Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Se Ka Kuku Loo Be Obasanjo Ko Waa Se Asaaju Awa Yoruba?
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

Se Ka Kuku Loo Be Obasanjo Ko Waa Se Asaaju Awa Yoruba?

Bo ba je irin ti egbon wa, Egbon Segun, (Obasanjo) rin lo si Ileefe lose to koja yii ti okan e wa, to si je lori ododo, a je pe isokan ti a n wa nile Yoruba ti bere naa niyen. Lojo ti Omooba Enitan Ogunwusi, Ooni Ile Yoruba tuntun, wo ilu naa wa, lojo naa ni Egbon Segun ti lo sodo re lati ki i, o mu awon eeyan mi-in dani ti won je agba nile Yoruba yii naa, won si se odomode ti yoo di baba gbogbo wa naa ni maa wole maraba. Ka sa so pe yato si awon agbaagba Ife, Egbon yii lo tun koko ki oba tuntun naa kaabo. Bi ile Yoruba ba dara, ti ko ba si iyapa, ti ohun gbogbo ba si n lo bo se ye ko ri, bi nnkan se gbodo sele lo sele yii. Bi won ba yan Ooni tuntun, eni to ba je asaaju Yoruba nigba naa gbodo ko awon agbaagba ilu lo si Ife lojo ti oba naa yoo koko de, awon ni won yoo loo pade re, ti won yoo si fi i wo sibi to ba dara, awon ni yoo koko maa ri bi gbogbo etutu ilu to ku ba ti n lo.

Idi ti eyi fi gbodo ri bee ni pe Ooni ki i se oba Ileefe nikan, Oba Yoruba ni. Gbogbo itan yoowu ka pa funra wa, gbogbo ona yoowu ka gba, gbogbo ohun yoowu ki oselu so wa da laarin ara wa, Yoruba gba pe Ileefe lawon ti wa, tabi pe Ife ni orirun gbogbo wa. Niwon igba ti Ileefe ko si ti i parun, ti oba si wa nibe to n dade, ti ase Oduduwa gbogbo si wa lowo re, oun naa ni oba gbogbo wa, iyen ti Yoruba ba fe ki nnkan roju, ti a ko si fe ki aye maa fi wa seleya, ki won maa pe wa ni alaimokan ti ko le to ile ara re, awon oniyeye ti won ko ni orirun. Okun kan ko ni i gun titi ko ma ni ibi ti won ti fa a wa, tabi ibi to ti n gun bo, Yoruba ni orirun, Ileefe si ni orirun wa. Bo ti wu ki omo lowo to, bo ti wu ki omo dagba to, baba re ko sa ni i dobale fun un ko ni oun lo bi baba oun, omo re naa ni won yoo maa pe e. Gbogbo eni yoowu to ba ti Ileefe lo, omo Yooba naa ni.

Gbogbo itan, gbogbo eya lo ni isoro tiwon o. Awon oyinbo ti a n wo bii angeli yen naa ni isoro,won ni eleyameya, bee naa ni awon Hausa ti won wa nitosi wa nibi naa ki i se omo iran kan naa, koda, iran kan naa ko lawon ara Meka, orisiirisii eya ni aye. Sugbon nigbeyin naa, ibi kan naa ni a ti wa, gbogbo iran aye lo sa so pe Adamu ati Eefa ni isedale gbogbo adarihunrun. Eyi ni pe iran kan naa kuku laye, omo ile kan naa ni gbogbo wa, aseju omo eda lo po ju ti Olorun fi da wa ni ede ru, ede yii naa lo si so wa di eya kookan. Awon ti won ba jo n so ede kan naa, ti won ba gbo ara won ye, okan won a maa bale lodo ara won ju awon ti won ko ba gbo ede ara won lo. Ohun ti won n pe ni alejo tabi ajoji niyen. Nigba ti enikan ba de ibi kan ti ko gbo ede awon to ba lori ijokoo tabi ninu ilu naa, ti ko si mo asa ati ise won, koda, ko je oun ni olori awo nibi to ti wa, ogberi ni yoo da lesekese, nitori pe ko gbede won.

Sugbon nitori ki aye le roju, nitori ki ilu le toro, nitori ki alaafia le wa, ka si ni isokan, awon eeyan a maa fi awon itan kan sile,won a maa fi awon aaye kan sile funra won lati le mu olori, lati le mu asaaju, lati le mu eni ti gbogbo won yoo maa tele, ilu tabi eya ti ko ba ni asaaju laburu n se. Eyi ni gbogbo Yoruba gbodo fi ori won mo eyin Oduduwa ti i se baba gbogbo wa, ka gba pe omo Oduduwa ni wa, ka si mo pe Ife ni gbogbo wa ti jade lo si ibi gbogbo. Omo ko le lo si ajo ko ma pada wa sile, koda ko dara fun un lohun-un, yoo maa fi eekookan wa sile baba re, ko si si ohun to buru nibe bi a ba fi akoko ti Ooni kan ba waja, tabi akoko ti Ooni kan ba fee je se akoko ipade, ti gbogbo oba nla, gbogbo omooba, gbogbo awon asaaju ilu ba n pade ara won ni Ileefe nigba naa, ti orisiirisii ilu n lo, ti orisiirisii awon onijo tele won, ti Yoruba fihan pe Ileefe ni ile won loooto, ta ni yoo foju di wa nibi kan nile yii mo, o pari niyen.

Abi bawo ni yoo ti ri ti won ba fi Alaafin, Oba nla nni, wo si ibi kan n'Ileefe lasiko ayeye, ti won fi Orangun ile Ila, Olowu Owu segbee ara won, ti won ranse si Alaketu ni Ketu ati Onisabe Sabe, ati Onipopo ile Popo, ti Oba Ibinni si de pelu ase lenu, tawon omo alade merindinlogun peju, ti won ri Ewi Ado, Otun Oore, ti Alake ati Awujale ko jinna si ara won, ti Osemowe l'Ondo ati Olowo ilu Owo naa wa nikale, ti Owa Obokun si ti wa nibi kan ki Oba Eko too de, ti ese oba nla nla nile Yoruba pe nitori pe won fee gbade kari Ooni, eya wo ni gbogbo Naijiria yii ni yoo waa ri Yoruba fin, oloselu wo ni ile Yoruba, tabi ni Naijiria lapapo ni yoo waa so pe ti Ooni bawo. Bi erin ba dan an wo, iwo re yoo lo ni, bi eegun kan ba si dan an wo, yoo deeyan lesekese ni. Sugbon ko si eni ti yoo se eleyii, awon ijoye Ife ko le se e, eni to ba je asaaju Yoruba lo le se iru eto bee ti yoo dara.

Iyen ni mo se soro irin ti Egbon wa yii rin lo si Ileefe, bo ba se pe tokan tokan ni Obasanjo fi lo, ibere nnkan daadaa ni iba je. Sugbon eru n ba mi! Hun-un, eru Egbon ba mi. O ba mi gan-an ni. Se e mo pe loni-in yii, ti Obasanjo ba ni oun yoo se olori wa nile Yoruba, iru awa yii ko ni a oo gbo egbon wa lenu, bee ni opo eeyan yoo ni awon faramo on ko se e, ko le ko wa yo ninu eyi to ba wa yii, o si le ba wa ja ija ka gba ara wa sile pada lowo awon ti won fee mu wa sin, lowo awon ti won fee fi wa se igba ikole won. Egbon Segun le se e daadaa, sugbon eru Booda Segun n ba mi o. Idi ti mo fi so bee ni pe egbon yii ko figba kan duro ti Yoruba ri, latojo to ti n rin kiri ti Olorun si ti faaye gba a, eyin Hausa-Fulani loun maa n wa, yoo ni Naijiria loun n ja fun, oun ki i se asaaju Yoruba, ko si ti i pe rara to fenu ara e so pe Yoruba ko le ni asaaju, bii eni pe Naijiria ti gbogbo wa n gbe ki i ni asaaju, tabi oun paapaa ko se asaaju Naijiria yii ri.

Sugbon bi eeyan ba mo egbon daadaa, iwa kan wa lowo won, ohun ti Obasanjo ba fe, ti ko ba to o lowo, yoo fenu yepere re ni. Obasanjo fee di asaaju Yoruba, sugbon o ti fenu yepere ipo naa debii pe awon ti won yoo loo jokoo ti i ti won yoo bere si i be e ko waa gba ipo naa lo n wa. Ki i se pe iru awa yii ko le loo be e ko gba ipo naa, a ti ba a so o ri. Sugbon kan tun wa nibe. Iyen ni asiko ti e ba ri Egbon Segun ti won ba n pooyi ile Yoruba bayii, ti won fee duro ti Yoruba bayii, e wo o daadaa, awon ore e nile Hausa ti kangi mo on nimu ni, won ti fiya kan je e,won ti se e lese kan, o n binu si won lowo, sugbon ibinu naa ko ni i see so sita. Tabi eyin ko mo pe Egbon yii n binu si Buhari lowolowo. Bi e ko ba mo, a je pe e ko mo eni ti e n pe ni Obasanjo ni.

Ki Buhari too gbajoba, e o ri i bi Egbon se n paara odo re, bo si ti wole ibo tan ni egbon ti ko awon kan jo,won ni won se iwe eto ti Buhari yoo fi se ijoba re, won ni eto to gbodo tele niyen.

Sugbon Buhari gba gbogbo iwe yii, o ju u segbee kan ni tie ni, ko wo o leemeji, nitori erin lawon yii maa n fi Obasanjo rin, won mo on ju wa lo gan-an. Nigba toro minisita tun de, Obasanjo ko oruko awon eeyan tire naa lo, awon to fe, to ro pe won le ba Buhari sise. Sugbon Buhari ko tun mu enikeni ninu won. O ti han si Egbon pe awon Buhari ti lo oun, won ti ju oun nu, idi ibinu ree o. Bi inu ba si ti n bi Egbon bee, tabi ti egbon ba jo nita to ba te, ile lo n sare bo, odo awon eeyan e ni yoo pada si, nigba naa ni yoo maa se bii eni to feran Yoruba tokantokan. Ni iru asiko yii, bi a ba be Egbon yii ko waa se asaaju wa, kia ni yoo wa, yoo si saaju wa, ti yoo maa fi oko oro ranse si awon Fulani yii, koda, asiri ti e ko gbo ri, e oo gbo o lenu e. Bawon ijoba Fulani ba waa ri eleyii ti won ba pe Obasanjo pada saarin won, nitori eeyan ti won ko le fi sile ni. Ebora Owu yoo pada to won lo o, yoo si da Yoruba sinu adanwo tuntun.

Ose to n bo ni n oo salaye ekunrere lori Ooni tuntun yii o, sugbon kin ni ka se si ti Egbon wa yii o. Se ka loo be Egbon pe ki won waa se asaaju awa Yoruba lasiko yii ni, ka si kilo fun won pe bi won ba da wa, awa funra wa la o se won lese ni. Abi ki leyin ro. Eyin naa, e soro!
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, April 29 @ 05:11:11 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Se Ka Kuku Loo Be Obasanjo Ko Waa Se Asaaju Awa Yoruba?" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: