Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Owo Te Oladele To N Ta Ori Eeyan N'Ibadan
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Owo Te Oladele To N Ta Ori Eeyan N'Ibadan

Pelu bi baba eni odun mejilelaaadota kan, Kamoru Oladele, atawon afurasi odaran egbe e ko se ri okoowo gidi mi-in se ju ki won maa ta ori eeyan atawon eya ara to je ti eeyan eleran ara bii tiwon, nigba ti won ba wa eya ara ajeji titi ti won ko ri i boro, boya omo ebi, ara tabi alabaagbe won ni won yoo pada maa lo lojo iwaju bi ko ba se opelope awon olopaa to tete fi panpe oba gbe won.

Niwon igba ti eya ara eeyan ko ti da bii eya ara moto tenikan le maa so pe oun fee ra tabi ta feeyan, A®gbon ni adape oruko ti Oladele ati okunrin kan to n je Mudashiru Adedokun pelu awon afurasi odaran egbe won to ku maa n pe ori eeyan. Bi ki i baa si i se pe eeyan je ara won, ti won yoo fi dunaadura odidi ori eeyan meeedogbon legbee re, ''agbon, agbon≈ naa ni won yoo maa daruko ti tohun ko si ni i mo pe emi odidi eeyan ti won daruko nni lo gbodo segbe; ki won too le ri iye iru agbon ti won n so naa, abi alaaye eeyan wo lo je gbe ori tie sile fawon adahunse.

Pelu gbogbo bi won se n sowo aibofinmu ohun labenu to naa, lojiji lawon olopaa ka Oladele mo inu ile e to wa laduugbo Bode, n'Ibadan, ti ile si mo ba oloro laarin igboro. Odidi agbari eeyan ni won ba ninu ile okunrin naa. Bee ni won fee mu Adedokun naa nile e to n gbe lagboole Esuawele, laduugbo Oja, sugbon tiyawo e sagbodegba fun un, ti ko je ki won ri i mu.

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, aajin oru lawon olopaa loo ka okunrin naa mole, boya oogun ifura to si n lo lo je ko mo pe won ti wa nitosi ni, tabi boya o gburoo awon agbofinro naa nigba ti won de enu ona ile e, ko si eni to ye, ohun to sa han sawon agbofinro ni pe won ko ba baba naa nile, jagunlabi ti ta poro ba ona eyinkule sa lo.

Sugbon ninu awijare re, Abileko Jolaobi Adedokun ti i se iyawo afurasi odaran tawon agbofinro n wa yii so pe oun ko mo pe iru ise laabi bee loko oun n se, bee loun ko mo pe awon olopaa lo n sa fun loru ojo to ba eyinkule sa jade nile naa.

Obinrin eni odun mejidinlaaadota yii salaye siwaju pe, ''Ileese ti won ti n se oti lo ti n sise nigba ta a fera ko too di pe o padanu ise naa, to si bere si i se gbogbo ise to ba saa mo pe o le mu owo wa foun. Ni nnkan bii odun meji seyin lo so fun mi pe ise isegun loun fee maa se bayii, ati pe oun ti bere si i ko nipa Ifa dida. Niwaju Olorun ateeyan, mi o mo pe o n se iru nnkan bee bo tile je pe mo ti gbo ti won n soro nipa agbon ri.

''Mo kan saa ri won lojo naa ti won bere si i soro pelu itara pe nibo lawon ti fee ri agbon ra bayii. Nigba ti mo ri i pe wahala won po ni mo ni se agbon naa le fee ra ti e n daamu bayii, ni ohun to je pe iye te e ba fe le e ra te e ba de oja Bode nibe yen. Sugbon nise ni won gbe idaamu ko mi, won ni gbenu sohun-un to o ba mo nnkan kan ni tie. Emi ko mo pe ori eeyan ni won n pe lagbon lojo naa, afi bi mo se n gbo yii.'' Lara iwadii tawon olopaa n se lowo bayii ni lati mo ibi ti won ti n ri awon ori eeyan, paapaa boya enikan tabi awon funra won ni won n pa awon eeyan ti won si n ge won lori. Sugbon Oladele so pe iran oun ki i paayan ni toun, o ni owo enikan loun kan ti maa n ra kinni naa lati fi soogun owo fawon eeyan nitori ise isegun loun n se ni toun.

Gege bo se so, ''Eyi ni igba akoko tawon olopaa maa se bayii mu mi. Ki i se pe mo n paayan, owo enikan lemi naa ti maa n ra awon ori yen. Egberun mewaa naira ni mo maa n ra a, mo si maa n tun un ta ni egberun meeedogbon naira fun eni ti mo ba fee lo o fun lati fi se aajo ola.'' Sa, oga-agba olopaa ipinle Oyo ti seleri lati wa Adedokun to sa lo kan nibikibi to wu ko wa, won seleri lati foju oun ati gbogbo awon towo ba te lori isele yii ba ile-ejo
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 19:49:46 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Owo Te Oladele To N Ta Ori Eeyan N'Ibadan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: