Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise Lati Owo Akoroyin Olootu

Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won

Ori ti ko obinrin onisowo Ibadan kan, Risikat Badiru, yo lowo iku ojiji pelu bo se ko sowo awon agbenisowo ti won mura lati pa a danu, sugbon ti won pada fi i sile leyin to lo odidi ojo marun-un ninu ahamo won.

Obinrin onisowo yii siwo ise fojo naa, iyen lale ojo Aje, Monde, ti i se ojo kerinla, osu keta, odun yii. Funra re lo si wa oko ayokele e lati ibi to ti n taja dele. Sugbon bo se de enu ona ile lawon eruuku ti won gun okada be gija siwaju e pelu ibon. Oko ayokele Honda re ohun naa ni won si fi waa lo sona jinjin rere.

Gege bi oga-agba olopaa ipinle Oyo, CP Leye Oyebade, se fidi e mule, inu ile nla kan nitosi ilu Imodi, nipinle Ogun, lawon ajinigbe ohun loo gbe Abileko Risikat pamo si. Leyin naa ni won pe awon ebi e lori ero ibanisoro pe owo awon ti ba iya naa, pipa lawon yoo si pa a bi won ko ba tete wa ogun milionu naira wa, bo tile je pe won pada din owo ohun ku si egberun lona eedegbeta naira (N500,000).

Oga olopaa yii so siwaju pe leyin tawon ebi obinrin yii ti fi isele ohun to awon agbofinro leti ni awon olopaa ri okan ninu awon afurasi odaran naa to n je Danladi Sodiq mu niluu Imodi, nipinle Ogun, nibi to ti n gbiyanju lati gba owo naa laimo pe nise ni won fi de oun.

Ilu Ijebu-Igbo, niwaju ile Sunday to je okan lara awon afurasi ajinigbe ohun la gbo pe awon olopaa ti ri oko Abileko Risikat. Ore timotimo ni won si pe Sunday ohun pelu Sodiq to ko si panpe awon agbofinro.

Nigba to n salaye bo se kagbako awon eni ibi naa, iya onisowo yii so pe, ''Nnkan bii aago meje ale ku iseju meeedogbon ni mo kuro ni soobu lojo naa. Mekaniiki mi naa n bo leyin mi lale ojo yen nitori mo ni ko waa ba mi se atunse kan lara moto ohun. Ba a se fee wonu ile ni mo ri awon merin kan lori okada meji ti won fi nnkan boju. Won na ibon si mekaniiki mi, o si sa lo.

''Won na ibon si emi naa pe ki n bo sile latinu moto, bi mo si se silekun moto ni won sare gba ilekun ohun mo mi lowo. Okan ninu won beere kokoro moto mi, won ni ti mo ba fi le pariwo, nise lawon maa pa mi. Won gbe mi jokoo si eyin moto, awon meji ninu won jokoo ti mi, eni kan n wa moto, eni kerin won si jokoo siwaju pelu eni to n wako.'' ''Ba a se n lo ni won ti fi aso di mi loju ki n ma baa ri nnkan kan. Nibi ta a ti n lo ni okan ninu awon taya oko mi fo. Won tun ri i pe epo ti fee tan ninu moto mi, ni won ba foonu enikan pe ko ba awon ra epo wa lowo awon to n fi keegi tun un ta. Bi oniyen se gbe e de ni won ro o sinu tanki epo moto, ni won ba n gbe mi lo.

''Nigba ti won gbe mi de ibi ti won gbe mi pamo si ni won pe oko mi pe ko fun awon lowo to ba mo pe oun si ni emi mi i lo. Odidi ojo marun-un ni won fi fi aso bo mi loju. Inu ile alaja meta kan ni won fi mi pamo si. Mi o ri ounje gidi je, eekookan ni won maa n fun mi lounje. Emi si ree, aisan ogbe-inu maa n da mi laamu, ko ju ojo keta lo tinu rirun fi bere si i yo mi lenu. Mo ni ki won fun mi lounje sugbon won o dahun, won ni awon ko le fun mi lounje nitori oko mi ko fun awon ni milionu marun-un naira ti awon beere lowo e. Won ni ebi lo maa pa mi ku sibi ti mo wa yen.

''Leyin opolopo ebe ti mo be won ni aanu mi too se won ti won fi fun mi ni omi, buredi ati kooki. Lojo Tosde to koja ni mo gbo ti won n so o laarin ara won pe awon ole n bo waa ja laduugbo yen, pe ki n ma sasunpiye. Won waa fun mi ni igbin kan pe ki n mu un lowo.

Leyin naa ni won mu mi kuro ni isale ibi ti won fi mi si, won mu mi gun aja keta ile yen lo.

Ki i se pe mo riran o, won ko si aso kuro loju mi, sugbon ninu akiyesi ti mo se pelu bi a se n gun oke ile yen lo, mo ri i pe aja keta sisale ti mo wa tele ni won mu mi lo ti won si tun fi mi pamo sibe.

''Leekan naa ni mo gbo ariwo, 'Ole ni, ole ni'. Okan ninu awon ti won gbe mi pamo sare fa mi lowo, o bere si i mu mi sokale lo. Nibi ta a ti n lo ni mo ti gbo iro ibon to deede dun pa.

Leyin naa ni omi-in tun dun. Eni to fa mi lowo mu mi jade sita, a soda si odi keji titi. O mu mi sa wonu igbo lo, a si sa pamo sibe. Mi o mo boya aaro la wa tabi ale nitori didi ni oju mi wa, sikaafu mi naa ni won fi di mi loju.

''O pe ka too kuro ninu igbo ta a sa si ti won si mu mi lo sinu ile kan. Inu ile yen ni won sun, emi o le sun, sugbon mo toogbe die. Lojo Fraide, won bere si i soro pe se ko ti i ye ki oko mi mu owo wa ni. Won ni nise lawon kuku maa pa mi danu, mo ba bere si i be won pe ki won ni suuru die si i.'' Nje bawo ni ori se ko o yo, Abileko Risikat salaye pe sadeede lawon ajinigbe ohun tu aso loju oun, won ni asiko ti to lati tu oun sile nitori awon ti won ran awon nise ti so pe ki won je ki oun maa lo lalaafia. O ni bi won se so bee tan ni won ba oju ferese jade, ti won si kilo foun pe ki oun ri i pe o to wakati kan leyin tawon ba lo tan ki oun too jade ninu ile ohun.

O tesiwaju pe, ''Bi mo se jade ninu ile yen ni mo bere si i rin lo laiwo bata, ko si pe ti mo fi ja si oju ona nla kan. Mo ri sainboodu ti won ko ona Abeokuta si lara, mo tun ri okan ti won ko ona Ijebu-Oru si. Mo waa duro, mo bere si i da awon onimoto duro pe ki won saanu mi, ki won gbe mi, sugbon nise ni won n sa fun mi nitori gbogbo ara mi lo ti doti pelu aso ti mo wo sorun, afigba tawon okunrin meji kan ti won gun okada de ti won duro gbe mi, bo tile je pe awon naa ko koko fee duro gbe mi tele. Won gbe mi lo si garaaji, won si fun mi ni apo meji aabo naira (N500) pe ki n fi wo moto lo sile.'' Bo tile je pe Sodiq ti won mu fesun ijinigbe yii so pe oun kan mo Sunday ti won lo ji iyawo oniyawo gbe ni, ati pe oun loun se oniduuro fun un ti won fi gba a sinu ile to n gbe to si je iwaju ile ohun ni won ti ba moto Abileko Risikat, sibe, o ni oun ko mo nipa oran ti won lokunrin naa da nitori omoluabi eeyan loun, ise okada loun si n se jeun, sibesibe iwadii awon olopaa fidi e mule pe oun paapaa ki i se eni ire.

Pelu bi Sodiq se so fawon agbofinro pe olokada loun, ati pe enu ise loun wa lasiko tawon olopaa mu oun, nigba ti won ye apo re wo, egberun mesan-an naira to je kikida egberun kookan naira ni won ba nibe to to o sinu apo daadaa, eyi to yato sona tawon olokada maa n gba pa owo, to je orisiirisii owo, ati owo were, ati owo nla ni won maa n pa jo.

Bakan naa ni won sewadii eni to ni okada ti Sodiq n gun kiri, o ni enikan to n je Gbenga lo gbe alupupu ohun foun sugbon Sanusi Tosin loruko to wa ninu iwe oko naa. Nigba tawon olopaa si pe nomba ero ibanisoro to wa lori iwe ohun paapaa, eni ti won pe so pe ki i se oun loun ni alupupu naa.

Sa, iwadii awon agbofinro si n tesiwaju lori isele yii, paapaa lati mu Sunday atawon emewa e ti won sa lo gege bi oga-agba olopaa ipinle Oyo se so fawon oniroyin n'Ibadan.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 20:32:26 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: