Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Bi awon ti won n sejoba yoo ba soro, won yoo ni isokan Naijiria lawon n wa, awon n fe ki gbogbo wa da bii omooya. Sugbon awon yii kan naa ni won yoo mu eni kan lowo dani, won yoo de owo re seyin, won yoo waa ni ki awon mi-in maa gba a loju, ki won maa gba a nimu mo igi. Bee omo iya kan naa ni won o.

Bi iya ba n je iran kan nile Naijiria, kaka kawon ti won wa nijoba sare, ki won gba awon ti iya n je yii, won yoo yi oju segbee kan ni, afi bii igba pe won n fe ki won pa wa run. 

Bi oro ba ri bayii, paapaa nigba ti Buhari ti i solori Naijiria bayii mo pe awon eya oun ni won wa nidii iwa aburu yii, oun lo ye ko koko soro, ko pe awon oba atawon ijoye won, ko si ran won sawon eeyan yii ki won kilo fun ara won, ko ba won soro lori redio nibi ti won ti n gbo, ko si je ki gbogbo ilu gbohun re pe oun ko faramo ohun ti awon eeyan oun n se.


Sugbon iran awon asaaju Hausa ki i se bee. Koda, kawon eeyan won maa saburu, won ko je soro, won yoo maa fi han won pe awon wa leyin won ni. 

Ko seni ti ko mo pe nibi ti ijangbon ati wahala ti n wa julo nile yii, lodo awon Hausa yii ni, won gbagbo pe ibi gbogbo tawon ba wa, awon lawon gbodo je gaba nibe, koda ko je ilu oniluu ni. 

Eleyii ko le je ki Naijiria roju, ko le je ki Naijiria toro, ko si le je ka ri ara wa bii okan naa laelae.

 Ohun to ti n da ija sile latojo yii wa niyen, ohun to ti wa laye awon baba wa ree, awon asaaju Hausa ki i kilo fawon onijagidijagan omo ti won bi, o si jo pe inu won maa n dun bi won ba n lo sawon ipinle ati ilu mi-in ti won ba n yo won lenu nibe ni. Ki Buhari soro o, ko tete soro. 

Gbogbo eyin oloselu ile Yoruba ti e ba awon eeyan soro lati dibo fun Buhari, keyin naa tete wa a lo bayii ke e ba a soro pe ko kilo fawon eeyan re, e wi fun un ko ma ba ile Yoruba je fun wa. 

Bi e ba ba a so o bi ko ba gbo, e so fun un pe ojo kan n bo ti won yoo maa sa oku awon eeyan tiwon naa nile kiri nile Yoruba yii, nitori were sun were sun, lojo ti were ba sun kan ogiri, yoo yiju pada si won o. 

Bi nnkan ba n lo bayii, Naijiria yii ko ni i toro laelae.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 19:42:46 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: