Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo
 
 
Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara Lati Owo Akoroyin Olootu

Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo

Beeyan ba ri i bawon omo ile-eko giga Poli ti Moshood Abiola to wa ni Ojere, niluu Abeokuta, se bere si i subu lule, ti won si n daku lojo Eti, Fraide, ose to koja lakooko ti won n sedanwo ise kan ti won pe ni EED 126, ni gbongan '800 seaters', aanu abiyamo yoo seeyan.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe awon akekoo mefa otooto lo daku lojo naa, tawon kan si subu lule, ti won bere si i bi bii oloyun. Ibi ti won duro si lati wonu gbongan ti won ti fee sedanwo ni won ti n subu lule lairotele.

Iyalenu lo je pe obinrin nikan lawon ti won n daku naa. Ohun ti a gbo ni pe wahala ti won n se lati tete wonu gbongan idanwo naa lo fa a nitori pupo ninu won ni ko jeun kuro nile nitori idanwo naa.

Elizabeth, okan lara awon to daku so fun akoroyin wa pe ooyi ati oru inu lo gbe oun, toun si bere si i bi nnkan toun ko je. O ni oun ko le so pato ohun to sele ju iyen lo, nise loun kan ri pe aso oun tutu.

Akekoo kan salaye pe onikaluku lo fee tete wole sedanwo tie lojo naa ki won too loo sedanwo kan to ku ti won ni laago meta osan, sugbon ti ko see se nitori tele-n-tele ni awon alakooso idanwo naa n pe awon akekoo ti won to sinu oorun wole, eyi to fa wahala naa.

Iwe Iroyin Yoruba tun gbo pe lati nnkan bii aago meje aabo aaro ojo naa lawon akekoo naa ti de gbagede yii lati sedanwo to fee bere laago mesan-an ohun. Awon akekoo eka-eko nipa iroyin, 'Mass Communications' merin ati SLT meji ni won daku lojo naa, ti won si fi moto gbe won lo sosibitu to wa ninu ogba ohun.

Igba ti oro didaku naa su awon akekoo ni won bere si i so okuta ati pio wota lu awon alakooso idanwo, tawon yen si ranse pe awon eso ogba lati waa daabo bo won. Awon eso wonyi lo waa n fi egba na awon akekoo towo te.

Nibi ti won ti n na won ni akekoo-binrin mi-in tun ti subu lule, toun naa tun daku, iyen ni won fi dawo nina duro, ti won si sare gbe e lo si osibitu fun itoju.

Nipinle Osun, awon oluko ileewe giga pada senu ise Florence Babasola, Osogbo Leyin osu merin ti egbe awon oluko nile-eko giga to je tipinle Osun ti bere iyanselodi, egbe naa atijoba ti jokoo papo, won si ti so iyanselodi naa ro bayii.

Gege bi alaga agbarijopo awon oluko ohun (Council of Academic Staff Unions of Osun owned tertiary institutions), Comrade Lasisi Jimoh, se so, won gba lati pada senu ise leyin tijoba ti so pe oun setan lati dahun ibeere won.

O ni ijoba ti seleri lati san owo osu kin-in-ni si ekefa odun yii laarin ojo meje tawon ba pada senu ise, ati lati san awon owo to ye sinu asunwon owo ifeyinti awon oluko naa.

Lasisi ni oun ti pase fun gbogbo awon oluko ile-eko giga mereerin, iyen ileewe gbogbonise tilu Iree, ti imo-ero to wa ni Esa-Oke, tawon olukoni agba to wa niluu Ila ati tilu Ilesa lati pada senu ise won kiakia.

O waa fi da gbogbo awon obi ati akekoo loju pe gbogbo akoko ti won ti padanu lawon oluko naa yoo ri i pe won di pada pelu ise asekara, ki won le lanfaani lati pari ohun gbogbo to ye ki won mo lasiko.

Ninu oro tire, olori osise lofiisi gomina, Alaaji Oyetola Gboyega, fi idunnu re han si igbese siso iyanselodi ro tawon egbe naa gbe pelu ileri pe ijoba ko ni i ja won kule ninu adehun ti won jo fowo si.

O ni ijoba Gomina Aregbesola je eyi to mu igbaye-nirorun awon osise elekajeka lokun-unkundun, ati pe ajalu to de ba oro owo epo lorile-ede yii lo fa a ti nnkan fi yiwo mo ijoba lowo.

O ni gbogbo ejo tijoba ti pe awon egbe naa ni won ti jawo ninu e bayii, ti oro naa si ti yanju nitubi-inubi. O waa ro won lati tubo maa fowo sowo po pelu ijoba lati le mu ipinle Osun goke agba.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, April 29 @ 05:07:01 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara:
Asiri Nla Alaaji Amosa So Itan Igbesi Aye Re, O ni: Anjonnu Ni Mo Fe Niyawo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara

"Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: