان الرجيم " يايها الذين ءامنوا لاتلهكم أموالكم ولا أولادكم عن ذكر الله ومن يفعل ذلك فأولئك هم الخاسورون. وأنفقوا مما رزقناكم من قبل أن يأتي أحدكم الموت فيقول رب لولا أخرتني إلى أجل قريب فأصدّق وأكن من الصالحين ولن يؤخرا الله نفسا إذا جاء أجلها والله خبير بما تعملون." ( المنفقون 9-11)

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 18:02:15 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin:
Oorun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 5
Awon Ibo Ni Oniyi: 1


E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin

"TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: