Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.
Onka Ni Oju-Agbo
Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi
E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi
Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran
E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:
Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.
Ona Igba Wole Si Agbo
Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.
Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
Gomina ipinle Ogun, Omoba Dapo Abiodun ti je ko di mimo pe ijoba ilu ko she e da she lai si imo ati ogbon awon agbaagba ilu nibe, nitori naa, o so pe idi ni yii toun yoo fi ya ninu imo ati ogbon awon agbaagba lati le rii pe ipinle naa gun oke ju bi enikeni she le lero lo.
Gomina Abiodun lo soro naa lonii niluu Abeokuta, lasiko to n gba egbe awon igbimo agbaagba lalejo ninu ofiisi re to wa ni Oke-Mosan. Nibe lo si ti so pe oun ko ni i koyan agba kankan, paapaa awon obinrin kere lati da si eto ishejoba oun.
Bakan naa lo tun so pe anfaani nla lo je fun ipinle Ogun lati ni awon agbaagba bi i eyi, iyen State Elders Consultative Forum, nitori pe awon gan an ni majeobaje ti won duro digbi ti ijoba, ti won ko si ni gba ki ipinle naa rele laarin awon akegbe e.
Nigba toun naa n gba awon yooku soro, Onidajo feyinti Bola Ajibola to je alaga egbe igbimo awon agbaagba naa, eni ti Olori Yetunde Gbadebo shoju fun so pe awon omo egbe naa je awon agbaagba to she e mu yangan lawujo, paapaa awon ti won ti ko ipa ribiribi nipinle Ogun ati orileede Naijiria, eyi ti won ni gbagbo pe won yoo ran ijoba Dapo Abiodun lowo.
KO WA TAN BI: IJOBA APAPO LE AWON TO N JE ANFAANI N-POWER LONA AITO DANU
Ko din ni egberun meji ati igba (2,525) awon ti won so pe won n je anfaani irolagbara ti ijoba she agbekale e lodun meloo kan seyin, iyen N-POWER lona aito danu, ti won si ti wogi le bi won she gba won sishe.
A gbo pe awon ti ko din ni egberun lona eedegbeta (500,000) lawon ti won gba wole nigba ti eto naa bere kaakiri gbogbo ijoba ibile 774 to wa lorileede yi, ti won si n gba owo oshu won, sugbon iyalenu ni won loo je nigba ti won so pe awon kan ko lo sibi ti won pin won si lati maa shishe, ti won si n gba owo oshu.
Egberun lona ogbon (30,000) naira lowo oya ti eni kookan n gba gege bi alakale ijoba latigba ti won ti bere lodun 2016 lti fi ran awon odo ti won ko nishe lowo.
Ijoba apapo si ti so pe awon ti shetan lati maa gbogun ti awon iwa etanje ati aishe ojushe awon eeyan bayii, lati le din iwa ajebanu ku lawujo wa.
Nigba to n fidi oro naa mule, Onidajo Bibiye to je agbenuso fun National Social Investment Office so pe awon ti ko din ni 18,674 ni won ti finufedo kowe fishe naa sile, nigba ti won ti ri ishe gidi, tawon min si n gba owo ti ko to si won leyin ti won ko lo sibi ti won pin won si mo.
Posted By
Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 02:57:52 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.