Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Owo Olopaa Te Awon Omo Ibo To n Jale N'Ibadan
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Owo Olopaa Te Awon Omo Ibo To n Jale N'Ibadan

Owo palaba awon omo Ibo ti won maa n dena de awon to ba loo gba owo nla ni banki n'Ibadan ti segi. Nibi ti won ti n gbiyanju lati fi ibon gba egberun lona eedegbeta naira (N500,000) ti okunrin kan to n je Ambali Lawal sese gba nileefowopamo lowo awon agbofinro ti to won.

Bo tile je pe ohun ti eeyan ko le so pe ki enikeni maa se ni Lawal se lojo naa, igboya ti okunrin naa ni lo ran an lowo pelu bo se je pe ariwo ole to pa le won lori lo koba awon afurasi adigunjale naa pelu bi awon olopaa se sare debe, ti won si mu meji ninu won lai je pe won ri erongba won muse.

Awon afurasi adigunjale ohun, Ebere Akanya ati Akpan Eyinnaya pelu eni keta won ti won n pe ni Spido, eni tawon olopaa si n wa lowo ni won loo da okunrin kan to n je Ambali Lawal, eni to sese gba owo nileefowopamo lona adugbo Academy, Iwo Road, n'Ibadan, lona lati gba owo naa lowo e, sugbon ti oro naa ko bo si i fun won.

Gege bi oga-agba awon olopaa ipinle Oyo se fidi e mule fawon oniroyin, okan ninu awon ileefowopamo to wa ni Iwo Road, ni Ambali ti loo gbowo lojo Aje, (Monde), ojo karun-un, osu kewaa yii, bee bo se jade ninu banki naa lawon afurasi adigunjale omo Ibo wonyi ti n so o sugbon toun ko mo.

Bi won se ri i pe o ti ya kuro loju ona Iwo Road to je titi nla, to ya si opopona kan ti won n pe ni Olubodun, laduugbo Academy, ni won sare wa okada ti won fi n tele e leyin dina moto Honda re niwaju. Ibon ni won yin soke loju e leralera lati deruba a, ko si gbe owo sile ko sa lo, sugbon nise lokunrin naa kigbe ole le won lori tawon olopaa ti won n mojuto eto aabo laduugbo naa lati tesan won to wa ni Alakia-Adelubi si yara debe, ti won mu awon eeyan ohun.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe awon omo Ibo ti won ti so idigunjale di ise yii jewo ara won fawon olopaa pelu bi won se be sile ninu moto tawon agbofinro fi n gbe won lo, sugbon tawon olopaa tun tun won mu.

Ibon ilewo meji pelu ota meta la gbo pe won gba lowo awon afurasi ole yii pelu okada ti won fi n sise ibi naa ti nomba re je NRK 475 QC Nigba to n ba awon oniroyin soro, Ebere Akanya to pera e lomo bibi ilu Nkwerre, nipinle Imo, so pe Eko loun ti n jale tele ko too di pe awon so Ibadan naa di ile oloraa fun iru ise laabi tawon yan laayo naa.

Gege bo se so, "Ore mi kan to n je Oba lo mu mi wo ise ole jija l'Ekoo, sugbon o ti ku bayii, inu ijamba moto lo ku si. Baagi la maa n ja gba lowo awon eeyan nigba yen. Ko too di pe Oba ku lo ti mu mi mo okan ninu wa to n je Spido, o ni ki n maa fi okada gbe e kiri lo sawon ibi ta a ba ti fee jale.

"Ni gbogbo asiko ta a fi n jale l'Ekoo yen, aaro kutu la maa n se e. Spido lo mu aba wa pe ki n je ka maa bo wa s'Ibadan lati waa maa so awon to ba loo gba owo nla ni banki kiri ka maa ja owo owo won gba." Okunrin eni odun metalelogoji yii so pe leyin ti Oba, iyen oga oun nidii ise ole ku tan loun sese mu Akpan tawon jo wa ni akata awon agbofinro yii mora, ati pe ode akoko ti Akpan ba awon lo ni owo ti te awon yii.

Nigba to n salaye ona ti won n gba ja awon eeyan lole owo nla nla, Ebere so fawon oniroyin pe oun loun maa n gun okada, bi awon ba si ti de itosi ileefowopamo ti awon ti fee pitu lawon yoo duro, ti Spido yoo si fi oun si egbe okada nita ti yoo wo inu banki lo lati wo awon to ba waa gba owo nla, ni kete to ba ti ri iru eni bee ni yoo dogbon tele e bo sita, tawon yoo si loo ka eni naa mo ese-o-gbeji nibi tawon yoo ti fibon gba owo ohun lowo e ni tipatipa, ati pe awon ki i gba owo ti ko ba wo egberun lona otalerugba-o-din-mewaa (250) si egberun lona eedegberin naira (700,000).

"Eko naa ni mo si n gbe. Ileetura kan to wa laduugbo Mokola, n'Ibadan, ni mo maa n de si lasiko ta a ba waa sise. Ta a ba ti pari awon ise ta a fee se ni mo maa lo si ilu mi ni Nkwerre, loo sinmi die ko too di asiko ta a tun maa pada tun waa se awon ise mi-in." Nigba to n salaye bi owo awon agbofinro se te won, Ebere ni nigba tokunrin tawon fee ja lole naa ko gbe owo owo e sile wooro ni Akpan yinbon soke lati deruba a, sugbon nise lokunrin naa tun fi ariwo bonu titi towo awon olopaa fi te awon nigba ti Akpan to je olori awon gan-an sa lo.

Okunrin afurasi adigunjale yii fi kun un pe, "Mi o le so iye ti mo ti ri nidii ise ole jija yii, sugbon mo n ri owo daadaa, bi mo si se n ri owo yen ni mo n na an. Nitori pe mi o fee lo sewon ni mo se fee sa lo mo awon olopaa lowo nigba ti won mu wa." Ninu oro tie, Akpan to je eni odun merindinlaaadota so pe ko too di pe oun darapo mo awon Ebere ninu idigunjale loun ti maa n se fayawo epo disu ati bentiroolu, eyi ti okunrin kan ti won n pe ni Spido fi ona re han oun.

Gege bo se so, "Nigba to ya ni won ko je ki gbogbo awa ti a n sise yen se e mo. Leyin igba yen ni Spido so pe oun maa gbe mi lo si Ibadan, nibi ti ma a ti maa ri ise se, o waa mu mi mo okunrin kan, mi o mo oruko iyen sugbon Fireburn lo maa n pe e, oju apa ina si wa kaakiri ara e loooto.

"Ilu Potakootu lemi n gbe. Fireburn lo pe mi lori foonu lojo kan pe ki n maa bo wa s'Ibadan. Oteeli kan to wa ni Agodi GRA la ti pade, nibe lo ti salaye nipa iru ise ta a fee se fun mi ati bo se fe ka se e. Lojo naa lo mu mi mo Ebere, sugbon Ghana lo pe oruko e fun mi nitori pe omo Ghana ni iya e (Iya Ebere).

" Fireburn ti salaye gbogbo ba a se maa sise yen fun mi. Nigba ta a de adugbo Iwo Road, o ni ki emi duro si egbe mosalasi kan, ati pe oun maa pe mi toun ba ti ri eni ta a le ja lole. Bo si se ri eni yen lo ti pe mi pe oun ti ri eni kan, pe ki n se daadaa, ki n ma je ki ise yen baje mo wa lowo o.

"Bi oko Honda buluu kan se n lo la tele e pelu ibon ti Spido ti fun wa. Nigba ta a de ibi soobu mekaniiki kan ni mo yo ibon si i pe ko gbe owo to loo gba ni banki wa sugbon okunrin yen ko sa lo, nise lo bere si i bi mi leere pe ta lemi. Iyen ni mo se yinbon pe ki n le fi deruba a ko fi sa lo. Bo se bere si i pariwo ole ole ole niyen tawon olopaa fi de.

"Ki n too so pe mo lori bayii, Ebere ti gun okada sa lo, awon olopaa ba mu emi ko too di pe won pada mu Ebere naa." Sa, oga-agba awon olopaa ipinle Oyo, CP Leye Oyebade, ti so pe laipe lawon afurasi adigunjale naa yoo foju ba ile-ejo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, April 29 @ 00:33:13 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Owo Olopaa Te Awon Omo Ibo To n Jale N'Ibadan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: