Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
'E Gba Wa Lowo T.B Joshua Atawon Eeyan e o, Ojoojumo Ni Won n Da Wahala Sil
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Lati Owo Johson Akinpelu, Abeokuta

'E Gba Wa Lowo T.B Joshua Atawon Eeyan e o, Ojoojumo Ni Won n Da Wahala Sile'

Lose to koja ni egbe Oodua Peoples Congress ti Otunba Gani Adams gbe atejade kan sita, eyi ti Oloye Owadokun Olufemi Lawson ati Oloye Olutayo Bode fowo si labe egbe kan ti won pe ni 'Arigidi Leaders Thought'.

Ninu atejade naa ni won ti ke si ijoba ipinle Ondo, awon eleto aabo atawon elegbejegbe lati kilo fun Pasito T.B Joshua atawon eeyan e ki won kowo omo won boso nitori bi won ko se ti i jawo lori dida alaafia ilu naa ru lati nnkan bii odun marun-un seyin.

Won ni bi ki i baa se opelope Olorun atawon agbaagba ilu, o ku die kawon omo eyin T.B Joshua tun da wahala mi-in sile lose to koja lo lohun-un nigba ti won fi dandan le e pe awon gbodo sodun ibile ti won n pe ni Ajagbo.

Eekan ni won so pe won maa n sodun naa laarin odun, won si ti se e ninu osu kesan-an, odun yii, tele, idi ti won se fee se tiwon loto ni ko ye awon eeyan.

Oro naa ni won so pe o dija igboro tan laarin awon omo-eyin oba to wa lori oye atawon omo eyin T.B Joshua yii, o si ku die ki o di itajesile, to si ti n da alaafia ru.

Won tun so o ninu atejade naa pe kaka ki T.B Joshua lo ipo e gege bii olori esin lati maa fi wa idagbasoke ilu gege bi awon akegbe e se n se niluu abinibi won, won ni se lo n ko awon eeyan e lati daluru. Ati pe ko le je iyalenu fawon nitori pe o ti ni awon ko le je kohun idagbasoke kankan wolu niwongba ti won ko ti je ki omo ijo won, iyen Omooba Tunde Olanipekun joba.

Awon agbaagba ilu naa waa so nibi atejade tegbe OPC Otunba Gani Adams gbe sita pe awon ro oga olopaa patapata lorile-ede yii lati ba won tete da si i, ki won ma je kawon omo- eyin T.B Joshua tun bere itajesile niluu naa.

Bee ni won tun ro awon agbaagba ilu naa lati gbagbe gbogbo nnkan to ti sele seyin, ki won si fowo sowo po pelu Oba Yisa Olanipekun ki alaafia le joba. Won ni wahala to tun n bo bayii ni ti ipade oniroyin ti won ni Omooba Tunde Olanipekun pe, nibi to ti so pe ki eni to wa lori oye naa ma pe ara e loba mo.

Won waa pari oro won pe idi ooto tawon wa lawon yoo duro si, awon ko si ni i gba kawon kan ba ilu Arigidi Akoko je lakooko tawon lawon se pariwo sita.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 19:39:50 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"'E Gba Wa Lowo T.B Joshua Atawon Eeyan e o, Ojoojumo Ni Won n Da Wahala Sil" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: