Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun
[ Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun ]

·Gbigba Kadara Gbo - Al-Imaan Bi-l-Qadar (Ayanma Tabi Akosile)
·Umaru Gbe Oogun Wo Kootu, Ladajo Ba Da Igbejo Duro Kia
·Fasasi Ko Iyawo e Sile N'Ibadan, O Ni Ko Ro Amala Fun Baba Oun
·Adajo Ni Ki Won Fi Emmanuel, Ayederu Looya, Sogba Ewon Kirikiri
·Alake To Fee Ko Oko Dero Ewon N'Ilorin
·Yekeen Fee Ko Munira n'Ilorin, O Ni Latigba Tawon Ti Fera Loun Ti n Ru, Tou
·Adajo Ni Kawon Ebi Oko Medinat Da Ogun Oko Re Pada Fun un
·Igbeyawo Ogun Odun Daru L'Osogbo
·Lori Oro Ti Ko To Nnkan, Awon Olopaa Fibon Fa Femi Lorun Ya, Ni Won Ba Sa Lo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


E Woju Won o: Awon Ti Won Ko Owo Naijiria Je Ree o
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

E Woju Won o: Awon Ti Won Ko Owo Naijiria Je Ree o

Nigba ti oro naa koko bere, ohun tawon eeyan ro ni pe ijoba Muhammadu Buhari n wa gbogbo ona lati mu awon ti won ba Aare ana, Goodluck Jonathan, sise ni. Sugbon nigba ti asiri nla naa bere si i tu sita, kaluku loro naa ya lenu. Nipari osu kejo, odun yii, ni ijoba Buhari gbe igbimo kan dide, igbimo oniwadii ni, ohun ti won si fe ki igbimo yii wadii ni bi awon ti won n seto aabo ile yii lati odun 2007 se na awon owo ti won ko fun won. Ohun to fa eyi ni pe laarin odun naa, ileese to n mojuto eka eto aabo fun ijoba apapo pese owo lati ri i pe won ra irinse to po, won ra eelo ogun jija, won ra ibon atawon eronpileeni repete, paapaa nitori ogun awon Boko Haram to gba gbogbo ilu kan. Sugbon bi won ti n gba owo to, bee lawon soja n pariwo pe awon ko nirinse, ti won si n sa loju ogun fun awon Boko Haram, oro naa si di nnkan abuku fun ijoba apapo, nigba tawon soja won ki ere mole ti won sa lo.

Bi e ko ba gbagbe, laye ijoba Jonathan, awon soja bii ogota kan wa ti won dajo iku fun, esun ti won fi kan won ni pe won sa loju ogun niwaju awon Boko Haram, won sa lo pata ti enikan ko ri won. Die lo ku ki won pa won, afi nigba ti Buhari gbajoba to da won sile. Esun ti won fi kan won ni pe won ko duro jagun, nigba ti won ti foju gan-an-ni awon omo Boko Haram yii, nise ni won ki ere mole ti won n sa lo. Sugbon awon soja ti won mu nigba naa soro, won ni ko si bi awon se le koju awon Boko Haram, nitori irinse ti won n lo lagbara, o si po ju tawon lo gan-an. Nidii eyi, won ni bi awon pe egberun ti awon dojuko awon omo Boko Haram ti ko ju mewaa lo, bii eni to mu adie ni won yoo mu awon, nitori awon irinse ti won n lo, irinse igbalode to lagbara ni, eni kookan won si le pa bii ogun eeyan laarin iseju meji pere. Nise lo da bii pe owo lasan lawon fi n ja ni tawon, eni ti ko ba nirinse ogun ko si le koju ogun.

Nigba ti ogun awon Boko Haram yii waa le ti ko je pe o fee lojutuu mo, Aare Goodluck Jonathan yo eni to ti wa nibe gege bii oludamoran eto aabo, o si fi Sambo Dasuki si i. Soja nla ni Sambo Dasuki ko too feyinti, awon soja aye ijoba Babangida ni, koda okunrin naa lo loo mu Buhari nigba ti won sejoba, ti awon Babangida si fee gba ijoba naa lowo re. Dasuki yii lo wo ile ijoba lo to si mu Buhari lodun naa lohun-un, iyen odun 1985. O see se ko je nitori eyi ni Jonathan se yan an, agaga nigba toun tile tun je omo oba Sokoto, to si je pe apa odo won lohun-un naa ni ogun awon Boko Haram yii ti gbile gidi. Sugbon bi won ti yan Dasuki sibe naa, awon Boko Haram ko tori e sinmi, akoko naa ni won tun ji omo gbe si, won n ji awon eeyan gbe, ati okunrin ati obinrin, bee ni won n pa awon soja repete si i.

Asiko yii lawon soja tun bere si i sa lo fun Boko Haram, o kan je bi won ba ti sa lo nigba naa, won ki i pada si orile-ede yii mo.

Awon mi-in tile n pada si orile-ede yii, sugbon ki won too wole ni won yoo ti bo aso soja won danu, ti won yoo si wa ibi kan sa lo nibi ti won yoo ti bere igbe-aye tuntun. Dasuki kowe si Jonathan, o ni ko si ohun meji ti awon le fi segun ju ki awon ra awon irinse to to irinse, ki awon ra eelo ijagun, ki awon si ra awon eronpileeni keekeeke ayara-bii-asa, ki awon le reyin awon araabi naa. Nibi yii ni owo ti bere si i yi wole lorisiirisii, owo nla ni.

Ijoba Jonathan fee fopin si Boko Haram, won si fe ki Dasuki ra awon irinse to to lati fi koju won. Araalu ko mo pe awon owo nla bayii n wo owo Dasuki, afi nigba ti igbimo elenimetala ti Buhari gbe dide yii bere ise won. Ohun ti won koko ri to so won laya kii ni pe Dasuki gbe ise bilionu aadorin lerugba Naira (N271.8bilion) fun awon agbasese kan, sugbon ko seni to ri ileese kan soso ninu awon agbasese to ni oun gbe e fun, owo naa fese rin lo ni.

Iyen ni asemase ti won koko kan, aya won si ja gan-an. Leyin naa ni won tun ri i pe laarin osu keta, odun 2012, si osu keta, odun 2015, awon obitibiti owo nla jade. Bilionu meji aabo owo Naira kan (N2.219 billion) ti koko lo, leyin naa ni owo dola to le ni bilionu kan aabo mi-in (1.671 billion) tun fese rin lo. Ati owo Yuro to le ni milionu mesan-an. Awon ohun ti won fee fi owo naa se ni lati ra eronpileeni ijagun merin, helikopita mejila, bombu lorisiirisii atawon ibon ogun. Sugbon nise lawon owo naa fese rin lo, nitori awon ileese ti Dasuki loun kowo fun, ko si eyi to ko gbogbo ohun ti won fee ra yii wa, won ko ri kinni kan gba nibe, nigba ti won si wadii awon ileese yii, won ri i pe ofurujagado ni won, ko si awon ileese bee. Awon ileese ti won si loruko bee, won ko sise kankan fun Dasuki. Lapapo, bii bilionu ojilelegbeta ati meta Naira (N643,817,955,885) lo sonu mo Dasuki lowo, bee ni owo dola to je bilionu meji o le (2.1 billion).

Ojo ketadinlogun, losu to koja, ni igbimo naa gbe abajade awon iwadii ti won ri kale fun Aare Buhari, ibinu okunrin naa si ru soke gan-an. Lesekese lo ti pase pe ki won mu Dasuki ati gbogbo awon ti oro naa ba kan, ki won mu won lati ba won sejo. Nigba naa ni ejo di ejo EFCC, won si ki Dasuki mole. Gbogbo ona ni Dasuki wa lati ja ajabo, o ti mura lati sa lo siluu oyinbo to ni ara oun ko ya, sugbon ijoba apapo ko gba fun un. Gbogbo bi won ti n te Dasuki ninu to ko soro, o saa n so pe oun ra awon irinse, nje irinse ogun naa da, o ni ki i se ejo oun bi won ko ba ko o wa o, oun ti sanwo. Risiiti da, ko si risiiti nibi kan. Sibe naa Dasuki ko soro, o ni oun ko mo kinni kan. Igba ti iya dun okan ninu awon dairekito re, Shuaibu Salisu, iyen dairekito fun eto inawo nileese eto aabo nibi ti Dasuki ti je olori won, iyen jewo, o ni ki won se oun jeeje, oun mo bi awon owo naa ti lo. Lati igba naa ni asiri nla nla ti bere si i tu jade.

Nigba naa ni won bere si i mu awon eeyan kan ti won n ti won mole, ti won si n gbowo to ha si won lowo ni tiwon. Lara awon ti won ti mu ni Raymond Dokpesi to ni ileese telifisan AIT, bilionu meji loun gba lowo Dasuki, nigba ti won si te e ninu daadaa, o ni oun fi owo naa sise fun Aare Jonathan lasiko ibo ni. Bo se je ise ipolowo to se fun Jonathan, odo Dasuki lo ti gba owo re lo ku to n salaye fawon EFCC. Igba ti won mu Gomina Sokoto tele ni tire, Attahiru Bafarawa, nitori pe bilionu merin owo Naira loun gba, o ni oro yii ko la ariwo lo, eto adura loun se fun Jonathan lasiko idibo, owo adura naa ni oun si loo gba lowo Dasuki, sugbon ko le salaye bo se na an atawon to na an fun. Bakan naa ni iroyin gbe e pe Bode George nile Yoruba nibi gba ogorun-un milionu, bee si ni gomina ipinle Rivers tele, Peter Odili, ogorun-un milionu loun naa gba, awon mejeeji yii ko si ti i salaye ohun ti awon fi owo tiwon se.

Opolopo oruko lo si ku lowo awon EFCC, sugbon Iwe Iroyin Yoruba gbo pe ohun ti won ko se ti i daruko won sita ni pe won ko fe ki won sa lo mo won lowo, nitori bi a ti se n wi yii, pupo ninu awon ti won gba owo lowo Dasuki yii, ati awon mi-in ti won ni awon seto idibo ati inawo fun Jonathan, gbogbo won lo ti farasoko, won ko jade sigboro rara, awon mi-in ninu won si ti wa ona lati sa kuro ni Naijiria, won ti lo seyin odi. Awon EFCC fee mu won ni, won ko si fe ki won ja ajabo, iyen ni won ko se daruko won sita. Ohun tijoba mura lati se fun won ni lati gbe won dele-ejo, ki won si ri i pe won ko bo ninu oro naa rara. Opolopo awon oloselu atijo ni ijoba n wa lori oro yii, afaimo ki won ma sewadii lodo Goodluck Jonathan funra re, nitori won ni gbogbo bi owo naa ti jade lawon yoo tan idi e wo, won si ti ni awon ko ni i fi Dasuki atawon ti won mu yii sile, afi ti won ba jewo tan patapata.

Bi won ba ti n ki won ti won n mu won, bee ni Iwe Iroyin Yoruba yoo maa gbe oruko won jade. Eyi ta a tun ri ree o!
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, May 21 @ 22:09:06 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"E Woju Won o: Awon Ti Won Ko Owo Naijiria Je Ree o" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: