Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti
 
 
Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose Lati Owo Akoroyin Olootu

Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti

Oludasile ileewe aladaani kan, Ogbeni Babatunde Ibitoye nile-ejo giga kan to wa niluu Ado-Ekiti pase ewon odun mewaa fun nitori esun fifi ipa ba akekoo ileewe re kan to je omo odun mewaa lo po niluu Ado-Ekiti.

Ibitoye to nileewe alakoobere God's Grace Nursery and Primary School to wa lagbegbe Agric Olope, ni Ajilosun, niluu Ado-Ekiti, lowo te lojo kewaa, osu kefa, odun 2013, lasiko to n ki omodebinrin ohun mole ninu oja ohun.

Gege bi idajo Adajo Toyin Abodunde, eri ti olupejo je fi lele pe lai si tabi-sugbon kan nibe, olujejo fipa ba akekoo naa lo po.

Adajo Abodunde so pe oun gba imoran ajo to n mojuto eka idajo araalu, DPP, wole pelu eri olupejo ohun to fi han pe loooto ni won ka olujejo naa mo ibi to ti n se kinni fun omo naa Gege bo se so, iwadii ti fi han pe olujejo ohun ti n ba omodebinrin naa lo po ko too di pe owo te e, ati pe awon oluko kan nileewe ohun jerii si i pe loooto ni won sakiyesi eje to n jade lara omode naa nigba die seyin saaju ki isele towo ti te oludasile ileewe ohun too waye.

''Ati pe pelu bawon eeyan se ba olujejo ohun nibi to ti fa awotele re sile ti fi han pe daju lo jebi esun ti won fi kan an, esun ohun lo si tako abala kokanlelogbon, ofin to n ja fetoo awon omode nipinle Ekiti, todun 2013. Nitori idi eyi, ile-ejo yii so olujejo sewon odun mewaa gbako lai si anfaani sisan owo-itanran.'' Adajo Abodunde lo so bee.

Se lojo kewaa, osu kefa, odun 2013, lowo te Ibitoye nibi to ti n ki akekoobinrin naa mole leyin tawon akekoo jade ileewe lojo naa. Ohun to so ni pe oun n mu omode naa lo sile.

Lojo naa, Ibitoye ko awon akekoo merin sinu moto to si gba agbegbe to kun fun igbo legbe oja Agric Olope naa lo lati se bii eni se ga, kete to si debe lo fogbon ran awon akekoo meta to ku ni orisiiriisii ise, leyin tawon yen lo tan lo mu omo naa wonu igbo lo.

Lasiko tawon mekaniiki to wa nitosi fura si okunrin naa ni won fogbon wonu igbo tele e, nigba ti won maa debe, nise ni won ba Ibitoye nibi to ti n ba akekoobinrin naa lo po.

Kia ni won fa a le awon olopaa tesan Ologede, niluu Ado-Ekiti, lowo ko too di pe won gbe e lo si olu-ileese olopaa, tawon yen si wo o lo sile-ejo.

Isele ohun lo mu ki ijoba Gomina Kayode Fayemi to wa lori aleefa nigba naa gbe ileewe naa ti pa, titi di asiko yii ni won ko si ti i si i.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 20:33:18 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose:
Iru Pasito Radarada Wo Waa Ni Oluso-Aguntan Oyelami Yii Gbogbo Awon Omobinrin Ij


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose

"Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: