Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
[ Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose ]

·Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi
·Eyi Ni Bi Pasito Se Gbe Majele Je Ni Ipinle-Ogun
·Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
·Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
·Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
·Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
·Orekunrin Bukola Fee Fi i Soogun Owo N'Ibadan
·Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo
·Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere Lati Owo Akoroyin Olootu

Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Lowolowo bayii, awon afobaje ti won dibo yan Gasali Adegoke lojosi gege bii Bagii, iyen Adele-oba ilu Saki, ti faake kori pe awon ko ni i tele ase ijoba ipinle Oyo lati tun ibo di laaarin ojo merinla.

Lojo Aje, ogbonjo, osu kokanla, odun yii, ni ase waye lati olu-ileese to n ri soro ijoba ibile ati oye jije nipinle Oyo pe kawon afobaje mejeejo to yan Gasali Adegoke gege bii Bagii ilu Saki tun ero won pa nipa siseto idibo tuntun. Eyi waye latari iwe ehonu ti won ri gba latodo idile Kujenya to letoo lati fa omo oye kale, won ni yiyan ti won yan Gasali ko ba ilana oye jije idile naa mu.

Ninu iwe to jade lati sekiteriati ohun lojo Eti, ojo ketadinlogbon, osu kokanla, eyi ti Ogbeni Femi Akano fowo si loruko komisanna ni won ti fi ye idile Kujenya pe pelu awon iwe ehonu tawon ri gba, atundi ibo se pataki. Iwe yii lo mu ki ipade pajawiri waye ni gbongan ile asofin to wa ninu ogba ijoba ibile Iwo-Oorun Saki laarin awon idile ti oro naa kan atawon Afobaje mejeejo, awon agbofinro, awon osise ijoba ibile Iwo-Oorun Saki pelu awon oniroyin.

Nigba to n side ipade alaafia naa lojo Aje, ogbonjo, osu kokanla, to pari yii, olori awon osise nijoba ibile naa, Ogbeni Nureni Ayinla, salaye pe latari leta tawon ri gba latodo ijoba ipinle, abajade ipade naa ti di ofin tuntun fun ijoba nitori isakoso Abiola Ajimobi mo riri idajo ododo, gbogbo ohun to ba sele yoo si ni akosile.

Nigba ti won soro debi atundi ibo lori oye Bagii ni eni to je alaga fun igbimo naa, Oloye Shittu Olayiwola, soro loruko awon afobaje to ku pe aja ko gbodo je obi, gbogbo igbese tijoba n gbe pe kawon tun ibo di ko waye laye awon baba nla awon, ko si le sele lasiko tawon.

Oloye Olayiwola so pe oro naa ki i se awada rara, awon oloye mejeejo ti setan lati duro niwaju Gomina Ajimobi to ba doju re tan, kawon si so gbangba pe ko si bi ijiya naa se le to, awon ko ni i yi ipinnu awon pada lori eni tawon koko dibo yan naa ti i se Gasali Adegoke.

Lati kin oro re leyin, Oloye Yekeen Aiki Oyedokun toun naa je Bada Bagii so pe gboingboin lawon wa leyin Gasali Adegoke gege bii Bagii ilu Saki, ko saaye lati tun ibo di, to ba ja siku gan-an, awon ti setan.

Ninu oro eni to n soju ijoba ibile Iwo-Oorun Saki, Ogbeni Nureni Ayinla, lo ti salaye leyin ipade naa pe bo tile je pe gbogbo eto idibo akoko lo woorowo, tawon si ti fi esi ibo naa sowo sawon alase, awon ko ni i gbe igbese lati lodi si ase ijoba to wa latoke, awon ko ni i yi ipinnu awon pada, gbogbo ohun to si sele ninu ipade naa lawon yoo fi sowo sijoba kiakia.

Fofoofo ni gbongan ipade naa kun pelu awon alatileyin Bagii, sugbon pelu bi awon agbofinro se peju wamu-wamu sibe, isoro lo je fun enikeni lati se radarada kan, sugbon won faaye gba kaluku lati so tenu re.

Lara awon to ba Iwe Iroyin Yoruba soro ni Ogbeni Rabiu Ijaduola to je Mogaji Idile Olugbe, tawon naa letoo sipo Bagii. O parowa si idile Bagii lapapo lati gba alaafia laaye lori oro oye Bagii. O tesiwaju pe bo tile je pe gbogbo won lo letoo si ipo baba won, nise lo ye ko je sise- n-tele nitori pe ohun ti ko to n bo waa seku.

Ijaduola so pe oye Bagii je eyi to lagbara laarin ilu, awon idile to n joye naa si maa n gbora won ye ni lati igba iwase. Baba naa so pe awon iwe ehonu yii ko ni nnkan kan i se, Gasali Adegoke tawon afobaje dibo yan naa lawon molebi fowo si.

Ni kete ti won pari ipade ohun ni awon odo adugbo kora won jo, ti won si se iwode alaafia lo si olu-ileese ijoba ibile Iwo-Oorun Saki laaaro ojo Isegun, nibi ti won ti fi atileyin won han fun Gasali Adegoke.

Lara akole tawon odo ti won to aadota naa gbe dani la ti ri, ''E fi adugbo Otun sile lati yan Bagii tuntun, 'Gasali leni tiluu fe', 'E ma ki oro oselu bo yiyan Bagii ilu Saki' ati bee bee lo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, May 21 @ 22:02:06 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: