Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo Lati Owo Akoroyin Olootu

Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure Ni Moto Te e Pa Si

Surusuru lomije n da loju awon eeyan to wa nibi toko akero kan ti te omokunrin eni odun meeedogbon kan pa l'Akure laaaro Ojobo, Tosde, ose to koja yii.

Gege bi alaye ti okunrin kan tisele naa soju re se fun wa nigba ta a sabewo si geeti ogba Fasiti Imo Ero (FUTA) to wa l'Akure leyin isele naa, o ni jeeje lokunrin toko te pa ti won poruko re ni Johnson Ogah n ta ipekere re nigba ti moto ohun sadeede loo ya ba a nibi to duro si, to si te e pa.

Oko boosi akero naa ti nomba idanimo re je Oyo XC 247 YYY to n bo lati Ileefe lo deede ya kuro loju ona tire nigba to de iwaju geeti Fasiti Imo Ero naa, to si se bee loo kolu awon moto mi-in to n lo ni tiwon, ko too waa te Johnson pa nibi to wa. Loju-ese lo ni omokunrin yii ti ku, bee ni ipekere to n ta fon soju titi nibe kaakiri.

A gbo pe awon olopaa ti fi panpe ofin mu awako ohun ti won poruko re ni Bamidele Orimisan, tesan olopaa to wa ni Okuta-Elerinla, niluu Akure, lokunrin afurasi naa to n gbe lagbegbe Oke Amala, ni Modakeke, nipinle Osun, si wa to n ran awon agbofinro lowo ninu iwadii won titi dasiko ta a fi n ko iroyin yii jo.

Nigba to n fidi isele naa mule, alukoro ileese olopaa nipinle Ondo, DSP Femi Joseph, so pe mosuari ileewosan ijoba to wa l'Akure ni won si toju oku Johnson si titi tiwadii yoo fi kese jari lori isele naa. Bakan naa ni pe akata awon olopaa lokunrin awako naa yoo wa titi tiwadii yoo fi pari lori esun ti won fi kan an.

Nigba ti oga-agba ajo eso oju popo nipinle Ondo, Ogbeni Edward Zamber, n fidi isele yii mule, o juwe e bii eyi to ba ni ninu je. O ni ijamba naa waye latari bi awako ohun se padanu ijanu-oko re. Bee lo sekilo fawon eeyan to kundun ati maa taja legbee titi pe ki won jawo ninu eyi nitori ewu pupo to ro mo on.

Leyin ojo meta ti won ti n wa Bako n'Ilara-Mokin ni won ri oku re ninu igbo Oluseye Iyiade, Akure Lowolowo ba a ti n ko iroyin yii, pelu iberu-bojo lawon eeyan ilu Ilara-Mokin ati agbegbe re nijoba ibile Ifedore, nipinle Ondo, fi n gbe nitori ko ma di pe awon Fulani darandaran waa gbesan iku to pa okan lara won.

Saaju ni ede-aiyede ti ko waye laarin awon omo egbe OPC l'Ondo atawon Fulani darandaran to wa niluu Akure lori bawon Fulani kan se ji okan lara awon omo egbe OPC gbe nibi to ti n sise oojo re, sugbon to je leyin ojo keta ti won ti ji i gbe ni won too ri oku re ninu odo kan ti won so o si leyin ti won gbemi e.

Lori oro naa ni won wa ti komisanna olopaa nipinle Ondo, Abileko Hilda Harrison, fi pe ipade pajawiri pe koun le yanju wahala to saaba maa n waye laarin awon agbe atawon darandaran.

Lasiko ipade naa ni komisanna olopaa ohun menuba oro yii lerefee, ki i se pe o fi gbogbo enu la ohun to sele mole. Lasiko ipade alaafia yii lo ni Olorun lo tete ba awon yanju rogbodiyan ti i ba sele nijoba Ifedore laaaro ojo naa.

Leyin-o-reyin la sese waa gbo ohun to sele gan-an latenu olori awon Fulani nipinle Ondo, Alaaji Ali Dogo. Okunrin naa salaye fun wa pe ounje ni won ran okan ninu won toruko re n je Dan Bako, eni to fi abule kan to wa nitosi Ilara-Mokin sebugbe, latigba naa lo si ti dawati.

Leyin to ni won bere si i wa okunrin Fulani darandaran ohun ni won ri okada to n gun ninu igbo, sugbon ti won ko roun funra re nibe. Lori eyi ni won wa titi di aaro Ojobo, Tosde, ose to koja ti okiki kan pe won salabaapade oku Bako ninu igbo kan ti won pa a si leyin ti won ji i gbe sa lo.

Oro naa la gbo pe o fee di wahala laarin awon agbe atawon Fulani to wa nijoba Ifedore pelu bi won se lawon Fulani kan n so pe iku okan ninu won ko seyin awon agbe agbegbe naa.

Ba a se gboro ohun la ti sare pe DSP Femi Joseph to je alukoro ileese olopaa nipinle Ondo lati le fidi oro yii mule, sugbon o se ni laaanu pe ba a se pe oga olopaa naa to, se lo ko lati gbe ipe wa, bee ni ko pe wa pada.

Lenu olopaa kan la ti waa pada gbo pe loooto nisele naa waye, ati pe komisanna olopaa nipinle Ondo, Abileko Hilda Harrison, ti gbo si i, o si ti gbe igbese lati ko opolopo olopaa lo sagbegbe ohun ki won le tete pana wahala to ba fee tidi isele yii suyo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 20:44:33 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 5
Awon Ibo Ni Oniyi: 1


E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: