Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa

Latari ijamba oko to n fopo emi sofo ati bi orisiirisii ajalu mi-in bee se maa n waye loju ona marose Osodi-Apapa, ile igbimo asofin Eko ti ke sijoba apapo lati pese afara elese soju ona naa.

Oro yii lo je yo latenu omo egbe oselu alatako, Onarebu Jude Idimogwu, pe asiko ree fun ile naa lati ta ijoba apapo ji lori pipese afara elese, eyi to ni yoo sadinku sun-kere-fa-kere oko ati ijamba moto nibe. Bee ni Onarebu Sola Giwa ni kijoba koko sewadii na ko too di pe won gbe igbese kankan lori pipese afara sagbegbe ohun.

Aba naa ni Onarebu Elliot Desmond kin leyin, o ni opo eeyan loko ti gba latari pe won fee fona loju ona yii. Iru ajalu buruku tiru isele bee fa ni eyi to lo sele si iya-iyawo oun nigba ti moto sadeede kolu u nigba to fona titi yii, to si se bee ku.

Sugbon Onarebu Segun Olulade to je alaga fun igbimo to n ri seto ilera nile naa ni opo awon agbegbe mi-in wa to se pe afara elese ohun wa nibe, sugbon tawon eeyan ibe ko lati samulo re, nitori e lo se ro ile naa lati ke sijoba ipinle nipa pipa awon osise KAI lase lati ri i daju pe awon eeyan n rin lori biriiji elese ti won se fun lilo won. Bee lo ni ki won so fun ijoba lati ri si bi afara yoo se di sise si oju ona marose Osodi-Apapa yii.

Nigba to n soro, Onarebu Mudashiru Obasa ni pupo ninu oro lawon asofin ti so, o si gba aba yii wole pelu kike sijoba apapo lati sewadii nipa ohun to n fa ijamba loju ona naa, ki won si tun se afara elese sibe.

Bakan naa ni won tun ke si ajo to n sayewo ohun jije (NAFDAC) lati pase fawon asobode ile wa pe ki won maa se ayewo awon oja ti won n ko wo orile-ede yii wa. Bee ni won tun ke sajo to n ri si oja nipinle Eko (Lagos State Consumer Protection Agencies) lati segbelewon oti waini ti won n ko wo ipinle yii.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, February 26 @ 21:39:32 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: