Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Tope To Pa Lanloodu e L'Ondo Ti Wa Lewon
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Lati Owo Akoroyin Olootu

Tope To Pa Lanloodu e L'Ondo Ti Wa Lewon

L'Ojobo, Tosde, ose to koja yii, nileese olopaa nipinle Ondo wo okunrin eni odun mejilelogun kan, Akindeji Tope, to pa lanloodu re nitori kanga lo sile-ejo majisreeti kan l'Oke-Eda, niluu Akure.

Gege bi ejo ti Inspekito Martins Olowofeso ti i se agbenuso olopaa ro lasiko ohun lese, nnkan bii aago mefa aabo aaro ojo kokanla, osu ta a wa yii, lojule kerinlelaaadorin, laduugbo Ayeferere, niluu Ondo, nijoba ibile Iwo-Oorun Ondo, ni Tope seku pa lanloodu re, Ogbeni Osunkalu Kayode.

O ni iwa ti afurasi naa hu lodi sabala oodunrun le mokandinlogun (319) tiwe ofin ipinle Ondo, todun 2006.

Leyin ti olujejo yii so pe oun ko jebi esun ti won fi kan an ni Olowofeso ro adajo kootu naa lati fi i pamo sogba ewon, kile-ejo naa si fiwe ipejo sowo si adari ajo to n gba ile-ejo nimoran lori esun to ba takoko.

Ninu ipinnu re, Onidaajo Victoria Bob-Manuel pase pe ki awon olopaa fi ojulowo iwe esun yii sowo sodo adari ajo to n gba ile-ejo nimoran. Bee lo ni ki won fi afurasi naa pamo sogba ewon Olokuta titi dojo keeedogbon, osu karun-un, odun ta a wa yii. 
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 20:26:43 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Tope To Pa Lanloodu e L'Ondo Ti Wa Lewon" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: