Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Nnkan De! Nitori Oro Ti Ko To Nnkan, Gabriel Lu Henry Pa n'Idanre
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Lati Owo Akoroyin Olootu

Nnkan De! Nitori Oro Ti Ko To Nnkan, Gabriel Lu Henry Pa n'Idanre

Pako bii igba ti maalu ba robe lomokunrin eni ogun odun kan, Francis Gabriel, n wo lagoo olopaa to ti n fimu danrin lowo lori esun pe o seku pa okunrin alabaagbe e kan lasiko ti won jo n ja.

Isele naa la gbo pe o waye lose to koja nile ti okunrin afurasi yii pelu oloogbe naa toruko re n je Henry Allison n gbe to wa loju ona kan to lo si Oja Alade, niluu Idanre, nijoba ibile Idanre, nipinle Ondo.

Gege bi ohun ta a gbo nipa isele yii, oro kekere kan lo da wahala sile laarin awon mejeeji ko too di pe esu ba won lowo si i. Gabriel ni won lo loo ba Henry, o si fesun kan an latari bo se da ile sibi ti ko ye ko da a si ninu ogba ile ti won jo n gbe.

Oro yii lo bi Henry ninu to fi so o dija mo Gabriel lowo, ka too wi, ka too fo, awon mejeeji ti yowo ese sira won. Ko seni to waa mo boro naa se je gan-an, boya se ni Gabriel gba Henry lesee nibi to lewu ni, ko senikan to ye. Ohun tawon to pejo sibi ti won ti n ja yii saa ri ni pe oloogbe naa deede subu lule, ko si le dide mo.

Ere lawon eeyan koko pe e, nigba ti won reti pe ki Henry dide nile ko maa ba ija re lo, sugbon ti ko dide nibi to subu si lawon eeyan sare gbe e digbadigba lo sileewosan, nibi ti won ti n gbiyanju lati doola emi re lo ti dagbere faye.

Alagba Allison Ekpo to je Baba Henry la gbo pe o loo fisele naa to awon olopaa Idanre leti, tawon agbofinro fi waa fi panpe oba gbe Gabriel abese-ku-bii-ojo lo si tesan won.

Ikawo awon olopaa, nibi ti won ti n foro wa afurasi yii lenu wo lo si wa titi digba ta a fi ko iroyin yii tan.

Alukoro ileese olopaa nipinle Ondo, DSP Femi Joseph, fidi isele yii mule fun akoroyin wa pe ija ajaku-akata ti Gabriel ati oloogbe yii ja lo sokunfa iku ojiji ohun. O fidi e mule pe omokunrin afurasi naa ti wa nileese olopaa, nibi to ti n ran won lowo ninu iwadii won.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, April 29 @ 04:53:23 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Nnkan De! Nitori Oro Ti Ko To Nnkan, Gabriel Lu Henry Pa n'Idanre" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: