Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
[ Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin ]

·Gbogbo Musulumi Jakejado Orileede Naijiriya Ni Babayemi Gba Niyanju Lati Se Awok
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji) Attack: Awon Omo Naijiria Ti Yari Pe Awon Naa Yo Gbes
·Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
·Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
·Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
·Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun
·Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nitori Owo Eja To Sonu, Kunle Gbe Ayoonu Gbigbona Le Omo Iyawo e Leyin N'Ib
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Nitori Owo Eja To Sonu, Kunle Gbe Ayoonu Gbigbona Le Omo Iyawo e Leyin N'Ibadan

Ko si eni ti yoo ri omokunrin eni odun mejila kan, Azeez Yusuf, lati ojo Aiku, (Sannde), ojo kejilelogun, osu kokanla, odun yii, ati leyin bii ose meji si asiko naa ti aanu e ko ni i se e pelu bi egbo nla nla se kun gbogbo eyin ati ejika re, ti inira si han loju omo naa gidigidi.

A®pa; to kun gbogbo ara omo yii ki i se ti pe o subu tabi pe o farapa nibi kan, apa ayoonu gbigbona ni, oko iya e to n je Kunle Anisere lo si han an leemo bee nitori pe o so egberun kan naira nu ninu owo eja yiyan to ba iya re kiri lo.

Leyin to ti koko lu u sugbon ti iyen ko te e lorun lo loo ki ayoonu bo ina, to si da a de Azeez leyin nigba ti kinni ohun ti gbona daadaa.

Amumora bii iso inu eku ni Azeez fi oro naa se titi di ojo keta tisele ohun han sita faye, nigba ti okan ninu awon ore e nileewe, iyen 'IDC Primary School', to n lo ni Gbagi, n'Ibadan sakiyesi pe ara re ko ya, to si bi i leere ohun to se e. Bo se jewo fun ore e yii niyen ti loo fi isele naa to oluko won leti, oluko naa ko si fi oro ohun bo to fi royin fun oga-agba ileewe naa.

Lojo Isegun, (Tusde), ojo kerinlelogun, osu kokanla, ti won ta oga-agba ileewe naa lolobo isele yii loun naa ti yara fi to awon agbofinro tesan Egbeda, n'Ibadan, leti. Logan ni CSP John Aku ti i se oga olopaa tesan naa ti ranse loo mu Ogbeni Anisere.

Nigba to n royin iya nla ti oko ti iya e fe leyin to ko baba e sile fi je e, Azeez so pe nitori pe oun so egberun kan naira nu ninu oja egbejo naira (1,800) ti oun kiri lo lojo naa lo je ko han oun leemo bee, bo tile je pe ojo naa ni igba akoko ti okunrin olokada yii yoo lu oun, sugbon oun ti maa n sowo nu tele naa.

Gege bo se so, ''Mo maa n ba mama mi kiri eja yiyan leyin ti mo ba ti sukuu de nirole, sugbon lojo yen, mo so egberun kan naira nu ninu owo ti mo pa, mama mi si na mi. Nigba ti mo ti sukuu de lojo keji, mi o wule loo ba mama mi ni soobu, nigba ti oko won de ti won ba mi ninu ile, won beere pe kin ni mo se si owo eja to fi din, mo ni inu apo ni mo ko o si to fi sonu.

"Inu bi won nigba ti won gbo idahun mi, bi won se loo mu waya ina niyen, won ba bere si i ko o bo mi. Nigba ti won ri i pe mi o sunkun ni won puloogi ayoonu mo ina, ti won si gbe e le mi ni opa eyin. Ko si ibi ti mo fee sa gba jade nitori won ti tilekun inu ile, mo pariwo pariwo, mi o ri eni wa gba mi sile.'' Omokunrin to wa ni iwe kerin nileewe alakoobere yii so pe ni tododo, omoluabi eeyan ni oko iya oun nitori o maa n toju oun ati egbon oun daadaa bo tile je pe ki i se oun ni baba awon, bee ni ko na oun ri latigba tawon ti ko de ile e.

''Ohun to bi won ninu ni pe ni gbogbo igba ni owo oja mi maa n din, mi o ki n mo nipa bi owo yen se n din, mo kan saa maa n ri i pe owo oja mi ko pe naa ni. Owo mi maa n din apo kan aabo (N300) nigba mi-in, o le din apo meji aabo naira (500) tabi egberun kan naira (N1,000) nigba mi-in.'' Bee l'Azeez so nigba to salaye ohun to ro pe o sokunfa iya buruku ti oko iya e fi je e.

Loooto ni Azeez jewo pe gbogbo igba toun ba kiri eja lo lowo oja oun maa n din, sugbon oro ko dun lenu e bi iya e, Abileko Toyin Anisere, eni to sapejuwe Azeez ati akobi e, iyen Ibrahim gege bii awon omo to sokunfa bi oun se di edun arinle nitori gbogbo igba ti won ba ti kiri oja lo lowo won ki i pe, to si je pe nise ni won maa n na owo naa ni inakunaa, ki i se pe owo ohun kuku sonu gan-an.

Gege bo se so, ''Idi ti mi o se je ki Ibrahim ba mi kiri oja mo gan-an niyen nigba to je pe ojoojumo lowo oja re ki i pe. Iwa yii kan naa ni Azeez naa tun n hu yii o, gbogbo igba lemi si maa n pariwo fun won, ti mo maa n be won pe ki won jowo, ma ba temi je.

''Nigba to di pe emi ti mo ti n ra eja loju paali ko ri owo ra oja mo, to je pe awin ni mo n gba eja lodo awon onibaara mi sugbon ti owo Azeez naa ko tun yee din lojoojumo, to di pe ti mo ba gba awin oja, mi o ni i ri oju owo pa ka ma sese so ere, ni mo tele e lo sodo awon onibaara re ni Gbagi lati sewadii ohun to fa a ti owo re se maa n din lojoojumo. Won waa so fun mi pe nise lomo mi maa n na owo oja to ba pa.

''Won fi ibi to maa n jokoo si han mi leyin to ba ti fi owo oja mi ra orisiirisii nnkan to ba wu u tan. Won ni omo mi ni ibi to ti maa n fi owo mi renti keke gigun. Opo igba ni mo maa n sunkun lori bi won se maa n na owo mi ni inakunaa nitori won ko je ki n ni akojo rara.

''Nigba to su mi ni mi o je ki Azeez naa ba mi kiri mo, sugbon nigba ti awon omo anti mi ti won n gbe lodo wa ti won maa n ran mi lowo gbe owo oja ti won ta sa lo ni mo ni ki Azeez maa ba mi kiri pada.

''Eja ti mo gba lawin gbeyin je ilaji paali, owo oja to ba pa lojo naa ni mo n reti pe ki n loo fi san gbese eleja ko too de ko too maa so fun mi pe egberun kan (N1,000) sonu ninu oja egbejo naira (N1,800). Mo ro pe iyen lo bi oko mi ninu ti won fi ba a wi. Mo gba pe esu lo fee ko wa sinu iyonu to fi di pe oro bibawi ti won fee rora ba a wi di nnkan nla mo won lowo.'' Ninu awijare tie, Ogbeni Anisere so pe oun kabaamo isele ohun nitori oun ko gba a lero lati se omo naa nijamba rara. O ni oun ki i tile i fee na awon omo naa kawon eeyan ma baa so oun lenu pe nitori won ki i se omo oun loun se n fiya je won.

Gege bi alaye to se, ''Odun kefa ree ti mo fe iya won, odun keta si ree tawon omo yen ti de odo mi ti mo si mu won bii omo. Omo daadaa lawon mejeeji, sugbon latigba ti won ti loo lo olude lodo iya baba won l'Ekoo ni won ti yowo.

''Odun Ileya lasan ni iya yen so pe ki won waa ba awon se nigba naa to di pe won ko je ki won pada wale mo. Won ko toju awon omo yen rara, pio wota ni Ibrahim so pe oun maa n kiri labe biriiji lati le ri ounje je.

Laarin awon omo abe biriiji lomo yen si ti ko gbogbo iwa buruku to bere si i hu bayii latigba to ti ti Eko de.

''Ibrahim gan-an lo fi foonu enikan pe iya e to salaye iya ti won fi n je won l'Ekoo tiyen fi fi owo moto ranse si won ti won fi wale. Sugbon latigba ti won ti de ni iwa won ti yipada patapata.

''Lojo kan ni Ibrahim ji egberun meeedogbon owo ajo ti iya won (N25,000) gba, to si sa lo s'Ekoo, sugbon ki i se odo iya baba won lo lo. Leyin to pada de lo tun ji egberun marundinlaaadota (45,000) iya won gbe, to si tun sa lo bakan naa ko too di pe awon olopaa mu un nibi to ti n na owo yen ninakunaa lowo.

''Nigba to di pe Ibrahim ti so o di asa lati maa na owo eja to ba ta lojoojumo ni iya e so pe ko ma kiri mo.

Igba yen ni Azeez bere si i kiri sugbon nigba to ya loun naa tun mu owo egbon e.'' Okunrin olokada eni odun mokanlelogbon yii so pe ohun to je koun da si oro iyawo oun atawon omo e lote yii ni pe oun ri i bi oro naa se ka iya won lara debii pe kinni ohun ti n sakoba fun ilera obinrin naa, ati pe lilu ti oun lu Azeez, oun se bee lati satileyin fun iyawo oun ni, ki i se pe oun gbero lati se e lese rara.

Alukoro ileese olopaa ipinle Oyo, DSP, Adekunle Ajisebutu, fidi isele yii mule, o ni CP Leye Ajibade ti i se oga-agba olopaa ipinle naa yoo fi oju Anisere ba ile-ejo ni kete ti iwadii awon agbofinro ba pari lori isele naa.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, May 21 @ 21:59:07 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"Nitori Owo Eja To Sonu, Kunle Gbe Ayoonu Gbigbona Le Omo Iyawo e Leyin N'Ib" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: