Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Charles Na Nani Daku N'Ilorin, O Ni o N Je Komo Oun Sunkun
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Lati Owo Akoroyin Olootu

Charles Na Nani Daku N'Ilorin, O Ni o N Je Komo Oun Sunkun

Ileewosan 'Tobi Hospital,' to wa niluu Ilorin, lo gba arabinrin to n ba won toju omo kan, Abileko Taye Babatunde, eni odun merindinlaaadota sile nigba ti arakunrin kan, Charles Obirili, na an daku latari pe o ba omo re, omo osu mefa to n sunkun.

Isele naa waye lojo Isegun, Tusde, ose to koja si arabinrin to n toju omo ohun, eni ti opo eeyan tun mo si Mummy Tomi. A gbo pe o ti to osu meje to ti n sise naa lodo Ogbeni Charles ati iyawo re.

Nigba ti arabinrin naa n ba awon akoroyin soro, o ni banki Zenith Ilorin keji to wa ni adugbo Surulere, loun ti n sise gege bii osise oojo (contract staff), nibe si ni iya omo naa to je iyawo Charles toruko re n je Grace ti n sise.

O salaye pe Grace lo be oun pe koun kuro ni banki naa, koun si maa ba oun sise nile nitori asiko naa ni Grace wa ninu oyun, ti iya re si tun ku. O ni oga oun ni Grace je, nigba to si ba oun soro yii, nise loun te e mo on leti pe ko seleri lati ma le oun danu nitori oun ko ni ibomiran toun fee lo.

Gege bo se so, "Egberun lona ogun naira lo seleri pe oun a maa san losoosu, dipo egberun mejo aabo naira ti mo n gba ni banki nigba naa, a si jo ni adehun pe odun mefa ni ma a fi ba a sise." Taye tesiwaju pe se ni Charles so pe oun n je komo oun sunkun, oun ko kobi ara si i. Lojo tisele yii sele, ero foonu tomo naa fi n sere lo jabo sile, to si bere si i sunkun. Nnkan isere to bo sile yii loun fee mu, sadeede ni Charles wole, to si bere si i pariwo pe oun je ki omo oun tun maa sunkun. O ni boun se n salaye oro lokunrin naa n pariwo, to si ni koun gbe omo naa sile, koun kuro nile oun lesekese.

Idahun pe oun ko le kuro afi toun ba ri iyawo re to gba oun sise loun fi fesi, bi Charles se bere si i lu oun bii bara niyen. Leyin to lu oun tan lo pase fun olode ile won pe ko ru oun jade.

Gbogbo akitiyan akoroyin wa lati gbo oro lenu Charles lo ja si pabo nitori atimole olopaa lo wa lasiko ti a n ko iroyin yii.

Lasiko ti akoroyin wa n ba alukoro ileese olopaa ipinle Kwara, ASP Ajayi Okasanmi, soro lori isele yii, o ni oun ko ti i gbo nnkan kan nipa re.

Gege bi oro ti olopaa kan to ni ka foruko bo oun lasiiri so fun wa, se ni Charles salaye fun awon pe nani naa ni arun opolo, ati pe oun lo koko doju ija ko oun.

Nigba ti akoroyin wa de osibitu ti won gbe nani naa lo, a ba a ti won n fa omi si i lara.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, April 29 @ 04:45:11 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Charles Na Nani Daku N'Ilorin, O Ni o N Je Komo Oun Sunkun" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: